File size: 36,617 Bytes
30b2b87
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
 
1
2
3
4
5
6
7
8
9
10
11
12
13
14
15
16
17
18
19
20
21
22
23
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
34
35
36
37
38
{"line_id": "01yy", "file_name": "01-yy_intro_alphabet.mp3", "text": "a àga\nb bàtà\nd dùndún\ne ehoro\nе eşin\nf filà\ng garawa\ngb gbágùúdá\nh hanrun\ni igi\nj jígí\nk kókóró\n| légbélégbé\nm mángòrò\nn náírà\no ológbò\nọ òbọ\np pépéye\nr ràkúnmí\ns sálúbàtà\n\nt\nu\nW\ny\n\n\ntata\n\nwárápá\nyanmùyánmú", "speaker_id": "01"}
{"line_id": "02yy", "file_name": "02-yy_intro_consonants.mp3", "text": "b bàtà\nd dùndú\nf filà\ng igi\ngb gbogbo\nk kó̟kó̟ró\nl labalábá\nm méjì\nn nísisìnyí\np pátápátá\nr rìkísí\ns sálúbàtà\nş şibĺ\nt tata\nw wàrà\ny yanmùyánmú", "speaker_id": "02"}
{"line_id": "03yy", "file_name": "03-yy_intro_nasal-vowels.mp3", "text": "an\nen\nin\nọn\nun\n'Ìbàdàn'\n'iyen'\n'erin'\n'ìbon'\n'fun'", "speaker_id": "03"}
{"line_id": "04yy", "file_name": "04-yy_intro_oral-vowels.mp3", "text": "a\najá\ne\nerin\nе\n--\ni\nO\nu\n\neye\nimú\nowó\no̟wó̟\n*ooru", "speaker_id": "04"}
{"line_id": "06yy", "file_name": "06-yy_ch01_l01_d01.mp3", "text": "Ę kááárò o, bàbá.\nKááárò o, Tádé. Şé o sùn dáadáa?\nBéè ni, mo sùn dáadáa. Ę ṣé.\n\nĘ káàbò o, Màmá\nKúulé O, Lolá. Şé àlàáfíà ni?\nAlàáfíà ni.\nEgbónon rẹ ńkó̟?\nWon wà nílé.\nÓ dáa o. Dìde.\n\nẸ káàárò mà.\nĘ kááárò o. Sé dáadáa ni o?\nDáadáa ni mà.\nŞé e sùn dáadáa?\nBé̟è̟ ni mà.\n\nKáásán o, Fúnmi.\nKáásán o, Şadé. Şé dáadáa ni?\nA dúpé. ìwọ náà ńkó̟?\nA dúpé o.\nKí ni orúko̟ò̟ rẹ?\nOrúko̟ò̟ mi ni Olúfémi.\nKí ni orúkọ bàbáà rè?\nOrúkọ bábáà mi ni Kúnlé Akínlàjà.\nBá mi kí àwọn òbíì rẹ tí o bá délé,\nMo gbọ sà.\n\nÓ dàbò o, Olúfémi.\nÓ dàbọ sà.\n\n\nĘ káásán o, Màmáa Fúnmi.\nĘ káásán o, Màmáa Şadé. Gbogbo ilé\nńkó̟?\nDáadáa ni o. Bàbáa Fúnmi ńkó̟?\nWón wà. Ẹ şé o. Ó dàbò̟ o\n\nÓ dàbò o.\n\nẸ káalé mà.\nKáalé o, Títí. Şé àlàáfíà ni?\nA dúpé mà. Şé Şadé wà nílé?\nRárá o. Ó ti jáde.\n\nÓ dáárò mà.\nÓ dáárò o, Títí. Kílé o.", "speaker_id": "06"}
{"line_id": "07yy", "file_name": "07-yy_ch02_l03_m01.mp3", "text": "Orúkọo mi ni Wálé. Mo jé̟ akékò̟ó ní Yunifásítì ti Texas ní Austin. Mo férán ilé-ìwéè mi\ngan-an ni nítorí pé gbogbo ohun tí ó lè mú kí è̟kó̟ rọ ènìyàn lórùn ni ó wà níbè àgàgà nínú\nkíláȧsìì mi.\nOrişirişi nǹkan ni ó wà nínú kíláàsìì mi. Láraa wọn ni àga, tábìlì, àwòrán, kò̟ǹpútà, monito,\nmáòsì, kíĺboodù, ìwé atúmò̟-èdè, pé̟è̟nì, pé̟ńsùlù, rúlà, ìrésà, fídíò, síídiì, fáìlì, máàpù\nàgbáyé, sóòkì, pátákó-ìkò̟wé àti béè béè lọ.\nLéyìn èyí, a tún lè rí àwọn nǹkan mìíràn tí wọn mú kíláàsìì mi yàtò̟ sí kíláȧsì mìíràn ni\nYunifásítì bli ìlèkun aláràbarà, fèrèsé aláràbarà, iná ìlétírſìkì, àjà, apèrè̟-ìdalènùsí àti béè\nbéè lọ.\nMo férán ilé-ìwéè mi lọpọlọpọ. Mo sì máa ń fi í yangàn láàárín àwọn ò̟réè mi nítorí pé\nnáánní náànnì náánní, ohun a ní là á náánní bí ọmọ aṣégità se ń náánní èpo igi.", "speaker_id": "07"}
{"line_id": "08yy", "file_name": "08-yy_ch02_l04_d01.mp3", "text": "Gbogbo yín, e mú ìwé ìṣiròo yín\njáde. Ę şí ìwé yín sí ojú-ìwé\nkarùnlélógbon. Títí, s̟e ìṣirò kìíní.\nAárùnúndínlógún àti eétàlá jé\neéjìdínló̟gbon.\nTítí, o gba ìşirò rẹ şámúṣámú. Kémi,\nşe ìşirò kọkànlá. Yọ ẹérin kúrò nínú\neétàlá.\nEm em em, ó ku ẹésànán.\nO káre, Kémi. Foláké, s̟e ìşirò tó\ntélé ìyẹn. Yọ ẹésànán kúrò nínú\neétàdínlógún.\n: Ó kù ẹéjo.\nÓ káre Folákę.\nÈyin ọmọ, ẹ dáké ariwo. Òla ni ọjó ìdánwò. Ó yẹ kí á tún ìṣiròo wa wò. Lọlá, Kí ni ìşiròo\neéjì àti eéfà?\nĘéjo ni.\nÓ káre Lolá. Títí, kí ni oókàndínlógún àti ogún?\nOókándínlógbon ni\nFémi, şé Títí gba ìṣiròo rè?\nRárá, oókándínlógójì ni àròpò̟ oókàndínlógún àti ogún.\nO káre Fémi. Rèmí, yo aárùnúndínlógún kúrò nínú oókánléló̟gbon.\nEérìndínlógún ni.\nFúnmi, şé Rèmí gba ìṣiròo rè?\nBéè ni, ó gba ìṣiròo rẻ.\nGbogbo yín, ẹ káre.", "speaker_id": "08"}
{"line_id": "09yy", "file_name": "09-yy_ch03_l02_d01.mp3", "text": "Bàbá Olá, şé wà á bámi lọ sí oko ní ò̟sè̟ tí ó ń bò̟?\nRárá o, nítorí pé mo máa lọ sí ò̟dò̟ àbúròò mi obìnrin tí ara rè̟ kò yá. Tí mo bá\ndé ibè, mà á ba lọ sí oko láti mú ișu, ilá, tòmátò, è̟gúsí, ata rodo, tàtàsé àti ègé\nwá sílé. Tí mo bá dé láti oko, mà á ba se oúnjẹ. Léyìn náà, mà á ní láti bá a\nfoṣọ, lọta, kí n sì bá a gé igi. Mà á ba lọ gba oogùn ló̟dò̟o apòògùn. Mà á tójú\nàbúròò mi dáradára. Mà á dúró tì í títí di alé. Mà á wá padà sí iléè mi.\nÓ dára o. Má á sì lọ sí oko láti hú koríko. Tí mo bá șe tán, mà á padà wá sílé.\nBóyá ti ara àbúròò mi obìnrin bá yá tán a má a jọ lọ. Jé̟ kí á lọ ìsò̟o Màmáa Títí.\nìyẹn á dára púpò̟.", "speaker_id": "09"}
{"line_id": "10yy", "file_name": "10-yy_ch03_l03_m01.mp3", "text": "Orúkọ mi ni Wálé. Mo jé̟ o̟mo̟ bíbí ìlú Ìbàdàn láti ìpínlè̟ Òyó̟ ní orílè̟-èdè Nàìjíríà. Tí ó bá di\nojó kesàn-án, oṣù kọkànlá ọdún tí ó ń bò̟ ni màá pé ọmọ ọdún mókándínlógbon.\nGégé bí ìtàn tí mo gbó̟, torí bí ọmọdé kò bá gbó̟ ìtàn, yóò gbó̟ àró̟bá torí pé àróbá ni bàbá\nìtàn. Mo gbó pé ojó ìṣégun ni ojó tí àwọn òbíì mi bí mi. Èyí máa ń jé̟ kí inúù mi dùn fún ọjó̟-\nìbíì mi tí ó bá bó sí ojó ìṣégun.\nNípa ti àwò̟, kín má puró, mo féràn àwò ṣùgbọn n kò fé̟ràn àwò̟ pupa àti yé̟lò rárá rárá.\nGbogbo ohun tí e̟nu ń jẹ pátá ni mo féràn.", "speaker_id": "10"}
{"line_id": "11yy", "file_name": "11-yy_ch04_l02_d01.mp3", "text": "Fèyí, ṣé wà á wá kí mi ní òpin osè, ní\nojó àìkú?\nNí aago mélòó ni o fé kí n wá? ó máa\ndára ní ò̟sán nítorí pé mo máa ń lọ sí\nìsìn o̟mo̟dé ní aago mésànán àbò\nàárò. Léyìn náà, ní aago mewa, ìsìn\nàgbà máa bèrè.\n(Èmi náà), ní aago márùnún ìrolé, mo\nń lo sí ibi ojo ìbí ò̟réè mi kan.\nOjo ìbli ta ni?\nOjó ìbí Akin Ọmóyemí.\nRárá o, aago méta ni ojo ìbí Akin yen.\nTí o bá lọ ní aago márùnúun, wà á kàn\nlọ gbá ile ni!\nO ò se kúkú jé kí á pàdé ní ò̟dò̟ Akin.\nŞé wà á so̟ fún àwọn òbli rẹ?\nNígbà wo ni o máa dé ò̟dò̟ Akin?\nBli aago méta àbò osán.\nÓ dára, ó dìgbà kan ná.", "speaker_id": "11"}
{"line_id": "12yy", "file_name": "12-yy_ch04_l03_d02.mp3", "text": "Yemí, Ọmọ ọdún mélòó ni é?\nỌmọ ọdún méjìdínlógún ni mí.\nỌmọ ọdún mélòó ni bàbáà rę?\nỌmọ ọdún métalélógójì ni wó̟n.\nỌmọ ọdún mélòó ni mȧmáà rę?\nỌmọ ogójì odún ni won.\nỌmọ ọdún mélòó ni àbúròo bàbáà rę?\nỌmọ ogbon odún ni won.\nỌmọ ọdún mélòó ni è̟gbó̟nòn rẹ?\nỌmọ ogún ọdún ni won.\nỌmọ ọdún mélòó ni àbúròò re?\nỌmọ ọdún mérìndínlógún ni.", "speaker_id": "12"}
{"line_id": "13yy", "file_name": "13-yy_ch05_l02_d01.mp3", "text": "Bàbáà mi, mo ní òré kan.\nìyẹn dára o. Ta ni òréè re?\nOrúkọ rẹ ni Láńre.\nTa ni bábáa Láńre ?\nOjogbón Òsúndáre ni bàbáa\nLáńre", "speaker_id": "13"}
{"line_id": "14yy", "file_name": "14-yy_ch05_l03_m01.mp3", "text": "Ębli mi ni ębí Adédiran\nÀ n gbé ní ìlú Ìbàdàn ní àdúgbò ìyágànkú. Bàbá àti ìyáà mi bí ọmọ merin. Àkó̟bí wọn ń je\nAdéolú. Ọmọ ọdún méjìlélógbon ni won. Apòògùn sì ni won pèlú. Won ní ìyàwó. Oruko\nìyàwóo won ni Gbémi. Wọn bí ọmọ méjìi, Doyin àti Yétúndé. Okùnrin ni Doyin. Doyin je\nọmọ ọdún mérin. Yétúndé sì jé̟ o̟mo̟ o̟dún méjì. Ọmọ kejì tí bàbáà àti màmáà mi bí ni\nBímpé. Bímpé jé ọmọ ogbon odún. Dókítà ni wó̟n, şùgbọn wọn kò ì tí ì fẻ ọkọ. Eni tí ó\ntělé Bímpé ni Jídé. Ọmọ ọdún mérìndínló̟gbọn ni wó̟n. Agbejorò ni won. Won sèsè bí\nọmọ kan tí orúkọ rẻ ń jé̟ Rónké. Rónké jé̟ o̟mo̟ oṣù méta. Èmi ni àbígbéyìn nínú ẹbí\nmi. Oruko̟ò̟ mi ni Àbíké. Mo jẹ ọmọ ọdún méjìlélógún. Mo wà ní Yunifásítì ti ìlú Ìbàdàn.\nMo ń ko nípa è̟kó̟ ìṣègùn.", "speaker_id": "14"}
{"line_id": "15yy", "file_name": "15-yy_ch05_l03_m02.mp3", "text": "Ębí Akinwálé\nOrúkọ mi ni Lolá. Orúkọ bàbáà mi ni Fémi. Orúkọ màmáà mi ni Ọláníkè̟é̟. Mo ní abúrò\nmeta. Orúkọ won ni Jídé, Báyò àti Bùnmi. Jídé àti Báyò ni àwọn abúrò mi ọkùnrin, Bunmi\nsì ni àbúrò mi obìnrín. Jídé ni ọmọ kejì. Báyò ni ọmọ kẹta. Bunmi ni àbúrò mi àbígbéyìn. À\nń gbé ní ìlú Èkó. Mo férànan gbogbo àwọn ẹbí mi gan-an ni.", "speaker_id": "15"}
{"line_id": "16yy", "file_name": "16-yy_ch05_l04_m03.mp3", "text": "Bàbáà mi tínínrín, wọn sì dúdú. Màmáà mi sanra, wó̟n sì pupa. Wón lewà. Kì í se pé\nbàbáà mi búréwà o! Wón je ologbón, alááánú àti onírèlè. Wọn sì tún jé ènìyàn gíga.\nMàmáà mi je oníwápělé. Won kì í se onígbéraga. Wọn kò ga bli bàbáà mi. Wọn kò sì kúrú\npúpo. Won jé ènìyàn rere. Won sì jé̟ o̟mo̟lúwàbí ènìyàn.", "speaker_id": "16"}
{"line_id": "18yy", "file_name": "18-yy_ch06_l03_d01.mp3", "text": "Eélòó ni tàtàsée yín, ìyá aláta?\nÈwo nínúu won?\nÀwọn tí ó wà ni àárín yen?\nNáírá márùnún ni àwọn yen.\nHáà! Wọn ti won jù. N kò lè san náírá márùnún o. Ę jé kín san náírà\nméta àbò.\nRárá, kò gbà. (Màmáa Tádé ń lọ.) Ó dára o. Ę wá mú u ní náírá méta\nàbò.\nẸ gbà. Náírá márùnún nìyío.\nÒ dára o. Ę gba náírà kan àti àádó̟ta kó̟bò̟. Ę padà wá o.", "speaker_id": "18"}
{"line_id": "19yy", "file_name": "19-yy_ch06_l03_d02.mp3", "text": "Ę kááárò o, Màmáa Fúnmi\nE kááárò o, Màmáa Şadé, a à jí bí?\nA jíire o. Gbogbo ilé ńkó̟?\nA dúpé o. Dáadáà ni won wà. Bàbáa Şadé ńkó̟? Şé àlàáfíà ni won\nwà?\nA dúpé o. Bàbáa Fúnmi náà ńkó̟ o?\nWọn wà o. Wọn mà ti lọ sí ìrìn àjò.\nDáadáa ni wọn yóò dé o. Mo mà fé ra ata rodo, ata s̟ò̟ǹbò̟, tòmáàtì,\nàlùbosà, iyò àti epo pupa.\nÈmi náà fẻ ra ẹja tútù àti s̟ò̟ǹbò̟ fún ọbè̟ eja aláta ni.\nMo máa ra è̟foo sọkọ yòkò̟tó̟ àti è̟gúsí. Mo ní láti ra èlùbó̟ fún àmàlà", "speaker_id": "19"}
{"line_id": "20yy", "file_name": "20-yy_ch06_l03_d03.mp3", "text": "Háá Kúnlé, ki ni o wá se ní ọjà?\nMàmáa mí ní kín wá ra eran náírà mé̟wàá, ìręsìi náírà márùnún ààbò̟, ata rodo náírà\nkan, àlùbosà náírà kan, èfó̟ọ tètè̟ náírà méji. Wó̟n fún mi ní ogúnun náírà. Tí ìṣirò rẹ bá\npéjú, eélòó ni ó yẹ kín mú padà lọ sí ilé?\nKúnlé, sé o mò̟ pé mo féràn ìṣirò! Wà á mú .....uhhhhh...... àádó̟ta kó̟bò̟ padà lọ sí ilé fún\nmàmáà rę. Tí o kò bá se béè, o ti wọ ìjò̟gbonọn màmáa rè̟ nìyẹn.\nLádi, èmi náà ti şirò iye tí ó yẹ ki n mú padà lọ sí ilé, O mọ ìṣirò gan-an ni o.\nMàmáa tèmi náà ní kí ń ra ata tàtàsé ogóta kó̟bò̟, epo pupa náírá kan, àlùbósa ogórin\nkó̟bò̟, è̟wà pupa náírà márùnún, gààrí náírà márùnún, nínúu náírà márùnúndínlógún. Èló\nlo rò wípé ó yę kín mú padà lo sí ilé?\nNáíra méjí ati ogóji kobo.\nO gbà á. Ó dàbò̟ o.\nÓ dàbò̟ o.", "speaker_id": "20"}
{"line_id": "21yy", "file_name": "21-yy_ch06_l03_s01.mp3", "text": "Lángbé jíná o\nOrokún orí ebè\nOlóko ò gbowó\nÀdàlú elédé o\nAwùsá gbó keke bí obì\nÓ gbó bí orógbó\nEléntú dé o.\nÒré ìkété dé o\nÓ tú sépo múyé,\nÓ fàtàrí napo pé bé\nÓmí é ń hó yeeyéè,\nYeeyéè ní ń hó o\nEyin omo àràbà méta Odòokun,\nĘ wa mu ún\nYeeyéè ní ń hó o", "speaker_id": "21"}
{"line_id": "22yy", "file_name": "22-yy_ch06_l03_s02.mp3", "text": "Oní moínmóín gbewá gbewá\nMoínmoín epo\nSó mepo\nŞó mepo sìndin\nMoínmóín epo\nŞo fedé si pèlálùbó̟sà\nMoínmoín epo\nOní dòdò oní moínmoin\nOní dòdò oní moínmoin\nNígbà tí ò tà ó gbé gbá kalè̟\nĘ wá wò jà ní Láfíàji.", "speaker_id": "22"}
{"line_id": "23yy", "file_name": "23-yy_ch07_l01_d01.mp3", "text": "Wálé, báwo ni nǹkan?\nDáadáa ni.\nÀwọn ẹbli rę ńkó̟?\nDáadáa ni gbogbo won wà o. Màmáà mi ní kín máa kí ẹ.\nWọn mà sé o, won kú àìgbàgbé mi.\nÀwọn òbli rę náà ńkó̟?\nWon ti jade láti àárò̟, kò sì yẹ kí wó̟n pé dé mọ.\nÓ ye kín dúró de won, nítorí pé ó pé tí mo ti rí wọn.\nKí ni kín fi ṣe é lálejò báyìí?\nÈmi! Àlejò? Gbogbo ohun tí o bá ní nílé pátá ni kí o gbé wá, má á ję wó̟n.\nÀmó, má gbé ògì wá o.\nKí ló dé?\nN kì í mu ògì. N kò féràn ògì rárá.\nKò burú o, ìręsì àti èwà ni mo fé fún ẹ je o.\nÌresì kè! Şé kò sí iyán tàbí è̟bà ní?\nWálé! O ti féràn òkèlè jù. Ọmọ ọkà!\nŞé ìwọ ti gbagbé òrò àwọn Yorùbá tí wọn sọ pé:\n\"Iyán l'oúnje, ọkà l'oògùn, Airí rárá là á j'èko, K'enu má dilè ni ti gúgúrú.\"\nÓ dára, má á fún ẹ lébà.\nHèn-en-én! O sé jàre òré.", "speaker_id": "23"}
{"line_id": "24yy", "file_name": "24-yy_ch07_l03_d02.mp3", "text": "Kí ni orúkọ ọjà tí wọn ń ná ní àdúgbò tí a\nrìn kojá yen?\nOjȧa Sánńgo ni.\nSé ojà kan soso tí ó wà ní ìlú ìbàdàn\nnìyẹn ni?\nRárá o!\nKí ni orúkọ àwọn ọjà tí ó kù àti àwọn ohun\ntí a lè rí rà ní ibè?\nOrişirişi ojà ló wà ní ìlú Ìbàdàn yìí. Nínúu\nwọn ní a ti rí Qjàa Sánńgo, Ojàa Màpó,\nOjà Aléṣinloyé, Ojàa Dùgbé, àti Ojà\nOrítamérin. Bí àpeere, a lè rí ohun èlò\nenú ń ję rà ní ọjà Aléṣìnloyé bí ó ti lè̟ jé pé\nìsò àwọn álaṣọ ló pò̟ jù níbè̟. Àwọn èlò\noúnjẹ bli ata, tòmáàtì, epo pupa, irú, òróó,\nàlùbosà, ilá, égúsí àti oúnjẹ bíi ìresì, è̟wà,\nàgbàdo, eja, eran, gàrí, èlùbó̟, àti è̟fó̟. A\ntún lè rí àwọn èso bli osàn, mángòrò,\nìbépe àti béè béè lọ ní àwọn ọjà wònyí.\nNínú àwọn ọjà tí mo dárúkọ wò̟nyí, a lè sọ\nwípé Qjàa Sánńgo, Màpó, àti Aléṣinloyé\nni àwọn ojà tí wọn tobi jù ní ìlú Ìbàdàn.\nÈyí mà dára o. Won yàto púpò sí àwọn\nojà tí a máa ń ná ní ilé-Ifè.", "speaker_id": "24"}
{"line_id": "25yy", "file_name": "25-yy_ch07_l04_d03.mp3", "text": "Màmá, irú oúnjẹ wo ni ẹ ní?\nÈbà, iyán, ọkà gidi àti fùfú.\nIrú obè wo ló wà?\nObe ilá, égúsí, ewédú àti gbègìrì.\nIrú eran wo ló wà?\nEran ògúnfe, màlúù àti ò̟yà.\nEja ń ko? Irú eja wo ló wà?\nEja sáwá, eja èpìà, eja aborí àti eja àrò.\nEélòó ni ìgbákọ àmàlà kan?\nOgúnun náírá.\nŞé ó gba náírá márùnúndínlógún?\nRárá, kò gbà. Ogúnun náírà ni ìgbákọ.\nẸ fún mi ní ìgbako merin.\nTrú obè wo le fé? Obè̟ ilá, ewédú, gbègìrì, è̟gúsí àti è̟fó̟ rírò.\nẸ fún mi ní àbùlà.\nErán ńkó̟?\nEélòó ni eran kò̟ò̟kan?\nNáírá márùnún ni eran kò̟ò̟kan.\nẸ fún mi ní eran méjì?\nŞé omi le fé tàbí mínirà?\nTrúu mínírà wo lẹ ní?\nA ní fáńtà, kóòkì, sípíráìtì, séfúno̟ò̟pù, pẹpusí àti dókítò̟ pẹpè̟.\nEélòó ni kóòkìi yín?\nOgbonọn náírá ni.\nẸ fún mi ní kóòkì kan. Eélòó ni owó mi jé̟?\nOwóo yín je ogofàa náírà.\nĘ gba owó.\nẸ ṣé o. (Oníbàárà gba oúnjẹ, ó sì wọ inúu búkà lọ láti jẹ oúnjẹ rè̟.)", "speaker_id": "25"}
{"line_id": "26yy", "file_name": "26-yy_ch08_l03_d01.mp3", "text": "Túndé, sé wàá wá sí ilé-ìwé lóla?\nRárá o, nítorí pé araà mi kò yá. Orí ń fó̟ mi. Gbogbo ara ń ro mí.\nŞé o ní ibà ni?\nÓ dàbée, sugbon n kò mò.\nŞébí tí o bá ní ibà, wà á kàn lọ rí dókítà ní ilé-ìwòsàn ìjoba ni.\nNjé o mo wípé n kò féràn láti máa lọ sí ilé-ìwòsàn? Mo bèrù abéré púpò̟.\nTúndé, kì í ṣe gbogbo àìsàn ni ènìyàn ń gba abéré̟ sí. Tí ó bá je wípé ibà\nlásán ni, o lè mu àgbo.\nHáà, èèmi, àgbo kè! Ki ni yen korò bli ewúro.\nŞebí kí àwọn òyìnbó tó dé, àgbo ni àwọn Yorùbá máa ń mu.\nÀwọn Yorùbá şi ń mu àgbo títí dì ìsinyìí, şùgbọn èmi kó̟. Mà á kúkú lo gba\nabéré yen ni!\nTí ojú, etí àti esè̟ bá ń dùn ó n ko?\nFún ojú, màá lọ rí dókítà ojú ni. Şebí dókítà kò níí fún mi ní abéré nínú ojú!\nTúndé, o kì í se dókítà.\nBee ni, n kì í se dókítà. Nję o mo pé eyín ń dun èmi náà?\nHáà! Wà á lo ri yoyinyoyín (dókítà eyín) nìyẹn. Wón á fún ẹ ní aber nínú\neyin.\nJo ó kúrò o jère. O dé nìyẹn.", "speaker_id": "26"}
{"line_id": "27yy", "file_name": "27-yy_ch09_l01_d01.mp3", "text": "Bàwo ni, Felicia?\nHáà! Marcus, dáadáa ni.\nKí ní o wá se ní láàbù?\nMo wá se ȧyewoo sámpùlù ni.\nHà! Hà! Şe è̟kó̟ nípa sáyéǹsì ni iwọ náà ñ kó̟ ni?\nBeeni. Mo ń ko nípa sáyè̟nsì. Bàó̟ló̟jì ni è̟kó̟ò̟ mi dálé lórí nítorí pé mà á fé\ndi dókítá nígbà tí mo bá parí è̟kó̟ò̟ mi.\nÓ dára bée. Abájọ tí o fi tera móṣé. Á á dára o!\nOo. O sé o Marcus. Kí ni ękóọ tìre dálé lórí?\nMo kan ń se işe kan tí ó jọmọ sáyéensì ni. Èkó̟ nípa ìmò̟-è̟rọ ni è̟kó̟ò̟ mi\ndálé lórí. Mo féràn ìmò̟-è̟ro gan-an ni nítorí pé má á fé di enjiníà nígbà tí\nmo bá parí è̟kó̟ò̟ mi.\nIṣé enjiníà náà dára púpò, ṣùgbón n kò lè ṣe é, nítorí pé mo férán isée\ndókítà gan-an ni.\nKò burú. A jé wípé níwòyí ọdún márùnún, màá ti di ẹnjiníà. Ìwọ náà á ti di\ndókítà. Ó dàbò̟ o.\nÓ dàbò o, enjinía Marcus!!!", "speaker_id": "27"}
{"line_id": "28yy", "file_name": "28-yy_ch10_l02_s01.mp3", "text": "ìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo\nìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo\nìmó̟tótó ilé, ìmó̟tótó ara, ìmótótó oúnjẹ\nìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo\n\nìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo\nìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo\nìmó̟tótó ilé, ìmó̟tótó ara, ìmótótó oúnjẹ\nìmótótó ló lè ségun àrùn gbogbo'", "speaker_id": "28"}
{"line_id": "29yy", "file_name": "29-yy_ch10_l02_s02.mp3", "text": "We ki o mo\nGé èékánná re\nJęun tó dára lásìkò\nMá jeun jù\n\nWe ki o mo\nGé èékánná re\nJęun tó dára lásìkò\nMá jeun jù", "speaker_id": "29"}
{"line_id": "30yy", "file_name": "30-yy_ch10_l03_m01.mp3", "text": "Ní ilẹẹ Nàìjíríà, àpátíméèntì ni àwọn Yorùbá máa ń pè ní fúláàtì. Tí àwọn ènìyàn kò bá tí ì\nşetán láti kó̟ ilé, wọn máa ń rentì àpátíméèntì láti gbé. Àwọn alákowé ni wọn sáábà máa ń\ngbé fúláàtì.\nÀbúrò màmáà mi jẹ agbejó̟rò ní ìlú ìbàdàn. Wọn sì ré̟nti fúláàtì kan sí Bódìjà Tuntun.\nOrúkọ won ni Loya Adébímpé. Fúláàtì wọn tóbi ganan ni. Ó ní pálò̟ ńlá méjì àti yàrá\nìbùsùn merin. Yàrá tí ó tòbi jù ni yàrá àbúrò màmáà mi àti ìyàwóo wọn. Yàrá yìí ní baluwè\nàti ilé ìyàgbé tiré lóó̟tó̟. Balùwè àti ilé ìyàgbé kan tó kù wà fun àwọn ọmọ àti àwọn àlejò.\nÈnìyàn kò lè şȧdédé wo̟ fúláàti àbúròo màmáà mi lái se pé ó jé ẹni mímò̟. Ìdí nìyí tí o fí je\npé ìta gbangba ni won ti máa ń gbàlejò. Tí ó bá se ènìyàn mímò̟ ni ó wá kí àwọn ìdílé\nàbúròo mámáà mi, pálò̟ tí ó wà ní iwájú ni wọn máa jókòó sí láti bá wọn sòrò àti şeré.\nŞùgbón tí ó bá ṣe àlejò pàtàkì ni, pálò̟ ńlá kejì ní wọn máa ti n gbàwọn lálejò. Pálò ñlá yìí\ntóbi bli ààfin Oba. Wón sí tún şṣe é lós̟ò̟ó lóríṣiríṣi pèlú àwọn ohun mèremère bí i góólù.\nKódȧ kò yȧtò sí àafin. Ìdí nìyí tó fi jé̟ pé àwọn àlejò pàtàkì nìkan ni wó̟n máa ń gbà láàyè\nláti jókòó nĺbè.\nỌmọ méjì péré ni àbúròo màmáà mi bí - Adébolá àtí Adébóyè. Okùnrin àti obìnrin ni won.\nAdébolá ń lo yàrá kan. Adébóyè náà sì ní yàrá tire. Yàrá kan tókù ni yàrá àlejò. Fúláȧtì\nàbúrò màmáà mi tóbi gan-an ni. Òpọlọpò̟ ènìyàn ni wọn máa ń sọ pé ó wu àwọn. Ìta\ngbangbaa won téjú, ó sì láàyè tó pò̟. Ohun tó wù mí jùlo nípa fúláàti àbúrò màmáa mi nipé\nwon fi ọgbà yiká tó fi jépé àwọn ènìyàn tí wọn ń lọ níta kò le rí ohun tí ó ń lọ nínúu fúláàtì\nàbúrò màmáà mi.", "speaker_id": "30"}
{"line_id": "31yy", "file_name": "31-yy_ch10_l04_m02.mp3", "text": "llée wa jé ilé alájà méjì. Òpọlọpò̟ ojúlé ni ilé yìí ní. Àjà kìíní ní yàrá méjo̟, bé̟è̟ sì ni àjà kejì ní\nyàrá méjo pèlú. Bàbáà mi fi gbogbo yàrá méjèèjo tí ó wà ní àjà kìíní rentì fún àwọn\nayálégbé. Àwọn ìdílé mérin otò̟ò̟tó̟ ni won gba àjà kìíní ní yàrá méji-méjì. Won fi yàrá kan şe\nyàrá ìbùsunun wọn. llé ìdáná méjì, balúwè̟ méjì àti ilé ìyàgbé méjì ni ó wa ní àjà kìíní. Àwọn\nayalégbé sì pin wọn ní ìdílé méjì sí balúwè, ilée ìdáná àtí ilée ìyàgbé kò̟ò̟kan.\nYará mejo ni ó wà ní àjà kejì ṣugbọn èmi àti àwọn òbli mi pèlú awọn è̟gbọn àti àbúròò mí\nnìkan ni à ń gbé ní àjà kejì. A ní pálò̟ ńlá kan tí a ti máa ń gba àlejò. A sì tún ní pálò̟ kékeré tí\nawa ọmọ ti máa ń şeré, tí a sì ti máa ń wo telifíṣàn. Bàbáà mi ní yàráa ti wọn tí ó ti pálo ńlá.\nYará ìyáà mi sì tělé ti bàbáà mi. Ègbó̟nò̟n mi ọkùnrin tí ó wà ní Yunifásíti ti Obafemi\nAwóló̟wó̟ ní ilé-Ifè̟ ní yàrá tiwọn lọtò̟, ó sì súnmó pálò ti àwa yòóku.\nYará àwọn ọmọ ọkùnrin méji yòókù àti ti awa obìnrin wà ní ìkangun ilé. Yàrá ìyáàgbà ni ó\ntělé ti ìyáa mi. Gbogbo yàrá tí ó wà ní àjà keji ni àwọn ẹbli mi ń gbé tó bée gé tí ó fi ję wípé\nkò sí àyè fún ayálégbé kankan láti gbé pèlúu wa. Yàrá ìdáná méjì, balúwè̟ méjì àtì ilé ìyàgbé\nméjì ni ó wà ní àjà kejì bí ó ti wà ní àjà kìíní. ṣugbọn àwọn ẹbí mi nikan ni wọn ń lo gbogbo\nàwọn yàrá wònyí. Eléyìí fún wa láàyè púpò̟ láti rí ibi kó erù sí. Kódà ìyáa mi ráȧyè sin nǹkan\nosìnin wọn bli adie, ehoro àti tòlótòló. Bàbáà mi fi ọgbà yí ilée wa ká. Eléyìí sì fún àwa\no̟mo̟dé láńfààní láti şere sí ibi tí ó bá wùwà nínú o̟gbȧa wa. Ogbà ilée wa tóbi gan-an ni, ó sì\ntéjú púpo.", "speaker_id": "31"}
{"line_id": "32yy", "file_name": "32-yy_ch10_l04_m03.mp3", "text": "Nínúu yàráà mi, mo ní ibùsùn, ìrò̟rí, àga, tábìlì ìkàwẻ, kó̟bó̟ò̟dù ìkáṣọsí, rédíò alágbèéká\nkékeré kan, kápéèti (ení àtéèká) àti béè béè lọ.\nNí pálo, aga onítìmùtìmù merin ni wọn wà níbè, telifíṣàn ñlá kan, rédíò ñlá kan, aago ńlá\nkan àti orişirişi àwòrán ara ògiri ni ó wa níbè pèlú. Sítóòfù onígáàsì àti sítóòfù\nonikerosfinì wà nínúu ilé ìdáná. Bé̟ẹ náà sì ni firſìjì àti sfinkì. Ohún-èlò ìdáná oríşirişi bli\nàwo, abo, ìkòkò, síbí, fó̟ò̟kì àti ò̟bẹ náà sì wà níbè. Ĕrọ omi, tó̟ò̟bù, sáwà, sfinkì, oṣẹ ìwè àti\ntáwèèlì wà nínúu balùwè.", "speaker_id": "32"}
{"line_id": "33yy", "file_name": "33-yy_ch10_l04_m04.mp3", "text": "Nínú ilé-ìwee mi, oríşirişi nǹkan ni mo ní níbě bíi ìpara, ìparun, ìyarun, oṣẹ ìfoyín, ose ìwè,\noṣẹ ìfo̟wó̟, aṣo ìnura, omi tútù, omi gbígbóná, búró̟ò̟sì, kábíné̟è̟tì, kànhìnkànhìn, tíṣù, àti\nàwọn nǹkan mìíràn.\nNí gélé tí mo ba ti wọ inú ilé-ìwèè̟ mi, búró̟ò̟sì mi ni mo kó̟kó̟ máa ń kì mó̟lè̟ tí má á fi ọṣẹ\nìfoyín sí i. Mo bèrè sí fọ ẹnu lọ nìyẹn. Léyìn òpò̟lò̟pò ìṣéjú, mà á bu omi yálà tútú tàbí\ngbigbóná láti fi fọ ẹnuù mi mọ.\nÀwọn Yorùbá ní ìgbàgbó̟ pé omi tútú máa ń jé̟ kí ara nà dáadáa, àmó̟ tí òtútù bá mú jù, omi\ngbigbóná ni mo máa ń fi í wè̟ pè̟lú ọṣẹ àti kànhìnkànhìn ní àárò̟ kí gbogbo ìdò̟tí ara le bá\nomi lọ. Mo máa fi ìpara àti ìparun ra ara àti irunùn mi. Tí mo ba ti wẻ tàn máa sì yarun pèlú.\nLéyìn gbogbo èyí, háà! Oúnjẹ yá láti je nìyen!", "speaker_id": "33"}
{"line_id": "34yy", "file_name": "34-yy_ch12_l02_d01.mp3", "text": "Tádé, njé o mò̟ pé kíláàsì márùnún ni mo ní ni simésítà yìí?\nHáà! Hun ùn. Tirẹ mà dára à. Kíláàsì márùnún ni èmi náà ni, pè̟lú láàbù.\nMò ń se kákúló̟ò̟sì, físíìsì, è̟kó̟ èdèe Yorùbá, kémísírì àti sitatísííkì. Is̟é̟ náà\nwò̟ mí lórùn nítorí pe ojoojúmó̟ ni mo máa ń lọ sí láàbù. Mo ń ṣe àyèwò\nkan ló̟wó̟ nísinsìnyí fún ìdánwò. N kò sì mọ bí mo ti máa rí ké̟míkà tí màá\nlò pè̟lú àyè̟wò náà láti fi rí èsì tỉ mò ñ retí nínú àyè̟wò náà.\nHáà! Mo yìn é o. Is̟é̟ ńlá ni ò ń s̟e. Èmi kò ní láàbù, bé̟è̟ ni n kò sì ní is̟é̟\nojoojúmó̟. Nítorí náà kò yẹ kí n máa rojó̟. Kú isé̟ o, Tádé.\nO o, O sé o. Wò ó, nís̟e ni mo ń retí kí simésítà yìí tán o jàre.\nMá ṣè ìyonu Tádé, gbogbo rè̟ ti n tán lọ. Láìpé̟ ìwọ náà yóò di ẹnjíníà tó\nmòye, tó ń gbówó rẹpętę.\nLóóótó ni o sọ Bùsólá, sùgbọn kíkékò̟ó̟ gboyè enjíníà kò rọrùn rárá.\nTádé, má sọ bé̟è̟ mó̟. Kò sí è̟kó̟ ìwé kankan tí ó rọrùn rárá. Șùgbọn tỉ\nènìyàn báá rójú, ènìyàn á jọrò̟ọ rẹ.\nOtító̟ ni ọrọọ rẹ o, Bùsólá. Mo ti gbo ohun tí o sọ. Màá ró̟jú.\nÓ dára béẹ. Jé kín kó̟ ẹ lórin tí bàbáa mi máa ń kọ láti gbàwá níyànjú kí a\nba à lè múra sí è̟kó̟o wa.\nBàtà rę á dún ko ko kà\nBàtà rę á dún ko ko kà\nBí o bá kȧwé rę, bàtà rẹ á dún ko ko kà\nBùsólá kàwé rẹ, bàtà rẹ á dún ko ko kà\nTádé kàwé rę, bàtà rẹ á dún ko ko kà\nBàtà rẹ á wó̟ ṣẹrẹrẹ nílè o\nBàtà rẹ á wó̟ ṣẹrẹrẹ nílè o\nBí o ò bá kàwé rẹ bàtà rẹ á wó̟ sẹrẹrẹ nílè̟.\nHáà! Bùsólá, O ti fún mi ní agbára ò̟tun láti kàwé síi.\nÓ dára o, alágbára ìwé.", "speaker_id": "34"}
{"line_id": "35yy", "file_name": "35-yy_ch12_l03_m01.mp3", "text": "Òpolopo ilé-ìwé ló wà ní tòótò̟, àmọ ti ilé-ìwée mi yàto gan-an ni. llé-ìwée mi yȧtò sí àwọn ilé-\nìwé yòóku. Oro mi yìí kojá àpónlé, béè̟ kì í se àponlu. Àwọn Yorùbá ní bí a kò bá dé oko\nbaba elomíràn wò, a kò lè mọ èyí tí ó tóbi jù nínú oko baba eni àti baba elomíràn.\nÈmi ti dé ilé-ìwé mìíràn, mo sì ti rí i dájú pé àjànàkú kojá mo ri nǹkan firí. Mo ti ri erin, mo sì\nmò̟ pé erin ni. Şé ti àwọn olùkó̟ tí wọn gbámúṣé ni kí n sọ ni tàbí ti àwọn ilé aláràbarà tí wọn\nwà ni kín wí?\nKá mú t'ègàn kúrò, ká tún fi t'ègàn kun, ilé-ìwé ni ilé-ìwéè mi. Yunifásítì ti Texas ní Austin\nni mò ń sọ. Gbogbo onà ni o lè gbà wọ ilé-ìwé mi yìí. Tí o bá wá gba iwájú ilé-ìfowopamosí\nwolé, ki o kàn gbé ojú wo ò̟ọkàn, wà á rí ilé gogoro. Gígaa rè fé è lè kan orun. llé yìí ni\nwon n pè ní \"UT Tower\". Ibè gan-an ni gbogbo ètò àti àṣẹ ilé-ìwée mi ti ń wá. Ènìyàn kò\ngbo̟dò̟ gbókè wòran rárá. Tí o bá gbìyànjú dé iwájú ilé yìí tàbí tí o ní àǹfààní láti wọ inúu\nrè, wà á kí ajé kú ìkòlé. Ilé-ìwéè mi dára t'ègan lókù. Ìwo gbìyànjú kí o wá, ìròyìn kò tó\nàfojúbà.", "speaker_id": "35"}
{"line_id": "36yy", "file_name": "36-yy_appx_syllabic-nasals.mp3", "text": "Adéńrelé\ndùndú\nBánké\ngbangba\nkonko\ngbàngbà\nDéńdè\nBóláńlé\nalángbá\nàǹkárá\nànfààní", "speaker_id": "36"}
{"line_id": "37yy", "file_name": "37-yy_appx_poem.mp3", "text": "Ìbàdàn\nllú ébá odan, olú ìpínlè̟ Òyó\nllú àwọn jagunjagun\nllú Lágelú àtOlúyòlé\nÌlú ìbíkúnlé òun Ògúnmolá\nOgun kò kóbàdàn rí\nÌbàdàn ló kó gbogbo won yéye\nìlú tó gbę àlejò, tó gbe oníle\nÌbàdàn ló fè fè fè\nTo kojáa Móníyà lonà Òyó\nTítí ó fi dé Ọmí Àdìó lónà Abéòkúta.\nOnídùndú lonà Ifè àti Onígàǹbàrí lonà Ìjèbú\nÌbàdàn, ìlú ológunlógó òrùlé\nElérò ènìyàn bi eşu yako\nBé e débàdàn, ẹ bá mi kí wọn lójà Òjé\nLójàaba, Dùgbé àt' Aléṣinloyé oun Gbagi tuntun\nNí bi ti wọn ti n şe kátàkárà\nTówó ti ń wolé sápò ìṣòwò ní pereu\nOlúbàdàn mo se o ní kábĺyèsí\nOba ìlú Ìbàdàn, mo gbósú bàǹbà\nìlú olóké púpò lèbá òdàn\nÒké Adó, Òkèe Mapó, Òkè Ààrę\nÒkée Séénì, Òkèe Bolà, Òkèe Bíókú\nÒkė Eléyelé, Òkèèbàdan!\nÒkèèbàdan dákun gbè mí o\nBí o ti gbe ara iwájú o\nEni to fapá se, fesè se nìbàdànán gbè\nNó şȧşekára ní těmi.", "speaker_id": "37"}
{"line_id": "38yy", "file_name": "38-yy_appx_vowels.mp3", "text": "Fáwọ̀jí Yorùbá (Yorùbá Vowels)\n\nàlá\nàrà\nàwà\nàsà\nàdà\nàló\nàfọ̀\nàdà\nàgbára\nàgà\n\nTone practice\nàcà\nàcá\nàcā\n\nÀjàlá je àpèjúwé Jidé\n\nÀdé je ìyẹn Jáyé\n\nẹwẹ̀\nẹwẹ́\nẹrẹ̀\nèdè\nòde\nọdẹ̀\nèdè\nòṣé\ngẹlẹ̀\nèkó\n\nTone practice:\nẹní\nẹní\nẹnī\n\nWhat is à to kìkì pro ọjẹ́\n\nDide dé èdè áńs.\n\nìwé\nìdẹ́\nìyàtọ̀\nìwé\nìlú\nìṣẹ́\nìyá\nìwé\nìdè\nTone practice:\nìní\nìní\nìnī\n\nOrọ́ je tàbí kórí kẹlẹ.\n\nPélépélé kojẹ́ í tápárá.\n\nìjó\nìjẹ́\nibí\nọmọ\niṣu\nìdí\nilé\nibẹ̀\nìdẹ̀j\n\nTone practice\nìbí\nìbí\nìbī\n\nÌyàtọ̀ fẹ́ rí mógbọn tá yẹn tòní.\n\nlọ́ lọ́ ní Jídé wá.\n\nBàbá dúdú ní orí ọjẹ gígọ.\n\nìwé\nèdè\nèké\nàdúrà\nòṣé\nẹbọ\nìdáná\nẹbọ̀\nọlàjú\n\nTone practice\nòjé\nojé\nọjẹ́\nòṣì\nòṣé\n\nỌjẹ́ gbowó lẹwọ́ ọlọ́run í Ọwódù.\n\nOlú dèédé sùn odò Mámúdù Tóbí.\n\nìwé\nẹ̀ṣẹ̀\ná jẹ\nà rí\nìdí\nẹjẹ́\nìdí\nìgbé\nèdè\nìkókó\nìmọ́lẹ̀\nìlọjọ̀\nNNPC\n\nTone practice\nèsè\nèsé\nèsē\n\nỌgbọ́n wò rẹ́ rán tí yẹnju tábitọ́run.\n\nOrí àná àtí ní ọrùn tí.\n\nìròyìn\nìsọ̀kàn\nìdàgbàsókè\n\n\n\n\njẹ\n\n\nTone practice:\nè\né\nē\n\nWo o kìní dúndú ńb'í Lágí.\n\nÀwọn bàǹtẹ́ ńb'í ilé Ọlọ́run.", "speaker_id": "38"}
{"line_id": "39yy", "file_name": "39-yy_appx_consonants.mp3", "text": "Kôñsónáõtì Yorùbá (Yorùbá Consonants)\n/b/\nbàbá\n\nbèrè\nBísí\nbàtà\n\n\nbèrù\nbúburú\nìbínú\n\nTone practice\n\n\nbi\nbo\nbo\nbọ\n\nBísí bá bábá bộ bàtà.\nOrin\nBá a bá léni\nBá a bá bánh\nìwòn là á bánií sòtá mọ\n\n/d/\nedá\nìdàmú\nìdále\nòòde\nòdėdė\ndárijì\nìdáwó\ndáwó\ndánilójú\nodė\node\n\nTone practice\n\n\nde\ndẹ\nedé\nèdè\node\nodę\n\nAdé dé adé oba ní Ayédé\nDàda tutù bí ẹyẹ àdàbà\n\n/f/\nIfẹ\nìfé\naféfé\nfunfun\nìfàkì\nféràn\nefun\nfún\nfilà\nFémi\n\nTone practice\n\n\nfó̟\nFémi férànan filà funfun.\nAféfé fé ìyẹ funfun náà lọ.\nFolá foso funfun fún Fémi.\n\n\n/g/\nògá\nògo\nogún\nogun\nÒgún\nogėdė\nagogo\nigi\nàga\n\n\nTone practice\ngùn\ngùn\ngún\n\nProverb\nIgi gogoro má gùn-ún mi lójú, òkèèrè la ti n wò ó.\n\nGbénga gé igi gíga.\n\nOwe\nIgi gogoro má gùn-ún mi lójú, òkèèrè la ti n wò ó.\n\n/gb/\ngbòngbò\nàgbà\negbé\négbé\nagbádá\nàgbàdo\nalángbá\nagbòòrùn\nìgbàgbo\n\nTone practice\nagbon\nàgbọn\nagbon\nàgbàrá\nagbára\n\nGbogbo àgbààgbà lo sí ojaa Gbági.\nGbogbo alángbá ń sá lángbáláńgbá nínú àgbàlá.\n\n/h/\nihò\nwàhálà\nWolé\n\n\n\nahon\neléhàá\nhọ\nìhà\n\nTone practice\nhan\nhàn\nhán\n\nha\n\nHíhanrun tí bàbáa Délé ń hanrun jé̟ wàhálà.\n\n/j/\n\nàjò\nojà\niji\nOjó\nòjò\noúnjẹ\nijù\nìjà\n\nTone practice\nėjė\néjé\n\nìjí jà ní ọjó̟ o̟jà ní ìjeje.\nJumokė judí ní ajo ijó.\n\n/k/\noká\noríkì\nkíákiá\neku\nkèké\nọkùnrin\nèrèké\nèké\nekùn\n\nTone practice:\nokò̟\nọkọ\noκό\nò̟kò̟\n\nKémi kí Kíké kááárò.\nKíké kí Kémi kááárò\n\nProverb\nKíkéré ni abéré ń kéré, kì í se mímì fún adie\n\n/l/\n\n\nle\n\nolá\nLékan\nlabalábá\nÀlàbá\nàlá\nláti\n\nTone practice\nlọ\nlọ\n\n\n\nLolá lá àlá lábà Àlàbá.\n\n\n/m/\nméjì\nìmò̟\nomowé\nọmọ\namò̟\nomobìnrin\nọmọkùnrin\nmámá\nomi\nmolémolé\n\nTone practice\nmó̟\nmò̟\nMo mu omi ní ilée màmàá Máyòwá.\nMàmáà mi mu omil mi.\n\nníbí\n\n/n/\nnĺbo\nnípon\nníwájú\nnísìnyí\nníbeyen\nnìkan\n\nnáírà\n\nTone practice\n\nni\n\n\n\nNíyì ná náírá nílé ànaa rè.\nNíran náwó nínȧákúnȧá.\n\n/p/\nàpá\nера\nepo\nаро\npotopótò\npátápátá\npín\npátá\npáálí\npàtàkì\n\nTone practice\napá\nȧpà\npón\npon\nPàkútée Péjú pa ẹyẹ àparò.\nParíolá pín èpà náà.\nPàdé pejò ní pápáa bó̟ò̟lù Àpápá\n\n/r/\nara\n\n\nrere\nrérìnín\nrárá\nronú\nrojó\nròyìn\nrántí\n\nTone practice\n\n\neré\nèrè\nerè\nère\nRírí tí Rèmí rí ò̟réè mi Rántí mú inuù Remí dùn.\nRemí ra ìresì ní Rémo.\n\n/s/\nìręsì\nìwòsí\nsùúrù\nesè\nìsìn\nsò̟rò̟\nSimilólú\nsinmi\nàìsàn\nàsè\n\nTone practice\nsìn\nsín\nsin\nìsìn\nèsín\nèsín\nSimilólá sinmi lójó ìsinmi\nSanmí binú sí Sánní.\n\n/ş/\nŞòkòtò\neşin\nişu\naṣọ\naláso\nŞadé\nŞolá\nsòro\nàṣà\nàşá\n\n\nTone practice\nṣé\nṣè\nàşà\nàşá\nŞadé subú níwájúu Şolá.\nŞé Şolá ń ṣiṣé ní soobù Şeye?\n\n/t/\natégùn\nàtélewó\nàti\nata\note\nọtí\ngbókìtì\ntélètélè\nòtító\nbàtà\n\nTone practice\nSángo Òtà\notá\nto\n\nTítí ta atá ní títì.\n\nProverb\nAtètè sùn làtètè jí.\n\nTítí ta atá ní títì.\n\nowe\nAtètè sùn làtètè jí.\n\n/w/\nìwé\nìwa\nwéréwéré\nweere\nwàhálà\nwó̟\n\n\n\nWolé\n\nTone practice\nìwé\niwe\nwọlé\nWėmimo\nWálé wọlée Wėmimo.\n\nWálé wolée Wolé.\n\nWálé wale mi.\n\n/y/\niyanrìn\nyȧto\nyìnyín\nyànmùyánmú\nyojú\nyìn\nYínká\nYemí\nyoyĺnyoyin\néyìn\n\nTone practice\nyo\nyo\nyará\nyarí\nOyȧyà ìyáa Yemi máyé yẹ ẹ.\nAyé ye Yelé ní ìlú Qyo.", "speaker_id": "39"}