|
[
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_001",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Dupe gba naira marun fún owó oúnjẹ kúrò ní ilé. Ó pàdé Iya Gbonke tó fún un ní naira mẹsan àti Baba Alatise tó fún un ní naira mejila bí ó ṣe ń lọ sí ilé-iwe. Èló ni owó tí Dupe ní jẹ lápapò?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_002",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Baba Sade fun Sade ni ẹkọ mẹwa. Sade fun Faderera ni ẹkọ meji. Mélò ni ẹkọ owó Sade kù?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_003",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Baba Jiginni gba Abeke niyanju lati jẹ ataare kookan lọjọjumọ fun ọsẹ meji gbako. Ataare melo ni o yẹ ki Abeke ra?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_004",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Oluko ri wipe Aarinola ko fi eti sile ninu yaara ikẹkọ, o si sọ fun wipe ki o lọ ka iye eranko ti o wa ninu ogba ile ikẹkọ naa. Ti ẹsẹ eranko ti o wa ninu ogba naa ba jẹ merindinlogota, ki ni idahun Aarinola yoo jẹ?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_005",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Ajani maa n sun fun wakati mẹjọ lojoojumọ. Ti o ba ji ni aago mẹsan ni àárọ̀ oni, aago mélò ni Ajani sun?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_006",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Bukola pinu láti fi 365 naira pa món ní ojoojúmó fún ọdun kan. Èló ni Bukola yóò ti fi pa món nígbà tí ọdún bá parí?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_007",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Aduke máa n lọ sí ibi isé ní ojoojúmó. Owó ọ̀yà re léyìn osù jé 60000 naira. Tí Aduke kò ba lọ sí ibi isé fún ọjọ́ marun ní osù yìí, èló ni owó osù re yóò jé l'ósù yìí?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_008",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Àgbè kan máa n lọ sisé l'óko fún wákàtí méfà lójoojúmó. Ní òsè yìí, kò leè lọ sí oko fún ọjọ kan nítorí òjò alágbára kan tí ó rò sulè ọjọ náà. Wákàtí mélòó ni àgbè náà fi sisé l'óko lápapò ní ọ̀sè yìí?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_009",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Ó gba enìkan ní ọjọ mésàn-án láti gbẹ kànga kan . Ọjọ mélòó ló ma gba ènìyàn meta láti gbé kànja mérindínlógójì?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_010",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Sade n tún yàra re se. Ó pinu láti kó asọ ogún géérégé sínú àpótí kòòkan. Ó ní orísìí asọ méji - ankara àti asọ àrán. Tí ó bá ní àpótí meta fún ankara àti àpótí méjì fún asọ àrán, asọ mélòó ni Sade ní lápàpoò?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_011",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Aduke wọ ọkọ̀ ojú irin láti Èkó lọ sí Sokoto. Ìrìnàjò náà yóò gba wákàtí márùn-dín-lógbón. Tí Aduke bá gbéra ní aago meje àárò ọjọ abameta, ọjọ wo ni Aduke yóò dé Sokoto?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_012",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Ajani bèrè isé ọde ní aago méje ìròlé, ó sì lo wákàtí méjj̀ilá gbáko. Aago mélòó ni Ajani padà sí ilé?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_013",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Faderera ní ẹgbèrún mewa lọwọ. Ó fi ìdá kan nínú ìdá marun owó náà ra oúnje, ó fi ìdá meji nínú marun ra ìwé, ósì fi ìda kan nínú merin ra asọ. ̀Eló ni owó náà sékù?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_014",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Tí a bá fi ẹgbẹ̀rúnméjì lé ní ọ̀tàlénígba naira kọ́ ọgbà yí oko ẹ̀wà onígun merin ká, èló ni a ná láti kọ́ abala kan nínú ọgbà náà?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_015",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Ade ra ẹyin méjìlá ní ẹgbẹrun marun naira. Ó ta ìkòòkan ní ẹgbẹta naira. Èrè èló ni Ade jẹ lórí ọjà náà?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_016",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Ajoke se ìgbéyàwó ní ọmọ ọdún márùnlélógún. Ó bí ọmọ àkọ́kọ́ léyìn ọdún marun. Kíni ọjọ orí Ajoke nígbà tí ó bí ọmọ yìí?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_017",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Ẹ̀ro àgbéléwò kan jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-lé-lógójẹ naira. Èdínwó ìdá meje àti ààbọ̀ nínú ọgọrun wà lórí ọjà náà tí a bá san owó náà lójú esè. Èló ní oníbàráà yóò san lórí ọjà yìí tí ó bá san owó náà lójú ẹsẹ̀?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_018",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Baba olówó kan ní òjìlénígba malu tí ó fẹ́ pín fún àwọn ọmọ rè mẹta ní ìwọ̀n mẹji sí mẹta sí marun. Mélòó ni ọmọ kòòkan yóò rí gbà?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_019",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Janduku kan lọ sí ilé ìrajà kan, ó sì jí ẹgbẹrún meji naira. Ó fi owó tí ó jí náà ra ìpápánu tí ó jé ẹgbẹrunkan-lé-nígba naira, ó sì gba àpò owó merin padà. Èló ni ilé ìrajà náà pàdánù?"
|
|
},
|
|
{
|
|
"id": "yoruba_arithmetic_020",
|
|
"subset": "arithmetic",
|
|
"question": "Alahji Malami ní malu ọgọ́òrún, ogíjì jé ako malu, mewa nínu abo malu náà ti bí ọmọ meta meta. Ọgbọn nínu abo malu náà ti bí ọmọ méjì méjì. Gbogbo awọn abo malu tókù ti bí ọmọ merin, merin. Mélòó ni gbogbo malu Alahji lápàpoò?"
|
|
}
|
|
]
|
|
|