Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
audio
audioduration (s)
0.66
25.7
text
stringlengths
16
345
Fón oúnjẹ rẹ sí ojú omi, torí pé léyìn ọjó púpò, wàá túnrí i. Pín in fún àwọn méje tàbí méjọ pàápàá, nítorí o kò mọàjálù tó máa dé bá ayé. Tí òjò bá ṣú lójú òrun, á rò sórí ilè; tí igi kan bá sì ṣubú sígúúsù tàbí sí àríwá, ibi tí igi náà ṣubú
sí, ibè ló máa wà. Ẹni tó bá ń wojú aféfé kò ní fún irúgbìn; ẹni tó bá sì ń woṣíṣú òjò kò ní kórè. Bí o ò ṣe mọ bí èmí ṣe ń ṣiṣé nínú egungun ọmọ tó wànínú aboyún, béè lo ò ṣe mọ iṣé Ọlórun tòótó, ẹni tó ń ṣeohun gbogbo. Fún irúgbìn rẹ ní àárò,
má sì dẹwó títí di ìròlé; nítorí o òmọ èyí tó máa ṣe dáadáa, bóyá èyí tàbí ìyẹn, ó sì lè jé àwọnméjèèjì ló máa ṣe dáadáa. Ìmólè dùn, ó sì dára kí ojú rí oòrùn. Tí èèyàn bá lo òpòọdún láyé, kí ó gbádùn gbogbo rè. Àmó, ó yẹ kó máa rántí
péàwọn ọjó òkùnkùn lè pò, asán sì ni gbogbo ohun tó ń bò wá ṣẹlè. Máa yò, ìwọ òdókùnrin, nígbà tí o ṣì jé òdó, sì jé kí ọkàn rẹmáa yò ní ìgbà òdó rẹ. Máa ṣe ohun tí ọkàn rẹ bá sọ, sì máa lọsíbi tí ojú rẹ bá darí rẹ sí; ṣùgbón mò pé Ọlórun tòótó máa dá ọléjó
lórí gbogbo nkan wònyí. Nítorí náà, mú àwọn ohuntó ń kó ìdààmú báni kúrò lókàn rẹ, kí o sì gbá àwọn ohun tó ńṣeni léṣe dà nù ní ara rẹ, torí pé asán ni ìgbà èwe àti ìgbà òdó.
Bí òkú eṣinṣin ṣe ń ba òróró ẹni tó ń ṣe lófínńdà jé, tí á sìmáa rùn, béè ni ìwà òmùgò díè ṣe ń ba ọgbón àti ògo jé. Ọkàn ọlógbón ń darí rè sí ònà tí ó tó, àmó ọkàn òmùgòmáa ń darí rè sí ònà tí kò tó. Ibikíbi tí òmùgò bá rìn sí, kòní lo làákàyè,
ó sì máa jé kí gbogbo èèyàn mò pé òmùgò niòun. Tí inú alákòóso bá ru sí ọ, má ṣe kúrò níbi tí o wà, torípé ìwà pèlé ń pètù sí àwọn èṣè ńlá. Ohun kan wà tó ń kó ìdààmú báni tí mo ti rí lábé òrun, àṣìṣe tí àwọn tí agbára wà lówó wọn ń ṣe: Àwọn òmùgò lóń wà ní òpò ipò
gíga, àmó àwọn tó dáńgájíá kì í kúrò ní ipò tórẹlè. Mo ti rí àwọn ìránṣé tó ń gun ẹṣin àmó tí àwọn olórí ń fẹsèrìn bí ìránṣé. Ẹni tó ń gbé kòtò lè já sínú rè; ẹni tó sì ń wó ògiriolókùúta, ejò lè bù ú ṣán. Ẹni tó ń gbé òkúta, òkúta náà lè
ṣe é léṣe, ẹni tó sì ń la gẹdú, gẹdú náà lè ṣe é ní jàbá. Tí irinṣé kan kò bá mú, tí ẹni tó fé lò ó kò sì pón ọn, ó máaní láti lo agbára tó pò gan-an. Àmó ọgbón ń mú kéèyàn ṣeàṣeyọrí. Tí ejò bá buni ṣán kí wón tó tù ú lójú, kí làfààní
atujú tógbówó. Òrò ẹnu ọlógbón ń mú ire wá, àmó ètè òmùgò ń faìparun rè. Òrò tó kókó jáde lénu rè jé òrò òmùgò, èyí tósì sọ gbèyìn jé òrò aṣiwèrè tó ń ṣekú pani. Síbè, ńṣe niòmùgò á máa sòrò lọ. Èèyàn ò mọ ohun tó máa ṣẹlè; ta ló lè sọ ohun tó máa ṣẹlèléyìn rè
fún un? Iṣé àṣekára òmùgò ń tán an lókun, torí kò tiè mọ bó ṣemáa rí ònà tó máa gbà lọ sínú ìlú. Ẹ wo bó ṣe máa burú tó fún ilè kan tí ọba rè jéọmọdékùnrin, tí àwọn ìjòyè rè sì máa ń bèrè àsè wọn ní àárò! Ẹ wo bó ṣe máa jé ohun ayò tó fún ilè náà, tí ọba rè bá
jéọmọ èèyàn pàtàkì, tí àwọn ìjòyè rè sì ń jẹun ní àkókò tí ó tó kíwón lè lágbára, kì í ṣe kí wón lè mutí yó! Ìwà òlẹ tó lé kenkà ló ń mú kí igi àjà tè, ọwó tó dilè sì ló ńmú kí ilé jò. Oúnjẹ wà fún èrín, wáìnì sì ń mú kí èèyàn gbádùn ayé; àmó owó la ń ṣe ohun gbogbo
tí a nílò. Kódà nínú èrò rẹ, má ṣe bú ọba, má sì bú olówó nínúyàrá rẹ; torí pé ẹyẹ kan lè gbé òrò náà tàbí kí ohun tó ní ìyétún òrò rẹ sọ.
Àwọn òrò akónijọ, ọmọ Dáfídì, ọba ní Jerúsálémù. Akónijọ sọ pé, Asán pátápátá gbáà! Asán pátápátá gbáà! Asán ni gbogbo rè! Èrè wo ni èèyàn rí jẹ nínú gbogbo iṣé àṣekára rè Èyí tó ń gbogbo
agbára rè ṣe lábé òrun? Ìran kan ń lọ, ìran kan sì ń bò, Àmó ayé wà títí láé. Oòrùn ń yọ, oòrùn sì ń wò; Léyìn náà, ó ń yára pa dà sí ibi tí á tún ti yọ. Èfúùfù ń lọ sí gúúsù, ó sì ń yí lọ sí àríwá; Yíyí ló ń yí po nígbà
gbogbo; èfúùfù ń yí po ṣáá. Gbogbo odò ló ń ṣàn lọ sínú òkun, síbè òkun kò kún. Ibi tí àwọn odò ti ṣàn wá, ibè ni wón ń pa dà sí, kí wóntún lè ṣàn jáde. Ohun gbogbo ló ń kó àárè báni; Kódà, ó kọjá ohun téèyàn lè sọ. Ìran kì í sú ojú;
Béè ni etí kì í kọ gbígbó. Ohun tó ti wà ni yóò máa wà, Ohun tí a sì ti ṣe la ó tún pa dà ṣe; Kò sí ohun tuntun lábé òrun. Ṣé ohun kan wà tí a lè sọ pé: Wò ó, tuntun ni? Ó ti wà tipétipé; Ó ti wà ṣáájú àkókò wa. Kò sí ẹni tó ń rántí àwọn
èèyàn ayé àtijó; Kò sì sí ẹni tó máa rántí àwọn tó ń bò; Béè ni àwọn tó máa wá nígbà tó bá yá kò ní rántí àwọnnáà. Èmi, akónijọ, ló ti ń jọba lórí Ísírélì ní Jerúsálémù. Mo ọgbón ṣe ìwádìí àti àyèwò ohun gbogbo tí a ti ṣe lábéòrun, ìyẹn iṣé tó ń tánni lókun tí Ọlórun
fún ọmọ aráyé tó ńmú kí ọwó wọn dí. Mo rí gbogbo iṣé tí a ṣe lábé òrun, Sì wò ó! asán ni gbogbo rè, ìmúlèmófo. Ohun tó ti wó, a kò lè mú un tó, Ohun tí kò sì sí, a kò lè kà á. Nígbà náà, mo sọ lókàn mi pé: Wò ó! Mo ti
ní ọgbón tó pògan-an ju ẹnikéni tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálémù, ọkàn mi sì tikó ọgbón àti ìmò tó pò gan-an jọ. Mo ọkàn mi sí mímọọgbón àti mímọ ìwà wèrè àti mímọ ìwà ègò, èyí pèlú jéìmúlèmófo. Nítorí òpò ọgbón máa ń mú òpò ìbànújé wá, Tó
jé pé ẹni tó ń ìmò kún ìmò ń ìrora kún ìrora.
Nítorí náà, rántí Ẹlédàá rẹ Atóbilólá nígbà òdó rẹ, kíàwọn ọjó wàhálà tó dé, kí àwọn ọdún náà tó dé nígbà tí wàásọ pé: Wọn ò mú inú mi dùn; kí oòrùn àti ìmólè àti òṣùpáàti àwọn ìràwò tó ṣókùnkùn, tí ojú òrun á sì tún ṣú léyìn tí òjòti rò;
ní ọjó tí àwọn èṣó ilé ń gbòn pèpè, tí àwọn ọkùnrinalágbára sì tè, tí àwọn obìnrin tó ń lọ nkan dáwó dúró nítorí péwọn ò pò mó, tí àwọn ọmọge tó ń wo ìta lójú fèrèsé sì rí i péòkùnkùn ṣú; nígbà tí àwọn ilèkùn tó jáde sí ojú ònà ti wà nítítì, nígbà
tí ìró ọlọ ti lọ sílè, nígbà tí èèyàn á jí nítorí ìró ẹyẹ, tíohùn gbogbo àwọn ọmọbìnrin tó ń kọrin kò sì dún sókè mó. Bákan náà, èèyàn á máa bèrù ibi tó ga, èrù á sì wà lójú ònà. Igi álímóńdì ń yọ ìtànná, tata ń wó ara rè lọ, àgbáyun
kápérì sìbé, torí pé èèyàn ń lọ sí ilé rè ayérayé, àwọn tó ń ṣòfò sì ń rìnkiri ní ojú ònà; kí okùn fàdákà tó yọ, kí àwo wúrà tó fó síwéwé, kí ìṣà tó wà níbi ìsun omi tó fó, kí kèké ìfami tó wà níbikòtò omi tó kán. Nígbà náà,
erùpè á pa dà sí ilè, bó ṣe wàtélè, èmí á sì pa dà sódò Ọlórun tòótó tó fúnni. Asán pátápátá gbáà! ni akónijọ wí. Asán nigbogbo rè. Kì í ṣe pé akónijọ di ọlógbón nìkan ni, ó tún máa ń kó àwọn èèyàn ní ohun tó mò, ó ronú jinlè, ó
sì wádìí fínnífínní, kí ó lèkó òpòlọpò òwe jọ. Akónijọ wá bó ṣe máa rí àwọn òrò tóń tuni lára, kó sì ṣàkọsílè àwọn òrò tó péye tó sì jé òtító. Òrò àwọn ọlógbón dà bí òpá késé màlúù, àkójọ òrò wọnsì dà bí ìṣó tó wọlé ṣinṣin; òdò olùṣó àgùntàn kan ni wón ti wá.
Yàtò sí àwọn nkan yìí, ọmọ mi, ṣóra: Kò sí òpin nínú ṣíṣeìwé púpò, fí àkókò tó pò jù kà wón sì ń kó àárè bá ara. Òpin òrò náà, léyìn gbígbó gbogbo rè ni pé: Bèrù Ọlórun tòótó, kí o sì pa àwọn àṣẹ rè mó, nítorí èyí ni gbogbo
ojúṣeèèyàn. Nítorí Ọlórun tòótó yóò dá àwọn èèyàn léjó lórí gbogbo ohun tí wón ṣe, títí kan gbogbo ohun tó fara pa mó, bóyáó dára tàbí ó burú.
Mo tún yè sí gbogbo ìwà ìnilára tó ń lọ lábé òrun. Mo ríomijé àwọn tí wón ń ni lára, kò sí ẹni tó máa tù wón nínú. Agbára wà lówó àwọn tó ń ni wón lára, kò sì sí ẹni tó máa tù wónnínú. Mo bá àwọn tó ti kú yò dípò àwọn tó ṣì wà láàyè. Ẹni tó sàn ju àwọn méjèèjì lọ ni ẹni tí wọn
ò tíì bí, tí kò tíì ríohun tó ń kó ìdààmú báni tí à ń ṣe lábé òrun. Mo ti rí bí ìdíje ṣe ń mú kí àwọn èèyàn máa sapá, kí wónsì máa fòye ṣiṣé; asán ni èyí pèlú, ìmúlèmófo. Òmùgò ká ọwó gbera, béè ló ń rù sí i. Èkúnwó kan ìsinmi sàn ju èkúnwó méjì
iṣé àṣekára àti líléohun tó jé ìmúlèmófo. Mo yè sí àpẹẹrẹ ohun míì tó jé asán lábé òrun: Ọkùnrin kan wà tó dá wà, kò ní ẹnì kejì; kò ní ọmọ, béè ni kòní ará, àmó iṣé àṣekára tó ń ṣe kò lópin. Ojú rè kò kúrò nínú kíkóọrò jọ. Àmó,
jé ó tiè bi ara rè pé, Ta ni mò ń tìtorí rè ṣiṣé káratí mo sì ń àwọn ohun rere du ara mi? Asán ni èyí pèlú, ó sì jéiṣé tó ń tánni lókun. Ẹni méjì sàn ju ẹnì kan lọ, nítorí pé wón ní èrè fún iṣéàṣekára wọn. Torí tí òkan nínú wọn bá ṣubú, èkejì lè gbé
edìde. Àmó kí ló máa ṣẹlè sí ẹni tó ṣubú tí kò sí ẹni tó máa gbé edìde? Bákan náà, tí àwọn méjì bá dùbúlè pa pò, ara wọn ámóoru, àmó báwo ni ẹnì kan ṣoṣo ṣe lè móoru? Ẹnì kan lèborí ẹni tó dá wà, àmó àwọn méjì tó wà pa pò lè kojú rè. Okùnonífónrán méta
kò ṣeé tètè fà já. Ọmọdé tó jé aláìní àmó tó jé ọlógbón sàn ju àgbàlagbà ọbató jé òmùgò, tí làákàyè rè kò tó láti gba ìkìlò mó. Nítoríinú èwòn ló ti jáde lọ di ọba, bó tiè jé pé ìgbà tí ẹni yẹn ńṣàkóso lówó ni wón bí i ní aláìní. Mo kíyè sí gbogbo àwọnalààyè tó
ń rìn káàkiri lábé òrun, mo tún kíyè sí bí nkan ṣe rífún ọmọ tó wá gba ipò ọba náà. Bó tilè jé pé àwọn èèyàn tóń tì í léyìn kò lókà, inú àwọn tó ń bò léyìn kò ní dùn sí i. Asánni èyí pèlú, ìmúlèmófo.
Ohun gbogbo ni àkókò wà fún, Àkókò wà fún gbogbo iṣé lábé òrun: Ìgbà bíbímọ àti ìgbà kíkú; Ìgbà gbígbìn àti ìgbà fífa ohun tí a gbìn tu; Ìgbà pípa àti ìgbà wíwòsàn; Ìgbà wíwólulè àti ìgbà kíkó; Ìgbà sísunkún
àti ìgbà rírérìn-ín; Ìgbà pípohùnréré ẹkún àti ìgbà jíjó; Ìgbà jíju òkúta sọ nù àti ìgbà kíkó òkúta jọ; Ìgbà gbígbánimóra àti ìgbà téèyàn ò ní gbáni móra; Ìgbà wíwá àti ìgbà gbígbà pé ó ti sọ nù; Ìgbà fí pa mó
àti ìgbà jíjù sọ nù; Ìgbà fífàya àti ìgbà ríránpò; Ìgbà dídáké àti ìgbà sísòrò; Ìgbà nínífèé àti ìgbà kíkórìíra; Ìgbà ogun àti ìgbà àlàáfíà. Kí ni èrè tí òṣìṣé rí jẹ látinú gbogbo ìsapá
rè? Mo ti ríiṣé tí Ọlórun gbé fún ọmọ aráyé láti mú kí ọwó wọn dí. Ó tiṣe ohun gbogbo rètèrente ní ìgbà tirè. Kódà ó ti ayérayé síwọn lókàn; síbè aráyé ò lè rídìí iṣé tí Ọlórun tòótó ti ṣe láé látiìbèrè dé òpin. Mo ti wá rí i pé kò
sí ohun tó dáa fún wọn ju pé kí wónmáa yò kí wón sì máa ṣe rere nígbà ayé wọn, àti pé kíkálukú máa jẹ, kó máa mu, kó sì jẹ ìgbádùn gbogbo iṣé àṣekárarè. Èbùn Ọlórun ni. Mo ti wá mò pé gbogbo ohun tí Ọlórun tòótó ṣe máa wàtítí láé. Kò sí nkan kan tí a máa
kún un, kò sì sí nkan kan tí amáa yọ kúrò nínú rè. Ọlórun tòótó ti ṣe é béè kí àwọn èèyàn lèmáa bèrù rè. Ohun tó bá ṣẹlè ti ṣẹlè rí, ohun tó sì ń bò ti wà télè; àmóỌlórun tòótó ń wá ohun tí a ti lépa. Mo tún ti rí i lábé òrun pé: Ìwà burúkú ti rópò
ìdájóòdodo, ìwà burúkú sì ti rópò òdodo. Torí náà, mo sọ lókànmi pé: Ọlórun tòótó yóò ṣe ìdájó olódodo àti ẹni burúkú, nítorí àkókò wà fún gbogbo iṣé àti gbogbo akitiyan. Mo tún sọ nípa àwọn ọmọ aráyé lókàn mi pé Ọlórun tòótómáa dán wọn wò, á sì jé kí
wón rí i pé bí ẹranko ni wón rí, nítorí pé ohun kan wà tó ń ṣẹlè sí èèyàn, ohun kan sì wà tóń ṣẹlè sí ẹranko; ohun kan náà ló ń ṣẹlè sí gbogbo wọn. Bí òkanṣe ń kú, béè ni èkejì ń kú; èmí kan náà ni gbogbo wọn ní. Torínáà, èèyàn kò lólá ju ẹranko lọ, nítorí pé asán ni ohun gbogbo.
Ibì kan náà ni gbogbo wọn ń lọ. Inú erùpè ni gbogbo wọnti wá, inú erùpè sì ni gbogbo wọn ń pa dà sí. Ta ló mòbóyá èmí èèyàn ń lọ sí òkè tàbí èmí ẹranko ń lọ sí ilè? Mo sì rí i pé kò sí ohun tó dáa fún èèyàn ju pé kó gbádùn iṣé rè, nítoríìyẹn ni èrè rè; torí ta ló
lè mú kó rí ohun tó máa ṣẹlè léyìn tó báti lọ?
Ṣó ẹsè rẹ nígbàkigbà tí o bá lọ sí ilé Ọlórun tòótó; ó sànkéèyàn wá fetí sílè ju kó mú ẹbọ wá bí àwọn òmùgò ti ń ṣe, nítorí wọn ò mò pé ohun tí wón ń ṣe kò dáa. Má ṣe yánu sòrò tàbí kí ọkàn rẹ sòrò láìronú níwájú Ọlórun tòótó, nítorí Ọlórun tòótó wà ní òrun àmó ìwọ wà ní ayé.
Ìdínìyẹn tó yẹ kí òrò rẹ mọ níwòn. Nítorí òpò iṣé máa ń múkí èèyàn lá àlá, àpòjù òrò sì máa ń mú kí àwọn òmùgò máa wíìrégbè. Nígbàkigbà tí o bá jé èjé fún Ọlórun, má falè, sanán, nítorí inú rè kì í dùn sí àwọn òmùgò. Ohun tí o jéjèé, sanán. Ó sàn kí o má ṣe
jéjèé ju pé kí o jéjèé, kí o má sì san án. Má ṣe jé kí ẹnu rẹ mú ọ déṣè, má sì sọ níwájú áńgélì péàṣìṣe ni. Kí nìdí tí wàá mú Ọlórun tòótó bínú nítorí ohun tí osọ, tí á sì pa iṣé ọwó rẹ run? Nítorí bí òpò iṣé ṣe ń mú kíèèyàn lá àlá, béè ni òrò púpò ṣe ń já sí asán.
Àmó, Ọlóruntòótó ni kí o bèrù. Tí o bá rí i tí wón ń ni àwọn aláìní lára tàbí tí wón ń tẹ ìdájóòdodo àti òtító lójú ní agbègbè rẹ, má ṣe jé kó yà ó lénu. Torí ẹnì kan wà tó ń ṣó ẹni tó wà nípò gíga, ẹni yẹn sì ga jù ú lọ, síbèàwọn míì tún wà tó ga jù wón lọ.
Bákan náà, wón pín èrè ilè náà láàárín ara wọn; kódà inúoko ni oúnjẹ ọba ti ń wá. Fàdákà kì í tó ẹni tó bá nífèé fàdákà, béè ni owó kì í tó ẹnitó bá nífèé ọrò. Asán ni èyí pèlú. Nígbà tí ohun rere bá pò sí i, àwọn tó ń jẹ é á pò sí i. Àfààní wo ló sì jé fún ẹni tó ní
in ju pé kó máa ojú rè wò ó? Oorun ẹni tó ń sìn máa ń dùn, bóyá oúnjẹ díè ló jẹ tàbípúpò, àmó òpò rẹpẹtẹ tí ọlórò ní kì í jé kó rí oorun sùn. Àdánù ńlá kan wà tí mo ti rí lábé òrun: ọrò tí àwọnọlórò kó pa mó fún ìpalára ara wọn. Àwọn ọrò yẹn ṣègbénítorí
òwò àṣedànù, nígbà tó sì bímọ, kò ní ohun ìní kankanlówó mó. Bí èèyàn ṣe jáde wá látinú ìyá rè ní ìhòòhò, béè náà ni yóòṣe lọ. Kò lè mú ohunkóhun lọ nínú gbogbo iṣé àṣekára tó ti ṣe. Èyí pèlú jé àdánù ńlá: Bí ẹni náà ṣe wá gélé, béè ló ṣemáa lọ;
èrè wo ló sì wà fún ẹni tó ń ṣiṣé kára lórí asán? Yàtò síyẹn, ojoojúmó ló ń jẹun nínú òkùnkùn pèlú ìbànújéńlá àti àìsàn àti ìbínú. Ohun tí mo rí pé ó dára tí ó sì tó ni pé: kéèyàn máa jẹ, kómáa mu, kó sì jẹ ìgbádùn gbogbo iṣé àṣekára tó gbogboagbára rè ṣe lábé òrun láàárín
ọjó díè tí Ọlórun tòótó fún un, nítorí èrè rè nìyẹn. Bákan náà, nígbà tí Ọlórun tòótó báfún ẹnì kan ní ọrò àti ohun ìní, tó sì jé kó lè gbádùn wọn, kí ẹnináà gba èrè rè kó sì máa yò nínú iṣé àṣekára rè. Èbùn Ọlórunni èyí. Torí bóyá ló máa mò pé ọjó ayé òun ń
lọ, nítorí Ọlórun tòótó ti mú kí ayò gbà á lókàn.
Nígbà náà, mo sọ lókàn mi pé: Wá, jé kí n dán ìgbádùn wò, kí n sì rí ohun rere tó máa tibè wá. Àmó wò ó! asán ni èyí pèlú. Mo sọ nípa èrín pé, Wèrè ni! Àti nípa ìgbádùn pé, Kí ni ìwúlò rè? Mo mu wáìnì, kí n lè ọkàn mi ṣèwádìí,
àmó ní gbogboàkókò yìí mi ò sọ ọgbón mi nù; kódà, mo fara mó ìwà ègò kí n lèrí ohun tó dáa jù lọ fún ọmọ aráyé láti máa ṣe láàárín ọjó díè tíwón máa lò lábé òrun. Mo ṣe àwọn iṣé ńlá. Mo kó àwọn iléfún ara mi; mo gbin àwọn ọgbà àjàrà fún ara mi. Mo ṣeàwọn ọgbà ògbìn àti ọgbà ìtura
fún ara mi, mo sì gbin oríṣiríṣi igieléso sínú wọn. Mo ṣe àwọn adágún omi fún ara mi, láti máa bomi rin ọgbà tí àwọn igi tó léwé dáadáa wà. Mo ní àwọnìránṣé lókùnrin àti lóbìnrin, mo sì ní àwọn ìránṣé tí wón bí níagbo ilé mi. Mo tún ní òpò ẹran òsìn, ìyẹn màlúù àti agbo ẹran,
tó pò ju ti ẹnikéni tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálémù. Mo kófàdákà àti wúrà jọ fún ara mi, ìṣúra àwọn ọba àti ti àwọnìpínlè. Mo kó àwọn akọrin lókùnrin àti lóbìnrin jọ fún ara mi, títí kan ohun tó ń múnú ọmọ aráyé dùn gidigidi, ìyẹn obìnrin, àní òpò obìnrin. Torí náà,
mo dẹni ńlá, mo sì ga ju gbogboàwọn tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálémù. Béè ni ọgbón mi kò mísílè. Mi ò ohunkóhun tí mo fé du ara mi. Kò sí irúìgbádùn tí ọkàn mi fé tí mi ò fún un, torí ọkàn mi ń yò nítorígbogbo iṣé àṣekára mi, èyí sì ni èrè mi nínú gbogbo iṣé àṣekárami.
Àmó nígbà tí mo ronú lórí gbogbo iṣé tí ọwó mi ti ṣe àtigbogbo iṣé àṣekára tí mo ti sapá láti ṣe yọrí, mo rí i pé asán nigbogbo rè, ìmúlèmófo; kò sí ohun gidi kan lábé òrun. Mo wá yè sí ọgbón àti ìwà wèrè àti ìwà ègò. Mo rí
i pé àfààní wà nínú ọgbón ju ìwà ègò lọ, bí àfààníṣe wà nínú ìmólè ju òkùnkùn lọ. Ojú ọlógbón wà ní orí rè; àmó òmùgò ń rìn nínúòkùnkùn. Mo sì wá rí i pé ohun kan náà ló ń ṣẹlè sí gbogbowọn. Léyìn náà, mo sọ lókàn mi pé: Ohun tó ṣẹlè síòmùgò ló máa ṣẹlè sí èmi náà.
Kí wá ni èrè ọgbón tí mo gbónní àgbónjù? Mo sì sọ lókàn mi pé: Asán ni èyí pèlú. Nítorí akì í rántí ọlógbón tàbí òmùgò títí lọ. Bó pé bó yá, a ò ní rántíẹnikéni mó. Báwo sì ni ọlógbón ṣe máa kú? Á kú pèlú àwọnòmùgò. Ayé wá sú mi, nítorí
gbogbo ohun tí à ń ṣe lábé òrun lóń kó ìdààmú báni lójú tèmi, torí asán ni gbogbo rè, ìmúlèmófo. Mo wá kórìíra gbogbo iṣé àṣekára tí mo ti ṣelábé òrun, torí mo gbódò í sílè fún ẹni tó ń bò léyìn mi. Ta ló sì mò bóyá ó máa jé ọlógbón tàbí òmùgò? Síbè, òunni yóò máa darí
gbogbo ohun tí mo ti akitiyan àti ọgbón kó jọ lábé òrun. Asán ni èyí pèlú. Torí náà, ìrèwèsì ọkàn bèrè síí bá mi nítorí gbogbo iṣé àṣekára tí mo gbogbo agbára mi ṣelábé òrun. Nítorí èèyàn lè ọgbón àti ìmò àti òye ṣiṣé níàṣekára, àmó ó gbódò èrè rè
sílè fún ẹni tí kò ṣiṣé fún un. Asán ni èyí pèlú àti àdánù ńlá. Kí tiè ni èrè tí èèyàn rí jẹ nínú gbogbo iṣé àṣekára rè àtigbogbo bó ṣe ń wù ú láti ṣiṣé kára lábé òrun? Torí nígbogbo ọjó ayé rè, iṣé rè ń mú ìrora àti ìjákulè bá a, kódà kì í ríoorun sùn lóru. Asán ni
èyí pèlú. Kò sóhun tó dáa fún èèyàn ju pé kó jẹ, kó mu, kó sìgbádùn iṣé àṣekára rè. Èyí pèlú ni mo ti rí pé ó wá láti ọwó Ọlórun tòótó, àbí ta ló ń jẹ, tó sì ń mu ohun tó dáa ju tèmilọ? Ọlórun ń fún ẹni tó bá ń ṣe ìfé rè ní ọgbón àti ìmò àtiìdùnnú, àmó ó ń fún àwọn
ẹléṣè ní iṣé kíkó jọ àti ṣíṣà jọ kí wónlè fún ẹni tó ń ṣe ìfé Ọlórun tòótó. Asán ni èyí pèlú, ìmúlèmófo sì ni.
Àdánù míì wà tí mo ti rí lábé òrun, ó sì máa ń ṣẹlè láàárínàwọn èèyàn: Ọlórun tòótó fún ọkùnrin kan ní ọrò àti ohunìní àti ògo, tí kò ṣaláìní ohunkóhun tí ọkàn rè fé; síbè Ọlóruntòótó kò jé kó gbádùn àwọn ohun náà, àmó ó jé kí àlejò gbádùnwọn. Asán
ni èyí àti ìpónjú tó lágbára. Tí ọkùnrin kan bábímọ ní ọgórùn-ún ìgbà, tó lo òpò ọdún láyé, tó sì darúgbó, síbètí kò gbádùn àwọn ohun rere tó ní kó tó wọnú sàréè, ohun tímàá sọ ni pé ọmọ tí wón bí ní òkú sàn jù ú lọ. Torí pé ẹni yìíwá lásán, ó sì lọ nínú òkùnkùn,
òkùnkùn bo orúkọ rè mólè. Bó tilè jé pé kò rí oòrùn, kò sì mọ nkan kan, ó ṣì sàn ju ẹniìṣáájú lọ. Kí làfààní kéèyàn gbé ẹgbèrún ọdún láyé ní ìlópoméjì, àmó kó má gbádùn nkan kan? Torí pé ibì kan náà nigbogbo èèyàn ń lọ. Gbogbo iṣé àṣekára téèyàn ń ṣe,
torí kó lè rí nkan sénuni; síbè kì í yó. Nítorí àfààní wo ni ọlógbón ní lóríòmùgò? Tàbí àfààní kí ló jé fún aláìní pé ó mọ bí èèyàn ṣe ńtójú ara rè? Ó sàn kéèyàn máa gbádùn ohun tí ojú rè rí ju kó máa dààmú lórí ohun tí ọkàn rè fé. Asán ni èyí pèlú, ìmúlèmófo.
Ohunkóhun tó bá wà, ó ti ní orúkọ télè, a ti mọ ohun tíèèyàn jé; kò sì lè bá ẹni tó lágbára jù ú lọ jiyàn. Bí òrò báṣe pò náà ni asán á ṣe pò, àfààní wo sì ni èèyàn máa rí nínúwọn? Ta ló mọ ohun tó dára jù lọ fún èèyàn láti ayé rè ṣeláàárín ọjó díè tó máa gbé
ìgbé ayé asán, èyí tó máa kọjá lọ bíòjìji? Àbí ta ló lè sọ ohun tó máa ṣẹlè lábé òrun fún èèyàn léyìn tó bá ti lọ?
Nítorí náà, mo fọkàn sí gbogbo èyí, mo sì gbà pé ọwó Ọlórun tòótó ni àwọn olódodo àti àwọn ọlógbón wà pèlú iṣé wọn. Àwọn èèyàn kò mọ ìfé àti ìkórìíra tó ti wà ṣáájú wọn. Ohun kan náà ló ń gbèyìn gbogbo wọn, àti olódodo àti ẹni burúkú, ẹni rere pèlú ẹni
tó mó àti ẹni tí ò mó, àwọn tó ń rúbọ àti àwọntí kì í rúbọ. Ìkan náà ni ẹni rere àti ẹléṣè; bákan náà ni ẹni tóbúra rí pèlú ẹni tó ń bèrù láti búra. Ohun kan ń ṣẹlè lábéòrun tó ń kó ìdààmú báni: Nítorí ohun kan náà ló ń ṣẹlè sígbogbo wọn, aburú ló kún ọkàn àwọn
ọmọ èèyàn; ìwà wèrè wàlókàn wọn ní ọjó ayé wọn, léyìn náà wón á kú! Ìrètí wà fún ẹni tó bá ṣì wà láàyè, nítorí ààyè ajá sàn ju òkúkìnnìún lọ. Nítorí àwọn alààyè mò pé àwọn máa kú, àmóàwọn òkú kò mọ nkan kan rárá, wọn kò sì ní èrè kankan mó, nítorí pé
wón ti di ẹni ìgbàgbé. Bákan náà, ìfé wọn àtiìkórìíra wọn pèlú owú wọn ti ṣègbé, wọn kò sì ní ìpín kankan mónínú ohun tí à ń ṣe lábé òrun. Máa lọ, máa ayò jẹ oúnjẹ rẹ, kí o sì máa ìdùnnú mu wáìnì rẹ, nítorí inú Ọlórun tòótó ti dùn sí àwọn iṣé rẹ.
Kíaṣọ rẹ máa funfun ní gbogbo ìgbà, kí o sì máa òróró pa orí rẹ. Máa gbádùn ayé rẹ pèlú aya rẹ òwón ní gbogbo ọjó ayéasán rẹ, tí Ó fún ọ lábé òrun, ní gbogbo ọjó ayé asán rẹ, toríìyẹn ni ìpín rẹ nígbèésí ayé àti nínú iṣé àṣekára rẹ, èyí tí ò ń gbogbo agbára rẹ ṣe lábé òrun.
Ohunkóhun tí ọwó rẹ bá ríláti ṣe, gbogbo agbára rẹ ṣe é, nítorí pé kò sí iṣé tàbí èrò tàbíìmò tàbí ọgbón nínú Isà Òkú, ibi tí ìwọ ń lọ. Mo tún ti rí nkan míì lábé òrun, pé ìgbà gbogbo kó niẹni tí ẹsè rè yá máa ń mókè nínú
eré ìje, béè ni kì í ṣe gbogboìgbà ni àwọn alágbára máa ń borí lójú ogun, béè ni àwọnọlógbón kì í fìgbà gbogbo rí oúnjẹ jẹ, ìgbà gbogbo kó sì ni àwọnolórí pípé máa ń ní ọrò, bákan náà àwọn tó ní ìmò kì í fìgbàgbogbo ṣe àṣeyọrí, nítorí ìgbà àti èèṣì ń ṣẹlè sí gbogbo
wọn. Èèyàn kò mọ ìgbà tirè. Bí ẹja ṣe ń kó sínú àwòn ikú, tíàwọn ẹyẹ sì ń kó sínú pańpé, béè ni àwọn ọmọ èèyàn ṣe ń kósínú ìdẹkùn ní àkókò àjálù, nígbà tó bá dé bá wọn lójijì. Mo tún kíyè sí nkan kan nípa ọgbón lábé òrun, ó sì wúmi lórí: Ìlú kékeré kan wà tí èèyàn ò béè pò
sí; ọbaalágbára kan wá gbéjà kò ó, ó yí i ká, ó sì ṣe àwọn nkan ńlá tí á gbógun ti ìlú náà. Ọkùnrin kan wà níbè tó jé aláìní àmó tóní ọgbón, ó sì ọgbón rè gba ìlú náà sílè. Àmó kò séni tó rántíọkùnrin aláìní náà. Mo wá sọ fún ara mi pé: Ọgbón
sàn juagbára lọ; síbè àwọn èèyàn kì í ka ọgbón aláìní sí, wọn kì í sì íṣe ohun tó bá sọ. Ó sàn kéèyàn tè lé òrò jééjéé tí ọlógbón sọ ju kéèyàn máafetí sí ariwo ẹni tó ń ṣàkóso láàárín àwọn òmùgò. Ọgbón sàn ju àwọn ohun ìjà ogun lọ, àmó ẹléṣè kan ṣoṣo lè ba òpò ohun rere jé.
Orúkọ rere sàn ju òróró dáradára, ọjó ikú sì sàn ju ọjó tí abíni lọ. Ó sàn láti lọ sí ilé òfò ju láti lọ sí ilé àsè, torí pé ìyẹnni òpin gbogbo èèyàn, ó sì yẹ kí àwọn alààyè sókàn. Ìbànújésàn ju èrín lọ, torí ojú tó fà ro ń mú kí ọkàn túbò
ṣiṣé dáadáa. Ọkàn ọlógbón wà ní ilé òfò, àmó ilé ìdùnnú ni ọkàn òmùgòwà. Ó sàn kéèyàn fetí sí ìbáwí ọlógbón ju kéèyàn máa gbóorin àwọn òmùgò. Torí pé bí ègún tó ń jó lábé ìkòkò ṣe máa ńta pàrà, béè ni èrín òmùgò rí; asán
sì ni èyí pèlú. Ìnilára lèmú kí ọlógbón ṣe bíi wèrè, àbètélè sì ń sọ ọkàn dìdàkudà. Òpin nkan sàn ju ìbèrè rè lọ. Ó sàn kéèyàn ní sùúrù ju pékéèyàn ní èmí ìgbéraga. Má ṣe máa yára bínú, torí péàyà àwọn òmùgò ni ìbínú ń gbé.
Má sọ pé, Kí nìdí tí àwọn ọjó àtijó sàn ju ti ìgbà yìí lọ? torí pé kì í ṣe ọgbón ló mú kí o béèrè béè. Ọgbón pèlú ogún jé ohun tó dáa, ó sì jé àfààní fún àwọntó ń rí ìmólè ọjó. Nítorí ọgbón jé ààbò bí owó ṣe jé ààbò, àmó àfààní ìmò ni pé: Ọgbón máa ń dá èmí àwọn
tó ní in sí. Kíyè sí iṣé Ọlórun tòótó, ta ló lè mú kí ohun tó ṣe ní wíwótó? Ní ọjó tí nkan bá dáa, jé kó hàn lójú rẹ, àmó ní ọjóàjálù, yè sí i pé Ọlórun ti ṣe àkókó àti èkejì, kí aráyé má bàa lèsọ ní pàtó ohun tó máa ṣẹlè sí wọn lójó iwájú.
Ohun gbogbo ni mo ti rí ní gbogbo ìgbé ayé asán mi, látorí olódodo tó ṣègbé nínú òdodo rè, dórí ẹni burúkú tó péláyé bó tilè jé pé ìwà burúkú ló ń hù. Má ṣe òdodo àṣelékè, béè ni kí o má ṣe gbón ní àgbónjù. Àbí o fé pa ara rẹ ni? Má sọ ìwà burúkú
dàṣà, má sì yaòmùgò. Ṣé ó yẹ kí o kú láìtójó ni? Ó sàn kéèyàn gba ìkìlòàkókó, kó má sì jé kí èkejì bó mó òun lówó; nítorí ẹni tó bábèrù Ọlórun yóò pa méjèèjì mó. Ọgbón máa ń mú kí ọlógbón lágbára ju akíkanjú ọkùnrinméwàá tó ń ṣó ìlú.
Nítorí kò sí olódodo kankan láyé tó ń ṣerere nígbà gbogbo tí kì í déṣè. Bákan náà, má ṣe máa fọkàn sí gbogbo òrò tí àwọn èèyànbá sọ; àìjé béè, o lè gbó tí ìránṣé rẹ ń bú ọ; torí o mòlókàn rẹ dáadáa pé òpò ìgbà ni ìwọ fúnra rẹ ti bú
àwọn míì. Gbogbo èyí ni mo ti ọgbón dán wò, mo sì sọ pé: Màá diọlógbón. Àmó, ó kọjá agbára mi. Ohun tó ti wà, ọwó ò lè tóo, ó sì jinlè gidigidi. Ta ló lè lóye rè? Mo darí ọkàn mi kí nlè mò, kí n lè wádìí, kí n sì lè wá ọgbón
àti ohun tó ń fa àwọnnkan tó ń ṣẹlè, mo sì darí rè kí n lè lóye aburú tó wà nínú ìwàègò àti àìlógbón tó wà nínú ìwà wèrè. Mo wá rí i pé: Ohuntó korò ju ikú lọ ni obìnrin tó dà bí àwòn ọlódẹ, tí ọkàn rè dà bíàwòn ńlá, tí ọwó rè sì dà bíi ṣẹkéṣẹkè.
Ẹni tó bá ń ṣe ìfé Ọlórun tòótó á bó lówó rè, àmó ẹléṣè á kó sówó rè. Akónijọ sọ pé, Wò ó! èyí ni mo ti rí. Mo gbé àwọn nkanyè wò léyọ kòòkan kí n lè mọ ibi tí màá parí èrò sí, àmó miò tíì rí ohun tí mò ń ìgbà
gbogbo wá. Mo rí ọkùnrin kan nínúẹgbèrún, àmó mi ò tíì rí obìnrin kan nínú wọn. Èyí nìkanṣoṣo ni mo ti rí pé: Ọlórun tòótó dá aráyé ní adúróṣinṣin, àmówón ti wá òpò ètekéte.
Òwe Sólómónì, ọmọ Dáfídì, ọba Ísírélì: Láti kó ọgbón àti ìbáwí; Láti lóye àwọn òrò ọgbón Láti gba ìbáwí tó ń fúnni ní ìjìnlè òye, Òdodo, ìdájó òdodo àti ìdúróṣinṣin; Láti mú kí àwọn aláìmòkan ní àròjinlè;
Láti mú kí òdókùnrin ní ìmò àti làákàyè. Ọlógbón máa ń fetí sílè, á sì kó èkó sí i; Olóye máa ń gba ìtósónà ọlọgbón Láti lóye òwe àti òrò tó díjú, Òrò àwọn ọlógbón àti àló wọn. Ìbèrù Jèhófà ni ìbèrè ìmò.
Àwọn òmùgò ni kì í ka ọgbón àti ìbáwí sí. Ọmọ mi, fetí sí ìbáwí bàbá rẹ, Má sì pa èkó ìyá rẹ tì. Wón dà bí adé ẹwà fún orí rẹ Àti ohun òṣó tó rẹwà fún ọrùn rẹ. Ọmọ mi, tí àwọn ẹléṣè bá fé fa ojú
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
98