Dataset Viewer
sentence
stringlengths 14
109
| root
stringlengths 2
6
| root_meaning
stringlengths 3
64
⌀ |
---|---|---|
Ówo tí ó sọ mí ní igi imú ni kò jẹ́ kí n mi dáadáa | ÓWO | BOIL |
Abọ́ ayọ́ ni ọmọ náà fi n jẹun | Ayọ́ | Aluminum |
Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù ní mo já orín náà | Orín | chewing stick |
kí ni wọn mú oyún wúndíá se ní òkò | Òkò | A town in Oyo state |
Orogún ìyá Kọ́lá lo ràn-án lọ́wọ́ | OROGÚN | RIVAL |
Ere ṣíṣá ni iṣẹ́ ẹṣin | ẸSIN | HORSE |
Wọ́n dá arákùnrin náà dúró sílé ìwòsàn ní torí ẹ̀ya ara rẹ̀ | Ẹ̀ya | Tears |
Ìdí tí Gboyega ko se wa sí ibi isẹ ko ye mi | Ìdí | Reason |
Ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN ni ko jòkó sí | Ọ̀tún | right |
Eku àgó mẹ́ta ni a bá nínú omi inú ada | ÀGÓ | A TYPE OF RAT |
Obì inú kókó náà so púpọ̀ | Obì | Colanut |
Ọwọ́ ọmọ náà yá níbi ọ̀wẹ búbù | Ọ̀wẹ | MORSEL |
Ọ̀TÙN jẹ ara olú ìlú ìpínlẹ̀ èkìtì | Ọ̀TÙN | A city in Ekiti |
Ọ̀kan lára erè ìdárayá ni bọọlu gbigba wà | Eré | Play/Drama |
Ọkan lára àwọn akọni ní lẹ̀ yoruba ni Ajagúnlá tí o tẹ ìlú ìlá do | Ìlá | a town in Osun state |
Èṣù ni Ogbẹni Akintọla yìí o, òun ni ó dá áwọ̀ sílẹ̀ láàárín Ọlá àti Ìbùkún | ÈṢÙ | DEVIL |
okó ní ọmọkùnrin ń fi se ọkọ obìnrin | Okó | penis |
Mo fẹràn ìlù púpọ̀ níbi àríyá | Ìlù | drum |
Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí mo fẹràn jùlọ | Ẹ̀kọ | Local food derived from maize |
OLORÌ ọba ìlú mi rẹ̀wá púpọ̀ | OLORÌ | QUEEN |
Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá | KẸKẸ | A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH |
Ìlú Ọ̀rẹ̀ ni ìyàwó mi bímọ sí | Ọ̀RẸ̀ | A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA |
Ìgbà ko tọ́ lọ bi orere | Ìgbà | Time |
Gbogbo àwọn ọdẹ abúlé wa ti gbára dì láti kojú ìkokò ọdaju náà | ÌKOKÒ | HYENA |
Mo bẹ̀rù ọmọ náà púpọ̀, nítorí pé asa ni | ASA | TALKATIVE |
Agbè yìí ti lu nìdí | AGBÈ | BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER |
Ajá jẹ gbogbo egun náà tán | Egun | Bone |
ọkùnrin tó sun rárà fún ọkùnrin ẹgbẹ rẹ̀ | Rárà | A type of song/elegy |
Àwọn àgbà ló lè yanjú ọ̀rọ̀ yìí | ÀGBÀ | ELDERLY PERSON |
Irọ́ ni Bola n pa fún àwọn òbí rẹ̀, ṣugbọn àbúrò rẹ̀ lo járọ́ rẹ̀ | Járọ́ | To expose a lie |
Pí Padé ni ilẹkun ilé iṣẹ́ wà di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yii | PADÉ | TO SHUT, TO CLOSE UP |
Ó ti rẹ ẹyẹ agbe yìí débi wípé kò lè fò dáadáa mọ́ | AGBE | A TYPE OF BIRD |
Iya àgbà ran Fọlákẹ́ ni Erèé l'ọja | Erèé | Beans(coupea) |
Baba gbìyànjú láti ré ègún kúrò lórí àwọn ọmọ | Ègún | Spell, curse |
Olóyè jagun gbìyànjú láti dáàbò bo ìlú rẹ | Jagun | A military title |
Ẹranko kò ní ohun méjì tí o fi ń se agbára kọjá ìwo | Ìwo | Animal horn |
Ókéré gbádùn ẹyìn jíjẹ | Ẹyìn | palm tree fruit |
Ọ̀ọni fi ìrù rẹ na ẹkùn ní ojú | Ìrù | tail |
Tí ẹ kò bá sà àwọn isẹpẹ igi náà dáadáa, ebè kíkọ náà kò ní yá | SÀ | PICK |
Ní aláìsí ìṣẹ̀lẹ̀, kì í sí ìtàn | ÌTÀN | STORY |
Ẹ̀re agbabọ́ọ̀lù náà wà ní pápá ẹgbẹ agbabọ́ọ̀lù rẹ̀ | Ère | Statue |
Owò tí ènìyàn ba mọ ni kí ó tẹra mọ́ | Owò | business |
Ọmọ náà ní ẹ̀jẹ̀ púpọ̀ lára | Ẹ̀jẹ̀ | Blood |
Ọjọ́ tí ẹ bá lọ sí oko, ẹ dákun ẹ bá mi gé okùn agba bọ̀ | AGBA | A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST |
ìyá ran ọmọ ní Abó ni oja | Abọ́ | plate |
Ọ̀wẹ tí ẹnu rẹ bá gbà ní kí ó máa bù | Ọ̀wẹ | MORSEL |
Ẹ sáré bá Ìyá Ìtùnú mú ife kan wá | IFE | CUP |
Lọ sun ilẹ̀ tí mo gbé sí èyìnkùlé | Sun | To burn |
Ọmọ ìlú Òró ni ìyàwó mi | ÒRÓ | A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA |
Egbò náà tí di ọyún sí inú gan-an ni o | ỌYÚN | TUMOR |
Àwọn amọ̀kòkò pọ̀ ni abúlé wa | ÌKÒKÒ | CLAY RESERVOIR |
Inú igbó ní wón sin òkú ẹni ti o bá ní iké sí | Iké | hunchback |
Mo bẹ̀rù awọn ọmọ bẹrẹ púpọ̀ | BẸRẸ | AN AREA IN IBADAN, OYO STATE |
Àwọn Agbè-fún-ọba rí pé àwọn doọ̀là àwọn ọmọ ìlú lọ́wọ́ àwọn ọdanran ni ÀYÈ | ÀYÈ | ALIVE |
Ọjà ni Ade ti bá ọrẹ rẹ atijọ pade | Ọjà | market |
Mo ti fi ìgbà kan jẹ ejò ỌKÁ rí | ỌKÁ | COBRA |
Àwọn olórin fẹràn Abo púpọ̀ | Abo | Female |
Ilé-Ifè ni ìran Yorùbá ti sẹ̀ wá | IFẸ̀ | A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní kó Ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ síáyẹ́nsì | Ẹ̀KỌ́ | Knowledge |
Bàbá naa jẹ́jẹ̀ pe awon kòní na ọmọ náà | Jẹ́jẹ̀ | To make a vow |
Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi | KẸ́KẸ́ | A PECULIAR FACIAL MARK |
Àgbẹ̀ náà fí inú oko rẹ kí àwọn irú náà le dínkù | Irù | tsetse fly |
Olóńgbò tó jẹ́ ẹja mi lo jẹ́ kí n jẹ Àmàlà mi ni àsán | ÀSÁN | EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT |
Ìgbà tí Bola jẹun tan ni o sun | Ìgbà | Time |
mo nífẹ̀ẹ́ sì ẹran ògúnfe ni jíjẹ | Ẹran | Meat |
ÀPÀ ọmọ kìí ni dúkìá tó ní láárí kan pàtó | Apà | Spoiler |
Mo nífẹ̀ẹ́ sí kíkọ́ èdè Ẹ̀GBÁ | Ẹ̀GBÁ | NAME OF A TRIBE IN YORÙBÁ KINGDOM |
Njẹ o ma wá sí ilé ikẹkọ ní ọ̀la | Ọ̀la | tomorrow |
Gágá ni ọnà há ni ẹnu ọnà abawole sile igbagbo náà | Gágá | Tightly |
Ẹ jẹ́ kí a bọ̀wọ̀ fún Ọ̀gá wa dáadáa | Ọ̀GÁ | MASTER |
Ẹní àrá bá pa kìí sun silẹ | Àrá | thunder |
Diẹ loku ki ọmọ jabọ́ lẹyìn ìyá ìkókó nígbà tí ọ̀já rẹ tu lojiji | Ọ̀já | Rapper to mount baby |
Ẹyẹ agbe mẹ́ta ni mo ṣe alabapade lọ́nà oko | AGBE | A TYPE OF BIRD |
Èdè ni o ma ń sọ ìran tí ènìyàn ti wá | Èdè | Language |
Wọn pe ẹranko tó ní ìwo ìgbín yọjú | Ìwo | Animal horn |
Àwọn Agbè-fún-ọba ní láti pàdé ni ìlú Ìbàdàn | PÀDÉ | TO COME TOGETHER |
Rí dájú pé o pe ògèdè sí oúnjẹ kí o jẹ́ | Ògèdè | incantation |
Àṣà radarada gbáà ni kí ènìyàn máa rin ní ìhòòhò | ÀṢÀ | CULTURE |
òkúta tí ọmọ náà jù ORÍ ni o ti bá ewúrẹ́ | ORÍ | null |
Gbé ìkòkò náà bá mi ní ọ̀dẹ̀ | Ọ̀DẸ̀ | PASSAGE |
Àgbò tí ìwo rè bá sẹ́ kò se pa iléyá | Ìwo | Animal horn |
Ọdẹ pa ikún jẹ ní oko | Ikún | A kind of Squirrel |
Owó ní àkàndùn ti mu ọmọ náà | Ọwọ́ | Hand |
Ẹṣin ọba ìlú ìgbẹ́kẹ̀lé kú ní àná | ẸSIN | HORSE |
Ẹyin meji ni Ade fi sori ounjẹ rẹ̀ | Ẹyin | Egg |
ỌSÁN ìlù náà já nígbà tí akọrin lòó | Ọsán | One of the rope used to tie talking drum |
Akinola n sáré gẹ́gẹ́ bíi ẹ́gbọ́n rè | Gẹ́gẹ́ | Exactly |
Ẹ̀tù, ọta ati ààyá ni o wà nínú ìbọn ọdẹ náà | Ààyá | null |
Ọ̀rọ̀ ẹnu Alarape kò dára tó | Ọ̀RỌ̀ | WORDS |
Bàbá mi lo kọmi bí a ṣe ń ṣe Ẹ̀TÙ | Ẹ̀TÙ | GUN POWDER |
won ti gbe igbá ọsẹ le ọmọ náà lórí ki àṣírí to tu | Igbá | Calabash |
Ọbẹ̀ ilá dara fún Ọkùnrin tí àtọ̀ rẹ sàn | Ilá | Okro |
Àdá ni ó fi pa ẹranko ẹhànnà náà | ÀDÁ | CUTLASS |
Ọjọ́ tí mo bá tún rí ọ pé o ṣe agbe, mo máa nà ọ́ | AGBE | BEGGING |
Àlàmú ni oríkì tí ìyà àgbà fún un mi | ÀLÀMÚ | A MALE NAME |
Gba ìparí yìí kí o máa fi ra Ekundayọ lórí | ÀWÙJẸ̀ | SOFT SPOT |
Kòsí ààyá kankan nínú ìbọn bàbá ọdẹ náà mọ́ | Ààyá | null |
Rí dájú pé o lọ sí ilé ìtọ̀ kí o tó sùn | Ìtọ̀ | Urine |
Gbogbo Igbìyànjú Awẹle láti di aya ni ọ̀dẹ̀ Àyànwande lo jásí asán | ASÁN | VAIN |
Ile ẹ̀kọ́ gbogbo nise ti ìlú ìré ni Ariyọ̀ ti kàwé | Ìré | A town in Osun State, Nigeria |
End of preview. Expand
in Data Studio
README.md exists but content is empty.
- Downloads last month
- 0