Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
audio
stringlengths
44
104
sentence
stringlengths
4
676
/kaggle/working/audio_data/ogabirin_chunk_3.wav
Mo gba àtẹ̀jíṣẹ́. Bàtà. Mo ní bàtà méjì. Mò ń wọ bàtà. Ra bàtà fún mi. Nu bàtà mi. Fèsì sí ìwé.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_45.wav
tí ó bẹ̀rù níwaju rẹ̀ bẹ́ẹni kì yóò dára fún ènìyàn búburú bẹ́ẹ̀ni kì yóò fa ọjọ rẹ̀ gùn bí òjìjí tí ó dàbi òjìjí, nítorí kò bẹ̀rù níwáju Ọlọ́run. Ohun míràn tún wà tí kò ní ìdùnnú tí ó ń ṣelẹ̀ láye olódodo tí ń ba àwọn tí ó kú lọ sí òṣìkà àti ẹni búburú tí ó ń gba ohun tí ó tọ́ sí olódodo, mo sọ wípé eléyìí gan kò ní ìdùnú, nítorí náà mo kan sára si ìgbádun ayé nítórí pé kò si ohun tí ó dára fún ènìyàn ní abẹ́ ọ̀run ju pé kí ó jẹ
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_9.wav
and then lórí ìyẹn, lórí website yen náà mo máa ń ta àwọn nǹkan àǹkárá, so àǹkárá ni like fashion stape àwọn Yorùbá. so mo ń ta àwọn nǹkan àǹkárá, mò ń ta ẹ̀ṣọ́ etí, mò ń ta àpò, àpò àǹkárá and then ẹ jẹ́ kí n fi nǹkan hàn yín mò ń bọ̀. So, láìpẹ́ yìí mo wá bẹ̀rẹ̀ sí ń rán àwọn àǹkárá print hairtie, so tẹ́ ẹ bá wo àwọn video kan tí mó ṣe màá link wọn above, ẹ ẹ́ ri pé mo máa ń wé bíi, mo ṣà ń wé aṣo sórí
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_0.wav
Kí lo fẹ́? Bèèrè. Mo bèère óunje. Bàjẹ́. Ọmọ yín yìí bàjẹ́
/kaggle/working/audio_data/muyiwa_chunk_1.wav
lo ti dágbà tóyìí lo wá ń sọ̀rọ̀ sí wa, ṣọ́ọ̀ mọ̀ wá mọ́ ni? Àwa tí a dáwó fún ọ láti lọ ilé ìwé. nígbà tí ẹ dáwó fún mí láti lọ sí school, so torípé ẹ dáwó fún mí láti lọ sí school ẹ ò lè mú ẹni ti ẹ sọ pé àjẹ́ ni lọ sí police station, abi kí ẹ gbé e lọ sí court. Ẹ gbẹ́nu sọ̀hún jàre sir, sir, sir, with respect ẹ má ever sọ fún mi pé kí n gbẹ́nu sọ̀hún, mò ń sọ fun yín ni pé kẹ́ẹ má sọ, haa o bàjẹ́, ogé ti ta lé ẹ, kò ní dáa fún ìyá rẹ, Ó dáa ti o ba le gbe ẹnu sọhun oya gbẹnu ẹ wá bí, ṣebí àgbàlagbà náà lẹ̀yin náà.
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_3.wav
Mi tó. Owó tó wà lọ́wọ́ wa, ó tó. O ní owó tó tó. Mo ní owó to tó. Ó tó gẹ́ẹ́.
/kaggle/working/audio_data/omo-isin_chunk_3.wav
bíi lọ́jọ́ ọ̀la akínrógun, ọmọ láróńpé àyọ̀ní tó jọ́mọ ti Balógun tó jẹ́ ọmọ ti, hà Àkànnì, ìyá mi, ọ̀rẹ́ yìí ti dààmú kú o, pẹ̀lẹ̀ la sì fi ń pàmúku pẹ̀lẹ́ o, ẹmi o gbọdọ̀ bọ́ lẹ́nu tí wọn ó fi lọ tí wọn ó e dé
/kaggle/working/audio_data/ojo-ose_chunk_4.wav
Mò ń lọ sí ayẹyẹ ìgbéyàwó nítorí mo fẹ́ràn láti jó. Kí lo ṣe ṣe lánàá? Àná ni ọjọ́ àìkú, mo lọ sí ilé ìjọsìn. Ó dára. Èní ṣì ni ọjọ́ ajé, iṣẹ́ bẹ̀rẹ̀, mi ò lè dúró kí ọjọ́ ẹ̀ti dé. Mo ní ayẹyẹ ìgbéyàwó lọ́jọ́ àbámẹ̀ta. Máse gbàgbé gbàgbé
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_5.wav
ẹ̀kọ́ nípa àkòrí, èyí túmọ̀ sí pé kí á kà nípa àwọn àkòrí tí ó wà ninú bíbélì bí àpẹẹrẹ ẹ̀mí-mímọ́, ìrìbọmi, ìrònúpìwàdà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, ọ̀rọ̀ pàtàkì kíka ọ̀rọ̀ ọlọ́run nípa ìmúlò ìlànà èyí jẹ èyí ò jẹ kò tọ́nà rárá nítorí kò lè mú ìdàgbàsó
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_9.wav
Fífi ebi pa ara ẹni
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_69.wav
Mission, on a mission to spread the love of God through giving to those in need and within our reach and through the creation of an edifying contents in audio written visual forms. We do have audio recordings of the entire books of the Bible in the voice of Bísọ́lá Wedlin. A ten track annual musical album available on all streaming platform, which started in 2023. Mini video series which you can follow up with on YouTube and our Instagram page encountering the word.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_24.wav
tí ń bẹ lábẹ́ ọ̀run pẹ̀lú ìpínyà ìkejì tí yòó gba ipò ọba yìí, gbogbo àwọn tí ó wà ní iwájú wọn kò sì lópin, ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn ni ó jẹ́ ọba lé lórí, ẹni tí ó wà ní ipò yìí kò dùn mọ́ àwọn tí ó tẹ̀lé wọn nínú, asán ni eléyìí pẹ̀lú jẹ́, ó dàbí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni, gbogbo àwọn tí ó wà ní iwájú wọn kò sì lópin, ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn ni ó jẹ́ ọba lé lórí, ẹni tí ó wà ní ipò yìí kò dùn mọ́ àwọn tí ó tẹ̀lé wọn nínú
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_2.wav
Tà n ṣe yìí àjọṣepọ̀ èmi àti ẹ tà ń kan ra wa ń Yorùbá tà ń learn, tà ń develop, ó tí ọ táa Ti ń ṣe bọ̀ ṣé wọ náà mọ̀, ọ mọ̀, ọ mọ̀,ọ mọ̀ now. A ti ń ṣe é láti 2017 ó tí tó ọdún mẹ́ta tí a ti ń ṣe kinní yìí. Ṣé ẹ̀yin náà ò máa pé ó yẹ kí ìtẹ̀síwájú wà n bẹ̀. Ṣé kò yẹ ká tẹ̀síwájú nínú ọ̀rọ̀ yìí? Ká take ẹ̀ to the next level. It's like à ń f'ara wa, ká ní pé èmi àti ẹ ń fẹ́ra wa nsìnín, ọdún kan lọ, ọdún méjì lọ, ọdún mẹ́ta lọ a à progress
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_4.wav
Mú èyíkéyìí tó bá wù ó nínú wọn, wọn kìí ṣe ìlù lásán, ìgbàkíìgbà tí ebí bá ti ń pa ọ́, lu ìlù náà. Lẹ́yìn àsìkò díẹ̀,iyàn mú, ebi ń pa àwọn ènìyàn ati.
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_4.wav
Ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí lẹ bèèrè fún-ùn. Rárá, mi ò fẹ́ ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí. E má bínú sir, màá gbé ọbẹ̀ tó tọ́ wá fún-un yín.
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_5.wav
Tí wàá lè take Yorùbá courses online okay, wà á lè lọ wàá fara balẹ̀ ní o, ni time e ni, kìí ṣe pé èmi màá ma sọ fún e pé aago yìí lo gbọdọ̀ pàdé mi, wàá lọ síbẹ fúnra è wàá ra course tóo fe àbí wàá subscribe sí course tóo fe, wàá dẹ̀ máa take ẹ̀, mo máa fún ẹ ni material. Gbogbo nkan bẹ́ yẹn ṣùgbọ́n ẹ̀yin náà bí mo ṣe n sọ̀rọ̀ ẹ gbọ́ pé okay eléyìí wà advance díẹ̀ ó gba àsìkò gan, kí n tó máa bẹ̀rẹ̀ máa kọ́kọ́ plani course tí mo máa kọ́ yẹn màá k
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_55.wav
Nígbà tí ọmọ aládé ń fi ẹsẹ̀ rìn bí ẹrú. Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ó le è ṣubú sínú rẹ̀; ẹnikẹ́ni tí ó bá la inú ògiri, ejò le è ṣán an. Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbe òkúta le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn, ẹnikẹ́ni tí ó bá la ìtì igi le è ní ìpalára láti ipasẹ̀ wọn. Bí àáké bá kú tí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ kò sì sí ní pípọ́n, yóò nílò agbára púpọ̀ ṣùgbọ́n ọgbọ́n orí ni yóò mú àṣeyọrí wá. Bí ejò bá ṣán ni kí a tó lo oògùn rẹ̀, kò sí èrè kankan fún olóògùn rẹ̀. Ọ̀rọ̀ tí ó wá láti
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_35.wav
lẹ́yìn tí ó bá ti lọ tán, kò sí, ìwé oníwàásù orí keèje, orúkọ rere sàn ju ìpara olóòórùn dídùn lọ, ọjọ́ ikú sì dára ju ọjọ́ tí a bí ènìyàn lọ, o dára látí lọ sí ilé ọ̀fọ̀ ju bi àṣè, nítorí pé ikú jẹ́ àyànmọ̀ gbogbo ènìyàn kí alàyè ní èyí ní ọkan, ìbànújẹ dára jù ẹ̀rín lọ, ó lè mú kí ojú rẹ dàrú, sùgbọ́n yóò jẹ́ kí àyà rẹ́ le, ọkàn ọlọ́gbọ́n wà ní ilé ọ̀fọ̀ sùgbọ́n ọkàn òmùgò ní ilé àríyá, ó dára láti gba ìbáwí ọlọ́gbọ́n
/kaggle/working/audio_data/omo-isin_chunk_1.wav
a fẹ́ kí lakáayé o fomí lẹ̀ Kó wá fẹ̀jẹ̀ lẹ̀ o, mò ń bèèré, wípé ta ló rán an yín wá? tẹ́ẹ fẹ Jokùn òrogùn tí ò mọ iṣẹ́ jẹ́, omí gbóná ha, o tún wá dìí títí, o wá di ìyá mi tó báyìí
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_8.wav
Esther 4:16, Esther 5:2-3. Fún ìrònúpìwàdà àti ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀. Jonah 3:1-5. Láti lè yan ọ̀nà tó tọ́ nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà. Luke 6:12-13
/kaggle/working/audio_data/200629-205402_yor_874_elicit_6.wav
nígbà tí ọmọdé kejì tí ó ní òún lè wẹ òkun ja gbọ́ ariwo ìdùnú yìí, eléyìí kìí láyà
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_41.wav
òmíràn, láti ṣàwarí ìdí ohun gbogbo, nígbà tí mo ṣì ń wá a kiri sùgbọ́n tí ǹ kò rí i, mo rí ọkùnrin tí ó dúró dáradára kan láàrin ẹgbẹ̀rún ṣùgbọ́n n kò rí Obìnrin kankan kí ó dúró láàárín gbogbo wọn, eléyìí nìkan ni mo ti rí , ọlọ́run ń dá ìran ènìyàn dáradára sùgbọ́n èniyàn ti lọ láti ṣàwarí ohun púpọ̀, ìwé oníwàásù orí kẹjọ tani ó dàbí ọlọ́gbọ́n ènìyàn tani ó mọ ìtúmọ̀ ohun gbogbo, ọgbọ́n á mú ojú ènìyàn dan, ó sì ma pàrọ̀ ìrínisí rẹ̀, pa òfin ọba mọ́
/kaggle/working/audio_data/ikute_chunk_4.wav
Aṣiṣẹ́ bí akúra. Págà! ìkùntè mí tí fọ́. Pẹ̀lẹ́ o, ló tèmi. Mí ò lè lo tiẹ, àwọ̀ ìkùntè rẹ kò ṣe déédéé létè mí. Mo ní òmíràn,ṣó o fẹ́ràn eléyìí, o seun, mo fẹ́ àwọ̀ eléyìí
/kaggle/working/audio_data/ogabirin_chunk_1.wav
Ka ìwé ìròyìn. Àgbàfọ̀. Ọkọ̀. Fọ ọkọ̀ mi. Ìwé àtẹ̀jíṣẹ́. Èsì. Ìyẹn Ìyẹn náà tó. Ṣé ó ti tán. Owó.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_62.wav
Yóò tẹríbà nígbà tí awọn tí ń lọ dákẹ́ nítorí pé wọn kò gbọ́ tí àwọn tí ń òde láti ojú fèrèsé yóò sókùnkùn, nígbà tí ilẹ̀kùn sí ìgboro yóò tì, tí ariwo ọlọ yóò dákẹ́ nígbà tí àwọn ènìyàn yóò dìde sí ariwo àwọn ẹyẹ ṣùgbọ́n gbogbo orin wọn yóò máa lọ ilẹ̀. Nígbà tí ènìyàn yóò bẹ̀rù ibi gíga àti ti ìfarapa ní ìgboro, nígbà tí igi álmọ́ńdì yóò tanná àti tí ẹlẹ́ǹgà yóò wọ́ ara rẹ̀ lọ tí ìfẹ́ kò sì ní ru sókè mọ́
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_6.wav
Jẹ́ n rèé bá a,ówù, ṣebí ọ̀rẹ́ ni wá. Òótọ́ níí oo. Jẹ́ kí á jẹun. Ní sùúrù náà,me bí o ní ìlù mẹ́ta ní bẹ lágbàlá ìya náà ,emi lówádé tí o wá gbé èyí tó kéré jù nínú àwọn ìlù náà. Ìtẹ́lọ́rùn làgbà, díè.
/kaggle/working/audio_data/omo-isin_chunk_4.wav
ọmọ ìyá mi, mo rí ọ ná ...(bell sound and music)
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_5.wav
Mo mọ̀ wípé salad ilé oúnjẹ yìí, ó dára gan-an. Kí lo túmọ̀ sí? Kí ló dé tí o fẹ́ kín n jẹ salad nìkan? O lè jẹ ohun tí o fẹ́ jẹ o, ṣùgbọ́n, salad ló ṣe ara lóore jù. Kí lò ń sọ? Kí lo fẹ́ sọ fún mi gangan.
/kaggle/working/audio_data/ikute_chunk_3.wav
èyí kò tọ̀, èyí ṣe àìtọ́, èmi tọ́, ìwọ́ ṣe àìtọ́, ìtọ́jú, mo ṣe ìtọ́jú, èmi kò ṣe ìtọ́jú, òún ṣe ìtọ́jú, gbájúmọ́ iṣẹ́ rẹ
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_1.wav
àwẹ̀ jẹ́ ìséraẹni láì jẹun tàbí mu omi ní pàtàkì jùlọ nípa ìlànà ẹ̀sìn, nígbàtí a bá ń gba àwẹ̀, ara máa ń wà ní ìrẹ̀sílẹ̀ àti ìséra nípa ìgbádùn kí á le fi àyè fún ẹ̀mí wa láti wà láìsí ìdènà pẹ̀lú ọlọ́run Galatians 5:17 àdúrà gbọdọ̀ wà ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwẹ̀.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_37.wav
kan èyí jẹ́ ohun tí ó dára, ó sì ṣe àwọn tí ó rẹ̀ wọn làǹfàní, ọgbọ́n jẹ́ àbò gẹ́gẹ́ bí owó ti jẹ́ àbò, ṣùgbọn àǹfàní òye ni èyí pé ọgbọn a máa tọ́ju ẹ̀mi ẹni tí ó bá níi, wo ohun tí Oluwa ti ṣe tani ó lè to ohun tí ó ti ṣe ní wíwọ́, nígbàtí àkókò bá dára, jẹ́ kí inu rẹ kí ó dùn, ṣùgbọ́n nígbà ti àkókò kò bá dára ròó, ro eléyìí, Ọlọ́run ti ó dá ìkíni ni ó dá èkejì nítorí náà, ènìyàn kò lè ṣàwárí ohun kankan
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_49.wav
ìyókù, ṣùgbọn òkú kò mọ ohun kan, wọn kò ni èrè kọkan mọ́ àti kódà ìránti wọn ti di ohun ìgbàgbé,ifẹ wọn, irira wọn àti irira wọ́n ti parí láí láí kọ́ ni wọn ó tún ní ìpín nínu ohunkóhun tó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run. Lọ jẹ óúnjẹ rẹ pẹ̀lú ayọ̀, kí o sì mu ọtí wáìni rẹ pẹ̀lu ìdùnu dé ọkàn nítorí pé ìsinsìyin ni Ọlọrun ṣíjú àànu wo ohun tò ń ṣe. Máa wọ aṣọ fúnfún nígbàkígbà kí ò si máa fi òróró yan ori rẹ nígbà gbogbo. Máa jẹ ayé pẹ̀lú ìyàwo rẹ.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_50.wav
Ẹni tí o fẹ́ràn ní gbogbo ọjọ́ ayé àìní ìtumọ̀ yí tí Ọlọ́run ti fi fún ọ lábẹ́ òòrùn, gbogbo ọjọ́ àìní ìtumọ̀ rẹ. Nítorí èyí ni ìpín tìrẹ ní ayé àti nínú iṣẹ́ wàhálà rẹ ní abẹ́ òòrùn. Ohunkóhun tí ọwọ́ rẹ bá rí láti ṣe, ṣe é pẹ̀lú gbogbo agbára rẹ, nítorí kò sí iṣẹ́ ṣíṣe tàbí ìpinnu, tàbí ìmọ̀ tàbí ọgbọ́n, nínú isà òkú níbi tí ò ń lọ. Mo ti rí ohun mìíràn lábẹ́ òòrùn, eré ìje kì í ṣe fún ẹni tí ó yára tàbí
/kaggle/working/audio_data/ikute_chunk_0.wav
(gángan lu "bàtà mi á dún koko kà"). tèmi, tìrẹ, tirẹ̀, tiwa, tiwọn.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_66.wav
Mission, on a mission to spread the love of God through giving to those in need and within our reach and through the creation of an edifying contents in audio written visual forms. We do have audio recordings of the entire books of the Bible in the voice of Bísọ́lá Wedlin. A ten track annual musical album available on all streaming platform, which started in 2023. Mini video series which you can follow up with on YouTube and our Instagram page encountering the word.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_61.wav
Kúrò ní ọkàn rẹ, kí o sì lèé ìbànújẹ́ ara rẹ kúrò. Nítorí tí èwe àti kekeré kò ní ìtumọ̀. Ìwe oníwaásù orí kejìlá, rántí Ẹlẹ́dàá rẹ ní ọjọ́ èwe rẹ, nígbà tí ọjọ́ ibi kò tí ì dé àti tí ọdún kò tí ì ní súnmọ́ etílé, nígbà tí ìwọ yóò wí pé, “Èmi kò ní ìdùnnú nínú wọn” Kí oòrùn àti ìmọ́lẹ̀ àti òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ tó ṣókùnkùn, àti kí àwọsánmọ̀ tó padà lẹ́yìn òjò; Nígbà tí olùṣọ́ ilé yóò wárìrì tí àwọn ọkùnrin alágbára yóò
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_3.wav
lósẹ̀ yìí a à make progress, ìwọ gan á bẹ̀rẹ̀ pé níbo ni kinni yìí nlọ where is this going let me know so, nǹkan tí mò ń ṣe ni pe, mo fẹ́ tẹ eléyìí sí wájú mo fẹ́ tẹ ètò yìí sí wájú, mo fẹ́ ká progress, ká get bigger. So, mò ń ṣiṣẹ́ lórí nǹkan tó jẹ́ pé èèyàn bí ìwọ àbí ọ̀rẹ́ ẹ àbí àwọn ọmọ ẹ, àbí àwọn ènìyàn tó jẹ́ pé wọ́n fẹ́ kọ́ Yòrùbá wọn á lè farabalẹ̀ nnkan tí máa ń ṣe Youtube video
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_26.wav
nígbà tí ìlépa púpọ̀ wà, bẹ́ẹ̀ni ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ nígbà tí ọ̀rọ̀ bá pọ̀jù nígbà tí o bá ṣe ìlérí sí ọlọ́run má ṣe pẹ́ ní mímúṣẹ, ọlọ́run ò ní inú dídùn sí òmùgọ̀, mú ìlérí rẹ ṣẹ, ó sàn láti má jẹ́ ẹ̀jẹ́ ju wí pé kí a jẹ́ ẹ̀jẹ́ kí á má mú un ṣẹ lọ, má ṣe jẹ́ kí ẹnu rẹ tì ọ́ sínú ẹ̀ṣẹ̀, má sì ṣe sọ fún òjíṣẹ ilé ìsìn pé àṣìṣe ni ẹ̀jẹ́ mi kí ló dé tí ọ
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_32.wav
ni ohunkóhun tí ọkàn rẹ̀ ń fẹ́, sùgbọ́n Ọlọ́run kò fún ní àláfíà láti gbádùn wọn dípò èyí, àlejò ni ń gbádùn wọn, asán ni èyí àrùn búburú gbáàà ni, ọkùnrin kan le ní ọgọ́rùn-ún ọmọ kí ó sì wà láyé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ odún síbẹ̀ kò sí ibi tí ó ti le wà láàyè pẹ́ tó, bí kò bá lè gbádùn ohun ìní rẹ̀ kí ó sì gbádùn ìsìnkún tí ó tọ́, ó sọ wí pé ọlẹ̀ ọmọ tí a sìn sán àn jù ú lọ, ó wá láì ní ìtumọ̀, ó lọ nínú òkùnkùn, nínú òkùn.
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_3.wav
Kí leléyìí? Ọbẹ̀ tí ẹ bèrè fún nìyíì. Rárá, ọbẹ̀, tí mo bèrè fún kọ́ nìyíì. Ọbẹ̀ ni mo bẹ̀rẹ̀ fún. Ṣùgbọ́n sir
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_68.wav
The heart and that it can run the word, we do too. Visit our websites, canto in the world dot org to get more insight about the work that we do or follow our Instagram and YouTube page at canton in the world.
/kaggle/working/audio_data/ogabirin_chunk_0.wav
Káàárọ̀, káàsán, káalẹ́. Oúnjẹ. Mo nílò. Ìwé ìròyìn.
/kaggle/working/audio_data/ojo-ose_chunk_5.wav
Ọ̀rọ̀ sísọ wa ní àkójọ wa níjọ́ ọjọ́bọ̀. Ọjọ́bọ̀? Èmi rò bóyá ọjọ́rú ni. Mo ní láti lọ gba aṣọ tí n máa wọ̀ lọ́jọ́ àbámẹ̀ta, lọ́jọ́bọ̀. Arábìnrin, èwo ló ṣe pàtàkì sí ọ? Iṣẹ́ rẹ tàbí òde ówàńbẹ̀? Méjèèjì ni. Iṣẹ́ Iṣẹ́ mi ló ń sanwó òde mi.
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_6.wav
Arínifín lọmọ yín yìí. Áh áh, mi ò fẹ́ gbọ́ bẹ́ẹ̀ mọ́. Fún-un ní ohun tí ó bá fẹ́. Ó da. Ǹjẹ́ ó tún lóhun kóhun tí ẹ tún fẹ́ béèrè. Bẹ́ẹ̀ni, ẹ fún mi ní ọbẹ̀ àpọ̀n àti gúgúrú.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_72.wav
Nil
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_40.wav
ó sì jinlẹ̀ tani ó lè ṣe àwárí rẹ̀? mo wa ọ̀run nínu ọkàn mi láti mọ̀, láti wá, àti láti ṣàwárí ọgbọ́n àti ìdi ohun gbogbo àti láti mọ ìwà àgọ́ àti ti ìsínwí tàbí òmùgọ̀. mo rí ohun tí ó korò ju ẹkun lọ, obìnrin tí ó jẹ́ ẹ̀bìtì tí ọkàn rẹ̀ jẹ́ tàkúté tí ọwọ rẹ̀ sí jẹ́ ẹ̀wọ̀n, ọkùnrin tí ó ba tẹ́ Ọlọ́run lọ́rùn yóò yẹ̀ẹ́ ṣùgbọ́n ẹní dẹ́ṣẹ̀ kò lè bọ́ nínu tàkúte rẹ̀. Oníwàásù wípé wòó eléyìí ni mo ti ṣàwárí nínu ohun kan pẹ̀lú
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_3.wav
má ṣe gbàwẹ̀ nítorí kí àwọn ènìyàn lè rò pé o já fáfá nínú ẹ̀mí Acts 23:12-13 Matthew 5:44-45, Romans 12: 14. bí o bá fẹ́ fi ètò sí oúnjẹ jíjẹ kí o má bá sanra má ṣe sọ fún ènìyàn pé ò ń gbàwẹ̀
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_46.wav
́kóhùn kí inú rẹ̀ sì dùn lọ, nígbà náà ni ìdùnu ýò ba rìn nínu iṣẹ́ rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé tí Ọlọ́run ti fi fún un lábẹ ọ̀run. Nígbàtí mo lo ọkàn mi láti mọ ọgbọ́n àti láti wo láàláà ènìyàn ní ayé, nígbà náà ni mo rí gbogbo ohun tí Ọlọ́run ti ṣe, kò sí ènìyàn tó lè mọ ohun ti ó ń lọ lábẹ́ ọ̀run láì bìkìtà gbogbo ìyànju rẹ̀ láti wáa rí jáde. Ènìyaǹ kò lè mọ ìtunmọ rẹ̀ kódà, bí ọlọ́gbọn ènìyán rò wípé òún mọ̀ọ́, kò lè ní òy rẹ̀, ní pàto. Ìwe oníwà
/kaggle/working/audio_data/baddie_laylay_chunk_0.wav
Gbogbo ẹ̀yin olólùfẹ́ Baddie of Le'lẹ, gbogbo ẹ̀yin tó ti wo apá kìnní movie Yorùbá movie tó ń trend lọ́wọ́ lọ́wọ́ tí everybody ń ṣe nípa yìí tó fẹ wọ apá Kejì. Ẹjọ̀ọ́ ẹ bá wa tẹ subscribe button, a á máa sọ fún yín níbìkan ní bí video ìgbà tí apá Kejì máa jáde. Kí lẹ gbádùn jùlọ nípa movie yìí? Ẹ jẹ́ ká máa ní comment section. Apá kìíní movie náà pàyàn lẹ̀rin gidigan, ṣùgbọ́n ta lẹ nìfẹ́ sí jùlọ ninu movie yìí? èmi nìfẹ́ Lọlá Ìdíjẹẹ́ àbí
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_31.wav
àti ohun ìní, yóò sì fún un ní agbára láti gbádùn wọn, láti gba ìpín rẹ̀, kí inú rẹ̀ sì dùn sí iṣẹ́ rẹ̀, ẹ̀bun ọlọ́run ní èyí, ó máa ń ronú lẹ́kọ̀ọ̀kan nípa ọjọ́ ayé rẹ lẹ́kọ̀ọ̀kan pẹ̀lú inú dídùn, ní ọkàn rẹ̀, nítorí pé ọlọ́run ń pa á mọ́ pẹ̀lú inú dídùn ní ọkàn rẹ̀, oníwàásù orí kẹfà, mo ti rí ibi mìíràn lábẹ́ ọ̀run, ọlọ́run fún ọkùnrin kan ní ọrọ̀,ọlá àti ọlà kí ó má bà á ṣe aláì
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_15.wav
Ìgbà láti ya àti ìgbà láti mú. Ìgbà láti dákẹ́ àti ìgbà láti sọ̀rọ̀. Ìgbà láti ní ìfẹ́ àti ìgbà láti kórìíra. Ìgbà fún ogun àti ìgbà fún àlàáfíà. Kíni òṣìṣẹ́ jẹ ní èrè nínú wàhálà rẹ̀ nítorí àjàgà tí ọlọ́run gbé lé ọmọ ènìyàn. O tí ṣe ohun gbogbo dáradára ní àsìkò tirẹ̀ ó sì tí fí èrò nípa ayérayé sí ọkàn ọmọ ènìyàn síbẹ̀ wọn kò lè ṣe àwárí ìdi ohun tí ọlọ́run ti ṣe láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin. Mo wá wípé
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_4.wav
Ó máa ń fast bákan mí ò kí ń f'ara balè kọ yín, mí ò kí ń pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ kọ yín. Sọ nígbà tí mi ò lásìkò láti f'ara balẹ̀ kan yín yẹn ìgbàmíì o máa ń get lost in transmission sọ nǹkan tí mo fẹ́ kọ́ọ yín ẹ ò ní kọ bẹ́ ẹ ṣe fẹ́ kọ, ẹ ò ní kọ délẹ̀délẹ̀. Ẹ ò ní become fluent. Kò ní jẹ́ bí èdè yín gangan. Torí bẹ̀ mo wá ń ṣiṣẹ́ lórí website tó jẹ́ pé website yìí Is going to be the first tó jẹ́ pé tẹ́nì kankan bá lọ ṣe kí n tó gbé tèmi jáde kẹ mọ̀ pé wọn copy mí ni. It is going to be the first one.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_1.wav
Ó sì sáré padà sí ibi tí ó ti yọ. Afẹ́fẹ́ ń fẹ́ lọ sí ìhà gúúsù, ó sì ń fẹ sí ìhà àríwá, á sì tún padà sí ọ̀nà rẹ̀. Gbogbo odò ń ṣàn sínú òkun síbẹ̀síbẹ̀ òkun kò kún.Níbi tí àwọn odò ti wá, níbẹ̀ ni wọ́n tún padà sí. Ohun gbogbo ní ń mú àárẹ̀ wá, ju èyí tí ẹnu lè sọ. Ojú kò tí ì rí ìrírí tí ó tẹ́ ẹ lọ́rùn, bẹ́ẹ̀ sì ni etí kò ì tí ì kún fún gbígbọ́. Ohun tí ó ti wà tẹ́lẹ̀
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_10.wav
Ànkárá print, mo mọ̀ pé àwọn míì ni pe àwọn like ẹ̀, mo dẹ̀ ni sewing machine ńlé so mo wá bẹ̀rẹ̀ sí ni rán àwọn àǹkárá print headties so inú mi kàn dùn torí pé mò ń ṣe àwọn nǹkan tí ọkàn mi nìfẹ́ sí, so nǹkan tí mo ti ń ṣe láti'jọ́ yìí nìyẹn. Nípa nńkan tí mo fẹ́ ṣe mi ò really fẹ́ sọ gbogbo àwọn èrò ọkàn mi fun yin torí mi ò fẹ́ kí ẹnì kankan lọ da ṣugar sí gaàrí mi àbí kan lọ da gàrí sínu sugar mi mi ò really feel ẹ̀ ṣùgbọ́n mo mọ̀ n pé ọkàn mi ṣì wà ni Nigeria, mo ṣì fẹ́ padà lọ sí Nigeria
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_0.wav
Ìwé oníwàásù, orí Kínní, asán ni ohun ayé. Ọ̀rọ̀ oníwàásù, ọmọ Dáfídì, ọba Jerúsálẹ́mù, asán nínú asán, oníwàásù náà wípé, asán nínú asán, gbogbo rẹ̀ asán ni. Kí ni ènìyàn rí jẹ ní èrè lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀, lórí èyí tí ó ń ṣe wàhálà sí lábẹ́ ọ̀run. Bí ìran kan bá ti wá ni ìran mìíràn ń kọjá lọ. Síbẹ̀, ayé dúró títí láé. Òòrùn ń ràn, oòrùn sì tún ń wọ̀.
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_8.wav
Oúnjẹ wa lónìí.Sugbon, ẹ̀ẹ̀kan péré yìí náà ni o. Olùwóúnjẹ, fún wa ní ọbẹ̀ ilá méjì pẹ̀lú iyán.
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_1.wav
Ẹ ẹ̀ lẹ̀ bínú sími,mo máa sọ fún un yín nínú video yìí ǹǹkan tó ṣẹlẹ̀. So nínú ètò yìí mo máa sọ̀rọ̀ jẹ́jẹ́ mi ò ní sáré sọ̀rọ̀ torí mo mọ̀ pé ẹ fi gbọ́ ǹǹkan tí mo fẹ́ sọ,ẹ dẹ̀ fi ń kọ́ ède Yorùbá torí bẹ́ẹ̀ máà máa rọra sọ̀rọ̀ sùgbọ́n tọ́rọ̀ mi bá bẹ̀rẹ̀ sí ní yá,ẹ má bínú,I take God beg you, no vex, so, kí ni mo ti ǹ ṣe látí ijọ́ yìí?,kí lódé tí mo fi fi yín sílẹ̀? tí mo fi fi yín sílẹ̀, tí mo fi sá lọ, ẹ wòó ẹ ní bínú ni, ẹbmọ̀ pé ètò Yorùbá yìí, ǹǹkan tá.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_65.wav
Ìwé kíkà púpọ̀ a máa mú ara ṣàárẹ̀. Nísìsiyìí, òpin gbogbo ọ̀rọ̀ tí à ń gbọ́ ni pé bẹ̀rù Ọlọ́run kí o sì pa ọ̀rọ rẹ̀ mọ́ nítorí èyí ni ojúṣe gbogbo èniyàn , èyí ni ojúṣe gbogbo èniyàn nítorí Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́ olúkúlùkù, iṣẹ́ àti ohun ìkọ̀kọ̀, kì báà ṣe rere, ki báà ṣe búburú
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_16.wav
Báwo ni ẹ ṣe ń find Corona period period yìí? Kí làwọn plans yín for the next couple of months, for the next year, both of them? Thank you so much for watching,ẹ ṣé gan-an tí ẹ wo ètò mi. Ẹ má gbàgbé láti like, comment, subscribe, share and tẹ bá fẹ́ kín n máa ṣe irú àwọn video yìí tí màá kàn máa sọ Yorùbá like ongoing, free-spirited, no break, ẹ comment down below àwọn topics wo lẹ fẹ́ kín n máa sọ ní Yorùbá, torí mi ò kàn lè máa come up with topics,mi ò mọ nǹkan tí ẹ fẹ́ gbọ́. So, ẹ̀yin lẹ máa sọ fún mi, kí ni mo ẹ fẹ̀ gbọ́? Kí ni ẹ fẹ́ kí n sọ̀rọ̀ lé lórí?
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_14.wav
yẹ kẹ máa wò wọ́n so èmi náà rò pé bóyá it's time láti diversify, ká wo àwọn other things, so tẹ bá mọ̀ pé okay ẹni idea fún iru videos tẹ́ẹ fẹ́ rí lọ́dọ̀ mi, irú àwọn videos tẹ́ fẹ́ kí n máa ṣe ẹ jẹ́ kí n mọ̀, ẹ sọ fun mi ní sàlẹ̀ màá kàn láti you know work ẹ in. Mo ti fẹ́ẹ̀ parí website yẹn torí bẹ́ẹ̀ màá lé ní more free time láti create videos fun yin ṣùgbọ́n ẹ sọ f'ún mi, kí lẹ fẹ́ rí gangan, ẹ̀ ń ọ pé Yorùbá lessons ẹ ẹ̀ dẹ̀ kí ń wò wọ́n, sọ kín ni ẹ fẹ́ rí gangan
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_0.wav
ẹ̀kọ́ Kejì, àkókò ìparọ́rọ́, ẹsẹ ọ̀rọ̀ ìyè, ẹ dúró nínú ẹ̀rù, ẹ má sì sẹ sẹ̀, ẹ bá ọkàn yín sọ̀rọ̀ lórí ẹní yín, kí ẹ sì dúró jẹ́, Psalm 4 verse 4, ọ̀rọ̀ àkọ́kọ́, àkókò ìparọ́rọ́ tàbí ìdákẹ́jẹ́
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_12.wav
ní sìn yìí torí pé màá ní my own set up, màá lè lọ sọ́jà màá bá yin r'ońjẹ, màá s'ońjẹ fún un yin. Mo lè take yin around Nigeria. Things to do in Lagos, taking you around the site,what the street food look like, gbogbo irú content tẹ bá fẹ́ màá lè máa vlog. Mo lè máa fún yin ní quality content, nǹkan tí mo fẹ́ lọ ṣe nbẹ̀ kọ́ nìyẹn o ṣùgbọ́n tí n bá wà níbè kí n kúkú fun yin ní nǹkan tí ẹ́yin náà fẹ́ . so mo ṣà n ronú bí mo ṣe máa diversify content mi tori bí mo ṣe sọ fún yin mi ò fẹ́ máa kan film video ti mi ò really nìfẹ́ sí, tí ọkàn mi ò
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_0.wav
Ẹ káàárọ̀, ẹ káàsán àti e káalẹ́ sí orí ètò mí ní gbogbo ibi tí ẹ bá wà. Ẹ káàbọ̀ sórí ètò Blessing Káyọ̀dé. Emi ni Blessing Káyọ̀dé,, báwo ni, báwo ilé, báwo ni iṣẹ́? Ṣé gbogbo ẹ̀ nlọ dáadáa. Mo máa ẹ̀ wò mí pé Ìbùkún pé Blessing níbo ló ti wà láti eeji yìí ọ kàn fiwálẹ̀ ọ kàn já, óò sọ̀rọ̀, o ò sọ fún wa nnkan tó ń ṣẹlẹ̀. Ẹ má bínú ṣẹ́ ẹ gbọ́ ẹwòó ẹ má bínú. Ẹ ò ní bínú
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_19.wav
Mo wá ri wípé kò sí ohun tó sàn fún ènìyàn ju kí ó gbádùn iṣẹ́ rẹ̀ nítorípé ìpín in ti rẹ̀ ni èyí. Tàbí tani ó leè mú kí ó rí ohun tí yó ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀? Kòsí. Oníwàásù orí kẹrin. Ìninilára, làáàlá àti aìlọrẹ̀. Mo sì tún wò ó, mo sì rí gbogbo ìninilára tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run mo rí ẹkún àwọn tí ará ń ni wọn kò sì ní olùtùnú kankan. Agbára wà ní ìkáwọ́ àwọn tí ó ń niwọ́n lára, wọn kò sì ní
/kaggle/working/audio_data/ojo-ose_chunk_1.wav
Ní ọjọ́ ajé, mo lọ sí ibi ìṣẹ́. Ní ọjọ́ ẹ̀ti, mo lọ sí ọjà. Ní ọjọ́bọ̀, mo lọ sí òde ìgbéyàwó. Ní ọjọ́ àìkú, mo lọ sí ilé ìjọsìn. Àná, oní, ọ̀la.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_25.wav
oníwàásù orí kaàrún, dídúró ní ìbẹ̀rù ọlọ́run, ṣọ́ ìrìn rẹ̀ nígbà tí o bá lọ sí ilé ọlọ́run kí ìwọ kí o sì múra láti gbọ́ ju àti ṣe irúbọ aṣiwèrè tí kò mọ̀ wí pé òun ṣe búburú, má ṣe yára pẹ̀lú ẹnu rẹ, má sọ ohunkóhun níwájú ọlọ́run, ọlọ́run ń bẹ ní ọ̀run ìwọ sí wà ní ayé, nítorí náà, jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ̀ mọ ní iwọ̀n, gẹ́gẹ́ bí àlá ti ń wá
/kaggle/working/audio_data/data_records_test_200625-215447_yor_874_elicit_12.wav
òwe yorùbá ní kí àgbàdo tó dé ilé ayé, adìyẹ ń jẹ, adìyẹ ń mu.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_29.wav
ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀ kìí jẹ́ kí wọ́n sùn rárá, mo ti rí ohun tí ó burú gidigidi lábẹ́ ọ̀run, ọrọ̀ tí a kó pamọ́ fún ìparun ẹni tí ó ní ǹkan tàbí ọrọ̀ tí ó sọnù nípa àìrí ojúrere tó jẹ́ wí pé bí ó bá bí ọmọ ọkùnrin, kò sí ohun tí yòó fi sílẹ̀ fún un, ìhòòhò ní ènìyàn wá láti inú ìyá rẹ̀, bí ó ṣe ṣe wà bẹ́ẹ̀ni yóò kúrò, kò sí ohunkóhun nínú iṣẹ́ rẹ̀ tí ó lè mú ní ọwọ́ rẹ̀, ohun búburú gbáàà ni eléyìí pàápàá, bí ènìyàn ṣe
/kaggle/working/audio_data/muyiwa_chunk_2.wav
ṣé ìwọ́ rí àjẹ́ ri ní police station rí ni, káwá mú àjẹ́ lọ sí police station, wọ́n ma ń sọ òkò pa àjẹ́ ni. Ma, ẹ listen ẹni tó bá pàyàn wọ́n ma ń paá ni, tí ẹ bá continue láti ṣe ǹkan tí ẹ̀ ń ṣẹ yìí, mo máa ṣe ǹkan tó máa jọ yín lójú, wọ́n máa ran yín lẹ́wọ̀n. Irọ́ lo pa, àwọn wo lẹ fẹ́ rán lẹ́wọ̀n? àwọn ọmọ yìí dà, ẹ wọṣọ ẹ múu, ẹ lẹ̀ẹ́ lókùta. Bàba alákùkọ, ẹ má fọ̀ọ́ fún un, ẹ gbàgbé lóri ǹkan tí ó ń sọ, ẹ jẹ́ kí ó múu ýin lọ sí police station ná, ìgbà náà lẹ ò mọ̀ pé ẹ léèyàn. Bẹ́ẹ̀ni, bẹ́ẹ̀ni, ẹ lọ police station, ẹ mú ǹkan re, ẹ jẹ́ kí wọ́n sọ̀kò lùú,ó yá ó yá ó yá. Ẹ continue
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_0.wav
Kí lo fẹ́? Kíni mo fẹ́? Kíni gbogbo wá fẹ́? Ronú. Mò ń ronú.
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_0.wav
Ìtàn òyín adùn oo,èro yáá,ẹ báwa ká lọ,èro yáá,bóṣọgbọ́n lo bá fẹ́ kọ́, ó yá, tẹ̀lé wa ká lọ, ó yá,ìmọ̀ lo bá fẹ́ ,òye,ó yá, tẹ̀lé wa ká lọ. The word "òyín" was pronounced as òyín.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_36.wav
ju fífetí sílẹ̀ sí orin òmùgọ lọ, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀gún tí ń dún lábẹ́ ìkòkò ni ìwé òmùgọ̀ asán sì ni eléyìí pẹ̀lú, ìrẹ́jẹ a máa sọ ọlọgbọn di òmùgọ̀, àbẹ̀tẹ̀lẹ̀ sì ma ń ba ìwà jẹ́, òpin ọ̀rọ̀ dára ju ìbẹ̀rẹ rẹ̀ lọ sùúrù sì dára ju ìgberaga lọ, má ṣe yára bínú ní ọkàn rẹ nítorí pé orí ẹṣẹ̀ òmùgọ̀ ni ìbínú ń gbé, má sọ wípé kíni ìdí tí àtijọ fi dára ju èyí nítorí pé kò mú ọgbọn wá láti bèère irú ìbéèrè bẹ́ẹ̀, ọgbọ́n gẹ́gẹ́ bii
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_3.wav
Ní Jerúsálẹ́mù rí. Mo fi àsìkò mi sílẹ̀ láti kọ́ àti láti ṣàwárí pẹ̀lú ọgbọ́n gbogbo ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run. Haaa, ẹrù wíwo tí Ọlọ́run ti gbélé àwọn ènìyàn mi. Èmi ti rí gbogbo ohun tí ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run gbogbo rẹ̀ kò ní ìtumọ̀. Pé ènìyàn gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni. Ohun tí ó ti wọ́, kò lè ṣeé tọ́ mọ́, ohun tí ò sí, kò lè ṣeé kà. Mo ronú nínú ara mi, wòó mo ti dàgbà.
/kaggle/working/audio_data/omo-isin_chunk_0.wav
ará oko ni ọ́, tí o gbémi láwọ̀ wọ̀ bí ọ̀gà, ìyá mi Àṣàbí, abiyamọ ọlọ́jàá mẹ́ta, ọjà àkọ́kọ́ lẹ fi sọlé rú, èkejì lẹ fi pọn àwọn ọmọ yín lápọ̀nyè, ọ̀já kẹta lọ̀já funfun lẹ fi ṣe ṣàkì tí ẹ fi kọ́rùn, tẹ fi dúró bi agọni lẹ́yin ọmọ yín gbọin-gbọin, Àṣàbí abánijà má fọwọ́ kan ẹni.
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_7.wav
Díè náà tó nínú ìkan oni ǹkan. Ìtẹ́lọ́rùn kóò,Ìtẹ́lẹ́sẹ̀ niì. Ẹ gbọ́ ná, ọ̀nà ọ̀jẹ́là ré o, tí owóò mi bá fi tẹ ìlú ńlá yìí ẹnu kí n yáa ṣí ilé óúnjẹ ńlá ní o, kí n ṣí ilé óúnjẹ ńlá sínú ìlu wa, kí n wá bẹ̀rẹ̀ sí ta óúnjẹ fún àwọn èèyàn, láìpẹ́ owó ádé tabua, ń kọ̀ ilé ńlá, ń sì fẹ́ obìnrin tó rẹwà
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_5.wav
Mo rò nínú ọkàn mi, wá nísinsìnyí, èmi yóò sì dán ọ wò pẹ̀lú ìgbádùn ìgbádùn láti ṣàwárí ohun tí ó dára, ṣùgbọ́n, eléyìí náà já sí asán. Mo wí fún ẹ̀rí pé òmùgọ̀ ni àti fún irẹ ayọ̀ pé kí ni ó ń ṣe. Mo tiraka láti dun ara mi nínú pẹ̀lú ọtí wáìnì àti láti fi ọwọ́ lé òmùgọ̀. Ọkàn mi sì ń tọ́ mi pẹ̀lú ọgbọ́n. Mo fẹ́ wo ohun tí ó yẹ fún ènìyàn ní ṣíṣe fún ènìyàn ní ìwọ̀nba ọjọ́ ayé rẹ̀.
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_11.wav
Irú eléyìí tí ìjàpá kó ara rẹ̀ sí látara àìníìtẹ́lọ́rùn. Ẹ̀yin ọmọdé,ẹ fi ìtàn yíì, ẹ ṣe ẹ̀kọ́,kí é sì mu lò. Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́,eeee Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́.
/kaggle/working/audio_data/baddie_laylay_chunk_2.wav
ò tá fojú bà, ẹ lọ sórí Yorùbá, Yorùbá Yorùbá, àwọn Àpáta TV ibẹ̀ lẹ ti máa rí apá kìíní wò, ẹ máa sọ pé mí ò sọ fún yín o. Ẹ má gbàgbé kẹ́ ẹ dẹ̀ tẹ subscribe button kí ẹ le mọ ìgbà àti àkókò tí a máa gbé apá Kejì jáde. Èèyàn tó bá tẹ subscribe button lá mọ̀gbà náà o. Ẹ má sọ pé mi ò sọ fún yín o, ó dìgbà.
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_2.wav
Ayò gbogbo wa ni. Owó. Iye-owó. Èdè-àyedè. Èdè-àyedè lèyí. Tó. Ó ti tó. Owó tí mo ní tó. Owó tó wà lọ́wọ́.
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_15.wav
jẹ́ kí n mọ̀, Sùgbọ́n àwọn nńkan tó ń ṣẹlẹ̀ pẹ̀lú èmi nìyẹn, nǹkan tí mò ń rí ńpa nìyẹn mo fẹ́ lọ sí Nigeria. Mò ń kọ ìwé Yorùbá náà, mò ń kọ novel, kí lẹ̀yín wà up to? Ẹ sọ fún mi, ẹ sọ fún mi ẹ jẹ́ ká sọ̀rọ̀ nínú comment section ká jọ sọ̀rọ̀, ẹ jẹ́ kí n tiẹ̀ mọ̀ díẹ̀ nípa yín ná, ẹ kàn ń wò mí ẹ̀ ń gba information nípa ayé mi tí mi ò dẹ̀ mọ̀ ǹkan tó ń ṣelẹ̀ pèlú èyin. So kí lẹ̀ ń ṣe? Kí lẹ wà up to? Kí ló ń ṣẹlẹ̀ nínú ayée yín? Sé ẹ̀yin náà fẹ́ travel? Báwo ni kòrókòró ṣe n affect yín? Mo lérò pé gbogbo yín ẹ wà dáada
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_1.wav
Ìwọ ń ṣe ronú. Gbogbo wa ń ronú. Iṣẹ́. Owó-iṣẹ́. Owó iṣẹ́ mi ni. Owó iṣẹ́ gbogbo wa ni. Ayò. Ayò mi, ayò ẹ.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_6.wav
Mo ṣe àwọn iṣẹ́ ńláńlá, mo sì kọ́ ilé púpọ̀ ni fún ara mi. Mo sì gbin ọgbà àjàrà púpọ̀. Mo ṣe ọgbà àti àgbàlá, mo sì gbin onírúurú igi eléso sí ẹnu ọ̀nà. Mo gbẹ́ adágún láti máa bomi rin àwọn igi tí wọ́n wú jáde nínú ọgbà. Mo ra àwọn ẹrú ọkùnrin àti ẹrú obìnrin, mo sì tún ní àwọn ẹrú mìíràn tí a bí sí ilé mi. Mo sì tún ní ẹran ọ̀sìn ju ẹnikẹ́ni ní Jerúsálẹ́mù lọ. Mo kó Fàdákà
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_57.wav
Lẹ, èyí tí ọba rẹ èyí tí ọba rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọlọ́lá, àti tí àwọn ọmọ-aládé ń jẹun ní àsìkò tí ó yẹ, fún ìlera, tí kì í ṣe fún ìmutípara. Bí ènìyàn bá ń lọ́ra, àjà ilé a máa jì bí ọwọ́ rẹ̀ bá ń ṣe ọ̀lẹ, ilé a máa jó. Ẹ̀rín rínrín ni a ṣe àsè fún, wáìnì á ti mú ayé dùn, ṣùgbọ́n owó ni ìdáhùn sí ohun gbogbo. Ma ṣe bú ọba, kódà nínú èrò rẹ, tàbí kí o ṣépè fún ọlọ́rọ̀ ní ibi ibùsùn rẹ, nítorí pé ẹyẹ ojú ọ̀run le è gbé
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_20.wav
Ní olùtùnú kankan. Mo jowú àwọn tí wọ́n sì ti lọ. Ó sàn fún wọn ju àwọn tí wọ́n sì wà láàyè lọ. Ní tòótọ́, ẹni tí kò tíì sí sàn ju àwọn méjèèjì lọ. Ẹni tí kò ti rí iṣẹ́ búburú tó ń lọ ní abẹ́ ọ̀run. Mo sì tún mọ̀ pẹ̀lú ìdí tí ènìyàn fi ń ṣiṣẹ́ tagbára tagbára láti ṣe àṣeyọrí nítorípé wọ́n ń jowú àwọn aládùúgbò wọn ni. Ṣùgbọ́n, asán ni. Ó dà bí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́. Asiwèrè
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_28.wav
pín èrè tí wọ́n bá lórí ilẹ̀ àní ọba pàápàá ń jẹ èrè lórí oko, ẹni tí ó bá ní ìfẹ́ owó kìí ní owó ànító, ẹni tí ó bá ní ìfẹ́ sí ọrọ̀ kìí ní ìtẹ́lọ́rùn pẹ̀lú èrè tí ń wọlé fún un, bí ẹrù bá ti ń pọ̀ síi bẹ́ẹ̀ni àwọn tí ń jẹ ẹ́ yóò máa pọ̀ síi, èrè kíni wọ́n sì jẹ́ sí ẹni tí ó ní ǹkan bikòṣe pé kí ó máa mú inú ara rẹ̀ dùn nípa rírí wọn, orun alágbàṣe a máa dùn yálà ó jẹ kékeré ní tàbí ó jẹun púpọ̀, sùgbọ́n
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_1.wav
Óunjẹ. Óunjẹ ma ń wù mí jẹ. Béèrè. Ó ń bèrè ohun lọ́wọ́ mi. Gààrí. Mo fẹ́ràn láti máa mu gààrí. Óunjẹ. Mo fẹ́ràn láti máa jẹ óunjẹ nígbàkugbà. Mo má ń bèèrè óunjẹ tí n bá fẹ́ nígbàkugbà
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_17.wav
yin màá dẹ̀ bayín sọ̀rọ̀ le lórí. so ẹṣẹ́ gan o, ó dàbọ̀ o màá rí i yín nígbààmíì
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_30.wav
wá niyì ó lọ, kí wá ni èrè tí ó jẹ nígbà tí ó ṣe wàhálà fún afẹ́fẹ́, ó ń jẹ́ nínú òkùnkùn ní gbogbo ọjọ́ rẹ̀ pẹ̀lú iyè ríra tí ó ga, ìnira àti ìbínú, nígbà náà ni mo wá ríi dájú pé ó dára o sì tọ́nà fún ènìyàn láti jẹ, kí ó mu, kí ó sì ní ìtẹ́lọ́rùn nínú iṣẹ́ wàhálà rẹ̀ lábẹ́ ọ̀run, ní àkókò ọjọ́ ayé díẹ̀ tí Ọlọ́run ti fi fi fún un, nítorí ìpín rẹ̀ nìyìí, síwájú síi, nígbà tí Ọlọ́run fún ẹnikẹ́ni ní ọrọ̀
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_38.wav
nípa ọjọ́ iwájù rẹ̀ nínu ayé àìnítunmọ̀ yìí ni mo ti rí gbogbo ìyẹn ènìyàn olótítọ́, ọkurin olódodo ń parun nínu òtitọ rẹ̀, ìkà ènìyàn sì ń gbé ìgbe ayé pípẹ́ nínu ìka rẹ̀, ma ṣe jẹ́ olódodo jùlọ tàbí ọlọ́gbọn jùlọ kílódé tí o fi fẹ pa ara rẹ run, ìwọ má ṣe ṣe búbúru jùlọ kí ìwọ má sì ṣe aṣiwèrè, èéṣe tí ìwọ yóò fi kú kí ọjọ rẹ́ tó pé, ó dára láti mú ọ̀kan kí o ma sì ṣe fi èkejì sílẹ̀, ọkùrin tí ó bẹ̀ru Ọlọ́run yóò bọ lọ́wọ gbogbo àrekérekè, ọgbọn ma ń mú ki
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_8.wav
Òkìkí, jáwọ́ nínú ìranù. Lónìí, gàrí lo ma mu.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_56.wav
ẹnu ọlọ́gbọ́n á máa ni ore-ọ̀fẹ́, ṣùgbọ́n ète òmùgọ̀ fúnra rẹ̀ ni yóò parun. Ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ rẹ̀ jẹ́ òmùgọ̀, ìparí rẹ si jẹ ìsinmi búburú, wèrè á sì máa ṣàfikún ọ̀rọ̀. Kò sí ẹni ti ó mọ ohun tí ó ń bọ̀, tani o lè sọ fún un ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ lẹ́yin rẹ̀, iṣẹ aṣiwèrè a máa dáa lágara, kò sì mọ ojú ọ̀nà sí ìlú. Ègbé ni fún ọ,ìwọ ilẹ̀ nígbàtí ọmọ rẹ̀ bá ṣe ọmọde, tí àwọn ọmọ aladé rẹ ń jẹun ní kùtùkùtu, tí àwọn ọmọ aláde n ṣe àṣẹ̀ ni òwúrọ̀, ìbùkún ni fún ilẹ
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_2.wav
ìmọràn fún ìlànà àkókò ìparọ́rọ́ tí ó ní èrè, jí dìde pẹ̀lú orin ìjúbà àti iyìnlógo, Psalm 100 verse 4, wọnú àdúrà ìyìn, ọpẹ́ àti ẹ̀bẹ̀ fún àánú, Psalm 136 verse 1, béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run fún ọgbọ́n, ìmọ̀ àti òye ní ìmúrasílẹ̀ láti
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_27.wav
L'ọlọ́run fi lè bínú sí ọ kí ó sì ba iṣẹ́ ọwọ́ rẹ jẹ́. Asán ni ọ̀pọ̀ àlá àti ọrọ̀ púpọ̀ nítorínà, dúró nínú ìbẹ̀rù ọlọ́run. Asán ni ọrọ̀ jẹ́. Bí o bá rí tálákà tí wọn ni lára ní ojú púpọ̀ tí a sì fi òtítọ́ àti ẹ̀tọ́ rẹ̀ dùú, ma ṣe jẹ́ kí ó yà ọ́ lẹ́nu láti rí irú ǹkan bẹ́ẹ̀ nítorípé ẹni tí ó wà ní ipò gíga má ń mọ́ òṣìṣẹ́ tó wà lábẹ́ rẹ̀ lójú ni. Àwọn kan sì wà tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn méjèèjì. Gbogbo wọn ni wọ́n ń
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_12.wav
Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, ayé ilé,Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, Ọ̀rọ̀ gbọ́gbọ́, ìrì sẹ́ o lórí alábahun,ìrì sẹ́ o lórí alábahun.
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_5.wav
Ìránṣẹ́ rẹ nínú olúwa. Acts 13:2-3, Exodus 34:28. Nígbàtí o bá fẹ́ gbé ìgbésẹ̀ pàtàkì nínú ayé rẹ, fún àpẹẹrẹ nípa iṣẹ́ ṣíṣe, ìgbéyàwó, kíkó lọ sí ilé titun abbl, Acts 14:22. Láti lè rí ojú rere àti àbò látòkè wá gbà
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_1.wav
Ìtàn òyín adùn oo, èro yáá, ẹ báwa ká lọ, èro yáá. Àlọ́ óò,àlọ̀. Àlọ́ọ̀ mí dá firigbàgbó, ó dá lórí ìjàpá, ajá àti ìya arúgbó kan. Ẹ pẹ̀lẹ́ ìya wa óò.O ṣéun ọmóò mi.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_43.wav
níwọ̀n ìgbà tí kò sí ẹni tí ó mọ ọjọ ọla, tani ó lè sọ fún un ohun tí ó ń bọ̀, kò sí ènìyàn tí ó lágbára lóri afẹ́fẹ́ láti gbára dúró nítorí náà kò sí ẹni tí ó ní agbára lóri ọjọ́ iku rẹ̀, bí ó ṣe jẹ́ pè kò sí ẹni tí a dá sílẹ̀ nígba ogun, bẹ́ẹ̀ náà ni ìkà kò lè fi àwọn tọ́ ń ṣe é sílẹ̀. Bí ó ti jẹ wípé kò sí ẹni tí a dá sílẹ̀ nígba ogun, bẹ́ẹ̀ náà ni ìwà búburú kò lè gba àwọn tí wọ́n ń ṣe e sílẹ̀. Gbogbo nkan wọ̀nyìí ni mo ti rí tí mo si mú lọ ni ọ̀gọrọ sí gbogbo
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_58.wav
Ọ̀rọ̀ rẹ. Ẹyẹ tó sì ní ìyẹ́ apá le fi ẹjọ́ ohun tí o ti sọ sùn. Oníwàásù orí kọkọ̀nlá, àkàrà lórí omi. Fún àkàrà rẹ sórí omi, nítorí lẹ́yìn ọjọ́ púpọ̀, ìwọ yóò rí i padà. Fi ìpín fún méje, àní fún mẹ́jọ pẹ̀lú, nítorí ìwọ kò mọ ohun ìparun tí ó le è wá sórí ilẹ̀. Bí àwọsánmọ̀ bá kún fún omi, ayé ni wọ́n ń rọ òjò sí. Bí igi wó sí ìhà gúúsù tàbí sí ìhà àríwá níbi tí ó wó sí náà, ni yóò dùbúlẹ̀ sí. Ẹni
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_5.wav
Ti ẹranko. huun, ebi yìí má wá pọ̀ o,á tií ṣè yí sí? Ǹjẹ́ ǹ ní lọ rè é bá ọ̀rẹ́ mi ajá báyìí? Ó fara jọ wí pé iyàn tó mú yìí ò dé ọ̀dọ̀ rẹ̀ rárá,ojoójúmọ́ ní ńjẹ tí ń mu,kò sì roko,kò rodò. Ú, a jẹ́ wí pé ó lọ́gbọ́n tó ń dá síi.
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_22.wav
ṣe làálà, àti wí pé èé ti ṣe tí mo fí ń fi ìgbádùn du ara mi, eléyìí náà, asán ni, iṣẹ́ òṣì, ẹni méjì sàn ju ẹni kan nítorí wọ́n ní èrè réré fún làálà wọn, tí ọ̀kan bá ṣubú lulẹ̀, ọ̀rẹ́ rẹ̀ léè ràn án lọ́wọ́, kí ó fà á sókè, sùgbọ́n ìyọnu ni fún ọkùnrin tí ó ṣubú tí kò sí ẹni tí ó le ràn án lọ́wọ́, àti pẹ̀lú pé bí ẹni méjì bá sùn pọ̀, wọn yóò móru
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
27