audio
stringlengths 44
104
| sentence
stringlengths 4
676
|
---|---|
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_53.wav | Ju igbe ohun alákoso lọ, ọgbọ́n dára ju ìlo ogun lọ. Sùgbọ́n ẹnìkan tó dẹ́sẹ̀ á máa ba ohun dídára púpọ̀ jẹ̀ ẹ́. Ìwé oníwaásù orí kẹwàá, gẹ́gẹ́ bí òkú eṣinṣin tí ń fún òróró ìkunra ní òórùn búburú, bẹ́ẹ̀ náà ni òmùgọ̀ díẹ̀ ṣe ń bo ọgbọ́n àti ọlá mọ́lẹ̀. Ọkàn ọlọ́gbọ́n a máa ṣí sí ohun tí ó tọ̀nà, ṣùgbọ́n ọkàn òmùgọ̀ sí ohun tí kò dára. Kódà bí ẹni tí ó ní ọgbọ́n bó ti ṣe ń rìn láàrín ọ̀nà, áfihàn pé òun |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_23.wav | sùgbọ́n báwo ni ẹnì kán ṣe lè dá nìkan móoru, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a lè kọjú ogun ẹni kan àwọn méjì lé gbèjà ara wọn, ìkọ okùn mẹ́ta kìí dùn yára fà já, asán ni ipò gíga otòṣì ìpẹ́ẹ̀rẹ̀ tí ó ṣe ọlọ́gbọ́n ó ṣàn ju arúgbó àti aṣiwèrè ọba lọ tí kò mọ bí yóò ṣe gba ìmọ̀ràn, nítorí pé láti inú túbú ni ó ti jáde láti jẹ ọba, bí á tilẹ̀ bí i ní tálákà ní ìjọba rẹ̀, mọ́rí gbogbo alàyè. |
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_2.wav | Jẹ́ ká lọ ran ìyá àgbàlagbà yẹn lọ́wọ́. Mi ò ní àkókò láti fí ṣòfò. Má rò ó béè gẹ́gẹ́ bíi ẹ̀kọ ọmọ oódua,a ní láti máa ran àwọn àgbàlagbà lẹ́rù. Mi ò dí ẹ lọ́wọ́ tí o báfẹ́ lọ ràn wọ́n lọ́wọ́ àmọ́ èmi ní tèmi mi ò ráyè. Ìya wa ,ẹ jẹ́ kí n ràn yín lọ́wọ́ ,O ṣéun ọmọ mi,ìwọ náà á dàgbà. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_42.wav | mo sì wípé pa òfin ọba mọ́, nítorí pé ìwọ ti ṣẹ ìbúra níwájú Ọlọ́run, ma ṣe jẹ́ kí ojú kán ọ láti kúrò níwájú Ọba, má ṣe dúró nínu ohun búburú nítorí yóò ṣe ohunkohun tí ó bá tẹ́ẹ lọ́rùn, níwọ̀n ìgbàtí ọ̀rọ ọbá ní àṣẹ, tani ó lè sọ fún un pé kíni ìwọ́ ń ṣe. Ẹnikẹ́ni tí ó bá pa àṣẹ rẹ̀ mọ́, kò ní wá sí ìpalára kankan, àya ọlọ́gbọ́n ènìyàn ó sì mọ àsìkò tí ó tọ́ àti ọ̀nà tí yóò gbà ṣe, ohun gbogbo ni ó ní àsìkò àti ọ̀nà tí ó tọ́ láti ṣe, ṣùgbọ́n òsì ènìyàn bọ́ sí |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_63.wav | Nígbà náà ni ènìyàn yóò lọ ilé rẹ́ fún ayérayé tí àwọn aṣọ̀fọ̀ yóò máa rìn kiri ìgboro. Rántí rẹ̀ kí okùn fàdákà tó já, tàbí kí ọpọ́n wúrà tó fọ́; kí iṣà tó fọ́ níbi ìsun, tàbí kí àyíká kẹ̀kẹ́ kí ó tó kán níbi kànga. Tí erùpẹ̀ yóò sì padà sí ilẹ̀ ibi tí ó ti wà, tí ẹ̀mí yóò sì padà sọ́dọ̀ Ọlọ́run tí ó fi í fún ni. Asán, asán, ni Oniwaasu wí, gbogbo rẹ̀ asán ni. Òpin gbogbo ọ̀rọ̀, Kì í ṣe wí pé |
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_4.wav | rídé orí èyí túmọ̀ sí pé kí á ka bíbélì láti Orí kan sí ìkejì ní sísẹ̀ntẹ̀lé, ẹ̀kọ́ nípa àwọn akọni èyí túmọ̀ sí pé kí á ṣe àgbéyẹ̀wò nípa àwọn akọni kànǹkan nínú bíbélì bí àpẹẹrẹ jóséfù, pọ́ọ̀lù, débórà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. |
/kaggle/working/audio_data/ojo-ose_chunk_2.wav | Mo jẹ ẹran adìyẹ lánàá. Lónìí, mo lọ sí ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ mi. Ní ọ̀la, mo mo máa ṣeré pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi. Ọ̀rọ̀ sísọ nínú àkójọ wa. Lónìí, mo ní ọ̀rọ̀ sísọ nínú àkójọ wa. Ní ọ̀la. |
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_9.wav | Yéè,ẹ gbá mí o, haa, mokú o,mi ò jẹ mọ́ o,Yéè,ẹ gbá mí o, haa, mokú o,mi ò jẹ mọ́ o,o,mi ò jẹ mọ́ o,ayé mi,tèmí bá mi,yeeeeeee. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_39.wav | kí ọlọ́gbọn ènìyàn ní agbára jú alákóso ohun mẹ́wàá lọ ní ìlu. Kò sí olódodo eniyan kan láyé, tí ó ń ṣe ohun tí ó tọ́ tí kò dẹ́ṣẹ̀ rárá, máṣe kíyèsi gbogbo ọ̀rọ̀ tí ènìyàn ń sọ, bí bẹ́ẹ̀kọ́, o lè gbọ́ pé ìránṣẹ rẹ ń ṣépè fún ọ, tí ò sì mọ̀ nínu ọkàn rẹ pé ọ̀pọ̀ ìgbà ni ìwọ fúnra rẹ ti ṣépè fún àwọn ẹlòmíràn, gbogbo èyí ní mo ti dánwò nípa ọgbọ́n, tí mò sì ríi pé mo pinnu láti jẹ́ ọlọgbọ́n, ṣùgbọ́n eléyìí ti jù mí lọ, ohun tí ó wù kí ọlọgbọ́n lè jẹ́, ó ti lọ jìnà. |
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_7.wav | Nígbàtí o bá sàkíyèsi aìsedédé nínú ìgbésí ayé krìstẹ́nì rẹ gẹ́gẹ́ bíi aìlèkóraẹni-ní-ìjánú, ìṣe ayé aìlègbàdúrà abbl Mark 14:38, Matthew 26:41. A lè lo àwẹ̀ láti ran ìsọjí ìdákọ̀kọ̀ tàbí |
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_6.wav | Máa kọ́kọ́ plan ẹ, máa kọ ọ́ lára màá ṣe gbogbo ẹ̀, màá wá record ẹ̀ màá film ẹ̀. Màá bẹ̀rẹ̀ sí edit ẹ̀, màá má subtitle ẹ̀, ẹ̀yin gan ẹ wòó ó pọ̀. Kó tún wá fún kí kọ́ọ̀sì pọ̀ lórí ibẹ̀ torí bẹ̀ for the past káni bí oṣù méjì àbóṣù meta òhun ni mo tí ǹ ṣe okay, website yẹn, kọ́ọ̀sì mo fẹ́ kó dáa gan fún yín mo fẹ́ kẹ́ẹri kẹ́ẹ ní pé háha "Blessing really tried for this matter. Sọ, nǹkan tí mo ti ń ṣe nìyẹn. Ẹ̀yin náà ẹ ronú npá rẹ̀ láti àárọ̀ di alẹ́ màá ma kọ́ àwọn ènìyàn ní |
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_4.wav | kò lè gan ọlọ́run Galatians 6:7 má ṣe wọnú àwẹ̀ nítorí o rí ẹlòmíràn tí ó ń gba àwẹ̀ a lè gbà àwẹ̀ nítorí àwọn ìdí wọ̀nyìí láti le mọ ìfẹ́ Ọlọ́run fún ayé wa isaiah 40:31 Jeremiah 3:25 láti le mọ iṣẹ́ |
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_7.wav | Ẹ fún mi ní sàláàdì àti puffpuff. Ẹ dẹ̀ má gbàgbée àkàrà òyìnbó mi oní ṣokoléètì àti wàrà dídì. Ó da, ǹkan tí ẹ bèrè fún á tó tẹ̀yín lọ́wọ́. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_64.wav | Oníwàásù jẹ́ ọlọ́gbọ́n nìkan ṣùgbọ́n ó tún kọ́ àwọn ènìyàn ní ìmọ̀, ó rọ̀ọ́ dára dára ,ó sì ṣe àwárí, Ó sì gbé àwọn òwe kalẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ, oníwàásù wádìí láti rin àwọn ọ̀nà tì ó tọ́nà, ohun tí ó kọ sì dúró ṣinṣin, ó sì jé òtítọ́, ọ̀rọ ọlọ́gbọ́n dà bí ègún ,àkójọpọ̀ ọ̀rọ wọn sí dà bí ìṣọ́ tí a kàn pọ̀ dára dára tí olùṣọ àgùntàn kán fi fún ni àti síwájú láti inú èyí ọmọọ̀ mi gbọ́ ìmọ̀nràn mi nínú ìwé púpọ̀ òpin kò sí. |
/kaggle/working/audio_data/ikute_chunk_1.wav | ìkùntè; mo ló ìkùntè mí. Fọ́, tí fọ́; ìkùntè mí tí fọ́. Ìrínisí dídára; ìkùntè mí ó dára. Ẹ̀rọ ayára bí àṣà; mo ló ẹ̀rọ ayára bí àṣà |
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_6.wav | kí ba ẹ̀kọ́ ọ̀rọ̀ ọlọ́run nínú ayé wa, gbàdúrà lóníruúrú ọ̀nà, bẹ̀rẹ̀ ọjọ́ rẹ kí o sì jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ rẹ mọ́lẹ̀ sí gbogbo ènìyàn nípa pínpín ìbùkún rẹ pẹ̀lú wọn Phillipians chapter 2:15, Colossians 3:16, lákòótán |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_74.wav | Nil |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_47.wav | oníwàásù orí kẹsàn an, nígbà naa ni ronú lóri gbogbo èyí tí mo sì parí rẹ̀ pé, olóòtọ́ àti ọlọgbọ́n àti ohun tí wọ́n ṣe wà lọ́wọ́ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n kò sí ẹniyan tó mọ̀ bóyá ìfẹ́ tàbí ìríra ni ó ń dúró de òun, àyànmọ́ kan náà ni gbogbo wọ́n ni, olóòtọ́ àti enìyàn búburu, rere àti ibi, mímọ́ àti àìmọ́, àwọn tí ó ń rebo àti àwọn tí kò rebo, bí ó ti rí pẹ̀lu ènìyàn rere, bẹ́ẹ̀ náà ni ó rí pẹ̀lu ènìyàn tí ó dẹ́ṣẹ̀, bí ó ti rí pẹ̀lu |
/kaggle/working/audio_data/ikute_chunk_5.wav | Bùnmi àti Ṣadé mo rò pé ó yẹ kí ẹ gbájúmọ́ iṣẹ́ yín. Ẹ̀rọ ayára bí àṣà kò níí ṣe pẹ̀lú ètè yín. Kọjú iṣẹ́ ẹ̀ rẹ, aṣiṣẹ́ bí akúrẹtẹ̀. |
/kaggle/working/audio_data/ogabirin_chunk_6.wav | Eléyìí tó náà fénìí. |
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_10.wav | Ǹjẹ́ àlọ́ yìí kọ́ wa pé kí á máa bọ́wọ́ fún àgbàlagbà, ó tún kọ́ wa pé kí á máa ran àwọn àgbàlagbà lọ́wọ́, ó tún kọ́ wa wí pé kò dára kí á máa jalè, kò dáa,olè ló ba ọmọlúàbí jẹ́. Ó tún kọ́ wa wí pé kò dára kí á ní ọ̀kanjúà. Ẹ má jẹ́ á máa ṣọ̀kánjúà. Ọ̀kanjúà a máa kó ni sínú ìyọnu,a ò ní rí ìyọnu o. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_2.wav | Òhun náà yó sì máa wà. Ohun tí a ti ṣe sẹ́yìn òun náà la á tún máa ṣe padà. Kò sí ohun titun kan lábẹ́ ọ̀run. Ǹjẹ́ a rí ẹnì kan tí ó lè sọ wípé, wò ó ohun titun ni èyí. Ó ti wà tẹ́lẹ̀ rí ní ọjọ́ tó ti pẹ́, ó ti wà ṣáájú ti wa. Kò sí ìrántí ohun ìṣáájú bẹ́ẹ̀ ni ìrántí kì yóò sí fún ohun ìkẹyìn tí ń bọ̀, lọ́dọ̀ àwọn tí ń bọ̀ ní ìgbà ìkẹyìn. Asán ni ọgbọ́n ènìyàn. Èmi oníwàásù ti |
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_1.wav | tí ó dára jù láti múlò ní òwúrọ̀, jẹ́ àkókò tí à ń yà sọ́tọ̀ láti dúpẹ́ lọ́dọ̀ Ọlọ́run, pẹ̀lú àwọn orin ìjúbà àti iyìnlógo kíka ọ̀rọ̀ ọlọ́run àti àdúrà sí Olúwa, ó jẹ́ àkókò tí Ọlọ́run máa ń bá wa sọ̀rọ̀ nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ bíbélì, àwa pẹ̀lú a sì máa ń bá ọlọ́run sọ̀rọ̀ nípa gbígba àdúrà sí i |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_51.wav | egun fún alágbára, bẹ́ẹ̀ni óúnjẹ kò wà fún ọlọ́gbọ́n, tàbí ọ̀rọ̀ fún ẹni tó ní òye, tàbí ojúrere fún ẹni tó ní ímọ̀, ṣùgbọ́n ìgbà àti ẹ̀sín ń ṣẹlẹ̀ si gbogbo wọn. Síwájú síi kò sí ẹni tí ó mọ ìgbà tí àkóko rẹ̀ yóò dé. Gẹ́gẹ́ bí a tí mu ẹja nínu àwọ búburú, tàbí tí à ń mu ẹyẹ nínu okùn, gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni à ń mú ènìyàn ní àkóko ibi tí ó ń ṣubú lù wọ́n lairo tẹ́lẹ̀. Ọgbọ́n dára ju òmùgọ̀ lọ, mo sì tún ri àpẹrẹ ọgbọ́n tí ó dùnmọ́ |
/kaggle/working/audio_data/omo-isin_chunk_2.wav | Ìtanọlá lorúkọ mi. ọjó ọ̀la yín ni míì. ọjọ́ ọ̀la tèmi? Bẹ́ẹ̀ni, èmi lọjọ́ ọ̀la ẹ̀yin méjèèjì. Balógun lọjọ́ọ̀la tiyín, lálóńpé Àyọ̀ní lọjọ́ọ̀la Balógun, nígbàtí Akínbógun tó jẹ́ bàba tèmi tó jẹ́ ọ̀la fún Lalóńpé tó jẹ́ ọmọ Balógun. Èmi |
/kaggle/working/audio_data/ojo-ose_chunk_0.wav | Ọjọ́ ajé, ọjọ́ ìṣẹ́gun, ọjọ́rú, ọjọ́bọ̀, ọjọ́ ẹtì, ọjọ́ àbámẹ̀ta, ọjọ́ àìkú. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_52.wav | Mi lábẹ́ òòrùn, Ìlú kékeré kan wà tí ènìyàn díẹ̀ wà nínú rẹ̀ wà ní ìgbà kan rí. Ọba alágbára kan sì ṣígun tọ ìlú náà lọ, ó yí i po, ó sì kọ́ ilé ìṣọ́ tí ó tóbi lòdì sí i. Ṣùgbọ́n, tálákà ọkùnrin tí ó jẹ́ ọlọ́gbọ́n kan ń gbé ní ìlú náà, ó sì gba gbogbo ìlú u rẹ̀ là pẹ̀lú ọgbọ́n rẹ̀. Ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó rántí ọkùnrin tálákà náà. Nítorí náà mo sọ wí pé, Ọgbọ́n dára ju agbára. Ṣùgbọ́n a kẹ́gàn ọgbọ́n ọkùnrin tálákà náà, wọn kò sì mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣe. Ọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́ ọlọ́gbọ́n ènìyàn a máa wà ní ìmúṣẹ |
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_7.wav | Rárá Ṣadé. Kìn ń ṣe ìnkan tí mò ń sọ nìyẹn. Èdè-àyedè ńlá lèyí. Jẹ́ ń sọ òótọ́ òótọ́ fún ẹ. Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ san iye owó ilé-ìwòsàn ilé-ìwòsàn ìyá mi, mi ò dẹ̀ lówó tó tó láti fi ra iyán ẹ. Ìyẹn lo ò bá ti sọ tipẹ́. Mo ṣẹ̀ gba owó iṣẹ́ ni, màá san owó. |
/kaggle/working/audio_data/baddie_laylay_chunk_1.wav | àti àwọn tó kù, Hassan gbogbo wọn ló pitú, ṣùgbọ́n tani favourite yín? Ẹ bá wa kọ sí comment section. Kí lẹ rò pé ó máa padà ṣẹlẹ̀, bí ọkọ ẹ̀ ṣe káa mọ́ ọkùnrin níbi tí part one parí sí? ó máa le síta ní, àbí kí lẹ rò pé ó máa fí ṣe? Pẹ̀lu gbogbo bó ṣe tẹ́ ẹ lọ́rùn tó, ó sì gbé ìwà obìnrin jáde, ó sì lọ ń cheat lórí ọkọ ẹ̀. Kí lẹ wá rò pé yóò ṣẹlẹ̀? Kí lẹ rò pé ọkọ ẹ̀ máa ṣe? ẹ bá wa kọ ọ́ sí comment section. Ẹ̀yin tí ò bá tíì wo fíìmù náà míìsì |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_60.wav | Ó sì dára fún ojú láti rí òrùn, sùgbọ́n jẹ́kí ènìyàn jẹ̀ gbádùn gbogbo iye ọdún tí ó lè lò láyé, sùgbọ́n jẹ́kí ó rántí ọjọ́ òkùnkùn nítorí wọn o pọ̀, gbogbo ohun tí ń bọ̀ asán ni, jẹ́kí inú re dùn ìwọ òdómọdé ní ìgbà tí o wà ní èwe, kí o sì jẹ́kí ọkàn rẹ́ kún fún ayọ̀ ní ìgbà èwe rẹ. Tẹ̀lé ọ̀nà ọkàn rẹ àti ohunkóhun tí ojú rẹ rí, sùgbọ́n mọ̀ dájú wípé nípa gbogbo ǹkan wọ̀nyìí, ọlọ́run yóò mú ọ wá sí ìdájọ́. Nítorí náà, mú ìjayà kúrò. |
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_7.wav | Ní Yorùbá, as in private lesson,mo máa ń kọ́ àwọn èèyàn ni Yorùbá, nínú free time màá tún film Yorùbá course, nínú free time màá tún edit Yorùbá course, Yorùbá ti sú mi as in I have spoken taught Yorùbá die, ó ti sú mi, so mi ò wá kí ní agbára,mi ò kì ní energy pé kí ń tún wá síbi ki tún ma sọ Yorùbá ó, I cannot mi ò lè ṣé torí bẹ̀ ni mo ṣe take relaxation period ṣùgbọ́n mo ní pé okay, mo ṣì fẹ́ kọ yín ní Yorùbá, mo ṣì fẹ́ fun yín ní Yorùbá content so mo wá ní pé jẹ́ kí n̄. |
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_4.wav | Kí lo fẹ́ bèèrè? Mo sì ń rò ó, bóyá mo máa yan ọbẹ̀ ilá àti ìyàn. Ṣé ó dá ẹ lójú? |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_4.wav | Ọgbọ́n mi sì ti pọ̀ ju ti ẹnikẹ́ni tí ó ti ṣe alákòóso Jerúsálẹ́mù bọ́ síwájú mi lọ. Mo ti ní ìrírí púpọ̀ nípa ọgbọ́n àti ìmọ̀ nígbà náà ni mo fi ara jìn láti nímọ̀ nípa ọgbọ́n àti pàápàá àìgbọ́n àti òmùgọ̀.Ṣùgbọ́n nítorí wí pé èyí pẹ̀lú bí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni, nítorí pé, ọgbọ́n púpọ̀, ìbànújẹ́ púpọ̀ ní ń mú wá, bí ìmọ̀ bá sì ṣe pọ̀ tó náà ni ìbànújẹ́ ń pọ̀ tó. Oníwàásù orí kejì |
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_5.wav | Kí leléyìí? Ọbẹ̀ ẹ̀wà tí ẹ bèrè fún rèé. Nísìnyí, mi ò fẹ́ ọbẹ̀ ẹ̀wà mọ́. Áh àh. Ẹ fún mi ní àkàrà òyìnbó oní ṣokoléètì àti wàrà dídì. |
/kaggle/working/audio_data/beere_chunk_2.wav | Kíni. Kíni o fẹ́? Ṣo ti jẹun? Óunjẹ. Mo má ń jẹ óunjẹ. Bàjẹ́. Ọmọ yín yìí bàjẹ́. |
/kaggle/working/audio_data/muyiwa_chunk_0.wav | kílódé kíló ṣẹlẹ̀ tẹ́ ǹ jẹ́ kí ó máa sọ òkùta mọ́ ẹni ẹlẹ́ni, àjẹ́ ni, wọ́n sì ń sọ̀kò pa àjẹ́ ni. So, báwo ni ẹ̀yín ṣe mọ̀ wípé àjẹ́ ni, Ha ha, kí lò ń wí yìí, a ò tó báyìí a kò wá ni dá àjẹ́ mọ̀, àjẹ́ leléyìí. Ẹ ti ẹ̀ dákun ẹ dúró ná, tani ìwọ tó ń lọwá ni , ọ ẹ ò mọ̀ọ́ ni? mebí akàwé mọ́ ríṣẹ́ ti mọ́ nọ́ḿba ọkọ̀ tí gbogbo ìlú dáwó jọ fún pé ó rèé kàwé nù un, hẹ̀n hẹ̀n hẹ̀n, Múyìwá rèé? oun nii, ha Múyìwa ìwọ lo ti tóyìí |
/kaggle/working/audio_data/ikute_chunk_2.wav | Ṣá mi; mo ló ẹ̀rọ ayára bí àṣà rẹ. Pàtàkì; ó ṣe pàtàkì, èyí ṣe pàtàkì, èyí kò ṣe pàtàkì. Mo lérò; mo lérò pé kò ṣe pàtàkì. Títọ́; èyí tọ́ |
/kaggle/working/audio_data/200625-215447_yor_874_elicit_23.wav | ní ìlú èkó sùnkẹrẹ fàkẹrẹ ọkọ̀ kò jẹ́ kí òbí tètè délé lẹ́yin iṣẹ́ ọjọ́ wọn, ẹlòmíràn ti jí |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_34.wav | n tí ojú rí ṣàn ju ìfẹnuwákiri lọ asán ni eléyìí pẹ̀lú, ó dàbí ẹni ń gbìyànjú àti wo afẹ́fẹ́, ohunkóhun tí ó bá ti wà ti ní orúkọ, ohun tí ènìyàn jẹ́ ṣì ti di mímọ̀, kò sí ènìyàn tí ó le ja ìjàkadì pẹ̀lú ẹni tí ó lágbára jù ú lọ, ọ̀rọ̀ púpọ̀ kìí nítumọ̀, èrè wo ni ènìyàn ní nínú rẹ̀ àbí tani ó mọ ohun tó dára fún ènìyàn ní ayé fún ọjọ́ ayé kúkurú àti àsán tí ó lọ kọjá gẹ́gẹ́ bí òjìji, tani ó lè sọ fún mi, ohun tí ò ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_59.wav | Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń wo afẹ́fẹ́, kò ní fúrúgbìn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń wo awọ sánmọ̀, kò ní kórè. Gẹ́gẹ́ bí ìwọ kó se mọ ojú ọ̀nà afẹ́fẹ́ tàbí mọ̀ bí ọmọ ti ń dàgbà nínú ikùn ìyà rẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ìwọ kò lè ní òye sí iṣẹ̀ olọ́run ẹlẹ́dàá ohun gbogbo. Fún irúgbìn rẹ ní òwúrọ̀ kùtùkùtù, má ṣìse jẹ́kí ọwọ́ rẹ ṣ'ọ̀lẹ ní àṣálẹ́, nítorí tí ìwọ kò mọ èyí tí yóó se rere, bóyá èyí tàbí eyì tàbí àwọn méjéèjì ni yóò se dáradára bákan náà. Rántí ẹlẹ́dàá rẹ nígbà èwe rẹ. Ìmọ́lẹ̀ dùn. |
/kaggle/working/audio_data/muyiwa_chunk_3.wav | a jọ yin loju , ki lo n ṣe yin, ha, ẹ wo ara yin, hẹ́n, ṣemi ree, ṣebi ẹ ti rii, ẹ wo bi mo ti ri lori foonu nla, foonu nla maa n jẹ ki eniyan rẹwa oo, |
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_3.wav | O ṣéun ọmọ mi. Ìyá,ńjẹ́ ǹkankan wà tí ẹ tún fẹ́ kába yín ṣe? O ti gbìyànjú ọmọọ̀ mi,ẹ̀mi náà ó sì ṣe ọ̀ lóore. Ẹ má ṣèyọnu ìya wa. Tẹ̀lẹ́ mi kálọ. Ṣo rí àwọn ìlù mẹ́ta yìí. |
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_11.wav | tí kòró bá jẹ́ ká,asin tí kòró bá fún wá láyè tó bá gbà wá láyè, tó bá fún wa lọ́nà t'Ọlọrun bá dẹ̀ ni bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe máa rí mo máa lọ sí Nigeria. E lè bèrè pé kí lo fẹ́ lọ ṣe ni Nigeria, kín lò ń lọ ṣe, mind your business, kò kàn yín, nǹkan tí mo fẹ́ lọ ṣe ni Nigeria kò kàn yín, ṣùgbọ́n mo mọ̀ pe mo ma máa fún un yin ni back to back content níbẹ̀ torí you know màa nílé ara mi máa lè máa fun yin ni what i need in a day màa le máa ṣe cooking videos fun yin, mo mọ̀ pé ẹ máa n bèrè cooking videos, and finally mà lè |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_21.wav | ká ọwọ́ rẹ̀ kò, ó sì bá tara rẹ̀ jẹ́ óúnjẹ́ ẹ̀kún ọwọ́ kan pẹ̀lú ìdákẹ́jẹ́jẹ́ ṣán ju ẹ̀kún ọwọ́ méjì pẹ̀lú wàhálà àti gbígba iyànjú àti lí afẹ́fẹ́ lọ. lẹ́ẹ̀kan sí i, mo tún rí ohun àsán kan lábẹ́ ọ̀run, ọkùnrin ṣoṣo dá wà, kò ní ọmọkùnrin kankan tàbí ẹbí , kò sí òpin sí inú làálà rẹ̀ gbogbo síbẹ̀ ọrọ̀ kò tẹ́ ojú rẹ̀ lọ́rùn, bẹ́ẹ̀ni kò sì wí pé nítorí tani èmi ṣe ń |
/kaggle/working/audio_data/ojo-ose_chunk_3.wav | Mo ní ayẹyẹ ìgbéyàwó ní ọ̀la. Mo máa lọ gba aṣọ ẹbí mi tí ń máa wọ̀ lọ sí ìgbéyàwó. Aṣọ ẹbí. Mo wọ aṣọ ẹbí. Mo máa wọ aṣọ ẹbí mi ní ọ̀la. Pàtàkì. Èwo ló ṣe pàtàkì jù lọ? Ṣé ówàńbẹ̀ ni tàbí iṣẹ́ mi? |
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_7.wav | ìjókòó ọ̀rọ̀ ọlọ́run nínú ókan àyà rẹ ni ó lè fún ọ ní ìyè àní ìyè ní kíkún èyí tí ó ń sọni di aṣẹ́gun kìrìstẹ́nì ọ̀rọ̀ pàtàkì àkókò ìparọ́rọ́ yàtọ̀ sí àkókò àdúrà ẹbí, ọ̀rọ̀ òtítọ́ fún ìyè, ọ̀rọ̀ náà ni ó lè mú ọ yàtọ̀ nínú ayé. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_54.wav | Òmùgọ̀ kò ní ọgbọ́n a sì máa fihan gbogbo ènìyàn bí ó ti gọ̀ tó. Kódà bí ó ti ṣe ń rìn láàrín ọ̀nà, òmùgọ̀ kò ní ọgbọ́n a sì máa fihan gbogbo ènìyàn bí ó ti gọ̀ tó. Bí ìbínú alákòóṣo bá dìde lòdì sí ọ, ma ṣe fi ààyè rẹ sílẹ̀, ìdákẹ́ jẹ́ẹ́jẹ́ le è tú àṣìṣe ńlá. Ohun ibi kan wà tí mo ti rí lábẹ́ oòrùn, irú àṣìṣe tí ó dìde láti ọ̀dọ̀ alákòóṣo. A gbé aṣiwèrè sí ọ̀pọ̀ ipò tí ó ga jùlọ, nígbà tí ọlọ́rọ̀ gba àwọn ààyè tí ó kéré jùlọ. Mo ti rí ẹrú lórí ẹṣin, nígbà |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_33.wav | hàn síi ni orúkọ rẹ̀ fi ara pamọ́ sí, bí ó jẹ́ wí pé kò rí òrùn, tàbí mọ ohunkóhun ó ní ọ̀pọ̀ ìsinmi ju ọkùnrin náà lọ kódà bí ó wà láyé fún ẹgbẹ̀rún ọdún méjì yípo sùgbọ́n tí ò kùnà láti gbádùn ohun ìní rẹ̀, ṣé kìí ṣe ibi kan ṣoṣo ni gbogbo wọn ń lọ, gbogbo wàhálà tí ènìyàn ń ṣe nítorí àtijẹ ni síbẹ̀ ikùn rẹ̀ kò yó rí, kí ni ànfàní tí ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní lórí aṣiwèrè, kí ni èrè tálákà ènìyàn nípa mímọ bí yóò ṣe wùwà níwájú àwọn tókù |
/kaggle/working/audio_data/ogabirin_chunk_4.wav | àtẹ̀jíṣẹ́ mi, mo fún ọ lési. Ẹ káàsán ma, káàsán Dami, mo nílò láti ra óúnjẹ yín. Fún mi ni àpamọ́wọ́ mi, owo mi wà nínu àpamọ́wọ. Gbà, jọ̀wọ́ ṣe o lè |
/kaggle/working/audio_data/ogabirin_chunk_5.wav | Bá mi ra ìwé ìròyìn. Bẹ́ẹ̀ni mà, màá ra ìwé ìròyìn pẹ̀lú. O ṣeun. Jọ̀wọ́ fọ mọ́tò mi. Gba aṣọ mi lọ́wọ́ alágbàfọ̀,nu bàtà mi, kí o sì fèsì sí ìwé àtẹ̀jíṣẹ́ mi. Ó dára dára mà, ṣé ó ti tán? Rárá o. Ṣé o fẹ́ iṣẹ́ si? Rárá mà o. |
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_3.wav | Ti ka ọ̀rọ̀ rẹ̀ Psalm 119 verse 130 ka bíbélì rẹ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀mí-mímọ́ bá ṣe darí second Timothy chapter 12 verse 15, Acts of Apostle chapter 17 verse 11, Job chapter 23 verse 12, èto kíka bíbélì léè jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìlànà wọ̀nyìí ẹ̀kọ́ láti o |
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_0.wav | ẹ̀kọ́ kẹẹ̀sán àwẹ̀ àti àdúrà nípa ìlànà bíbélì, ẹsẹ ọ̀rọ̀ yìí, ó sì wí fún wọn pé irú èyí kò le tipa ohun kan jáde bikòṣe nípa àwẹ̀ àti àdúrà Mark 9:29 ọ̀rọ̀ àkọ́kọ́ |
/kaggle/working/audio_data/oregbin_chunk_6.wav | Salad dáa fún ẹ. Kílódé tí salad fi dáa fún mi? Ṣé ò ń pè mí ní ẹni sísanra ni? O ò sanra. Mo ní ìfẹ́ sí bó bó o ṣe rí. O pé. Ìwọ ni obìnrin ayò mi. Èmi ni obìnrin kan ayò ẹ? Pé obìnrin pọ̀ lọ́wọ́ ẹ dáadáa. Àà, mo mọ̀. |
/kaggle/working/audio_data/Eko-2_chunk_8.wav | nill. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_44.wav | tí à ń ṣe lábẹ́ ọ̀run, ìgbà kan wà tí ẹnikan ń ṣe olóri àwọn tó kù fún ìpalára ara rẹ̀. Nígbà náà ni mó tún rí ìsìnkú ènìyàn búbúrú àwọn tí wọn ma ń wá tí wọ̀n sì n lọ láti ibi mímọ kí wọn si pa ìgò ní ìlú tàbí tí wọ́n ṣe ìlu, éléyìí pẹ̀lú kò ní ìdùnnú. Nígbàtí a kò bá tètè ṣe adájọ́ fún ẹlẹ́ṣẹ̀ kíákíá, ọkàn àwọn èyàn a máa kún fún èrò láti ṣe ibi. Bí ènìyàn búburú tí ó dẹ́ṣẹ̀ nígba ọgọ́run ti lè wà láyé fún ìgbà pípẹ́, mo mọ̀ wipé yóò dára fún ẹni tí ó bẹ̀ru Ọlọ́run |
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_2.wav | láìsí èyí yóò jásí ìjaraẹniníyàn lásán, kíni ìdí tí ènìyàn fi ń gbàwẹ̀, kí a tó máa sọ̀rọ̀ nípa ìdí tí ènìyàn fi ń gbàwẹ̀, a ó kọ́kọ́ tọ́ka sí àwọn ìdí tí kò yẹ láti fi gbàwẹ̀, máṣe gbàwẹ̀ nítorí kí ọlọ́run lè yí ìfé rẹ̀ padà fún ayé rẹ Psalm 106:15 |
/kaggle/working/audio_data/ijapa_chunk_8.wav | Àlábuhun ò ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́, alábuhun ò ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́, ìjàpá tìrókò ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́ ni, ọkọ yáníbo ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́ ni,ìrí ǹ ọ̀kẹ́,A jẹ jolóhun lọ. |
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_13.wav | really wà n bẹ̀, tí mi ò lè really ṣe dáadáa tó. Mo fẹ́ máa film àwọn video tó jẹ́ pé èmi gan tí n b'ń wò wán màá máa gbádùn ẹ̀ inú mi á dùn si, torí bẹ̀ tẹ́ẹ bá mọ bí mo ṣe lè diversify content mi àti pé ẹ ò kúkú wo àwọn video yìí ẹ kàn ń sọ̀rọ̀ ni, ẹ ẹ́ ma pariwo fún wa ni video fún wa ni video, video méji àbí mẹ́ta tí mo ṣe ẹ ò wò wọ́n, wọn ò tíì tó 1000 a ti fẹ́ẹ̀ tọ́ 30000 kí ló ń ṣẹlẹ̀ ṣẹ́ẹ get. So èmi gan ó ti ń sú mi torí ó dàbípé ó ti ń sú ẹ̀yin náà torí ẹ ò wo àwọn video bó ṣe yẹ |
/kaggle/working/audio_data/eko-9_chunk_6.wav | Esther 4:16, Esther 5:2-3. Fún ìrònúpìwàdà àti ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀. Jonah 3:1-5. Láti lè yan ọ̀nà tó tọ́ nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà. Luke 6:12-13 |
/kaggle/working/audio_data/chit-chat_chunk_8.wav | video ní Yorùbá so wọn a ṣì máa kọ ṣùgbọ́n màá lé fún wọn ni explanation torí ìgbàmíì ẹ máa ń kọ̀wé sími pé oh, "Blessing where are you? Are you still doing lessons?" Mo mọ̀ mi ò le gbọ̀ ohùn yín ṣùgbọ́n ohun kankan tí mo máa n gbọ́ tí mo báa ń ka message yin nìyẹn " Are you still doing lessons?" mo ṣì ń ṣe lesson dear. màa ṣì máa fún yin ni video láwọn lóri bí, màá ṣì má fún un yin ní content lóri bí. Màá ṣì máa fun un yin ni àwọn content tí ẹ̀ ń seek. The content you are asking for you are still gonna get it. Ẹ má worry, ẹ má worry, láti kọ́ Yorùbá yìí ẹ ẹ́ ṣì k |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_48.wav | àwọn tí ó́ ń ṣe ìbúra bẹ́ẹ̀ náà ni o rí pẹ̀lu àwọn tí ó bẹ̀rù láti ṣe ìbúra. Ohun búburú ni èyí jẹ́ nínu gbogbo ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run, ìpín kan ṣoṣo ni o ń dúró de gbogbo wọn, ọkàn ènìyàn pẹ̀lú ó kún fún ibi, ìsinmi ṣì wà ní ọkàn wọn nígbàtí wọn wà láàyè àti nígbàtí wọ́n bá darapọ̀ mọ́ òkú. Ẹnikẹ́ni to wà láàrin alàyè ni o dì, kódà àye ajá sàn ju òku kìnìun lọ. Nítorí pé, ẹni tí ó wà láàyè mọ̀ wípé |
/kaggle/working/audio_data/Yoruba Conversation In the market - Èdè Yorùbá (1)-[AudioTrimmer.com].mp3 | èló ni tàtàṣé? ẹgbẹ̀run náírà. Háà ó ti wọ́n jù. Gbogbo ǹǹkan ti wọ́n. |
/kaggle/working/audio_data/trimmed_chunk_67.wav | Charitable outreaches in line with the United Nations sustainable development goals particularly number two, zero hunger and number four, quality education. And of course, we do have audio cantons store where you can purchase Christian teamed mesh. Your donations and or your purchase is valuable for it contribute to the success of our nation to spread the love of God through giving and to create edifying contents in audio. Remember that Jesus loves you, has your best interest… |
/kaggle/working/audio_data/ogabirin_chunk_2.wav | Fún mi ní owó. Mo nílò láti ra oúnjẹ. Ra oúnjẹ fún mi. Àgbàfọ̀. Mo, wa ọkọ̀ mi. Ọkọ̀. Fọ ọkọ̀ mi. Àtẹ̀jíṣẹ́. Mo kọ àtẹ̀jíṣẹ́. |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.