Proverbs
stringlengths
8
373
Labels
int64
0
1
Pátákó ìpolówó ọjà wó pa èèyàn mẹ́rìnlá tó sá sábẹ́ rẹ̀ lásìkò ìjì òjò líle.
0
A kì í jẹ oyè ẹnu ọ̀nà kalẹ́ .
1
Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ni mo kà lókè òkun.
0
‘‘M̀bá wà lỌ́yọ̀ọ́ mà ti so ẹṣin’’; àgùntàn-an rẹ̀ á níye nílẹ̀yí.
1
Ará okó ní òun gbọ́ fínrín fínrín; ta ló sọ fun bí kò ṣe ará ile?
1
B'éégún bá wọ'lé àgbẹdẹ kó l'éèwọ, àfara ní 'ò gbọdọ já.
1
Bí ó di ọdún m ta tí ẹkùn-ún ti ń ṣe òjòjò, olugbe la ó ha rán lọ bẹ̀ wò? I
1
Àwọn ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ti kéde pé àwọn yóò yan-iṣẹ́-lódì ní ọjọ́ kẹwàá oṣù yìí.
0
Ààrẹ gbàdúrá pé kí Ọlọ́run tu àwọn ẹbí olóògbé náà nínú.
0
Bí a bá gbóńje f'egbę, a á dùró gbàwo bọ ni.
1
Olórí àwọn agbẹjọ́rò olùpẹjọ́ ti pẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn lórí ọ̀ràn náà.
0
Àwọn ajínigbé ti Ayọ̀mídé jáde nínú ọkọ̀ wọn bí ó ṣe ń pariwo.
0
Wọ́n sọ wí pé ó wun àwọn láti lọ ṣiṣẹ́ ní òkè òkun.
0
A ní ìgbàgbọ́ pé ètò ìbò ọdún yìí yóò yàtọ̀ sí ti tẹ́lẹ̀.
0
Emi ni mo dára tó yìí' larẹwà fin han ara rẹ lénmọ.
1
Ìlú Ọ̀yọ́ kò lè ní Lèmọ́mù bí wọn kò bá ì tí ì yan Aláàfin.
0
Bísí àti Tọ́lá ń jà sí ọkùnrin kan náà.
0
B'éèyàn bá ta'jà erùpẹ, yóó gb'owó Ògúlùùtu.
1
Àwọn ọlọ́pàá sọ pé ó ṣeé ṣe kí obìnrin ọ̀hún lọ sẹ́wọ̀n.
0
B'ẹni bá ń relé ìmùlẹ, k'ẹni sán ọbẹ-bàbà, kẹni sán ọbẹ-òjé, toríawo eni níí se'ni níhun.
1
Àbòsí pèléte, n'ọn jọmore. (n'ọn je omore/ọmọ ìyà)
1
Ewúrę gun pẹpẹ, àgbébọ ń gun àjà, àkùkọ ń kọ l'órùlé, ọmọ ńgbá baba létí, e pé kò sí nnkan. A ó rẹyìn-in re bí yóó se rí.
1
Ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí wọ́n bá níbẹ̀ ló ṣe ọ̀nà bí wọ́n ṣe sá lọ.
0
Àkíyèsí ti wà lórí bóyá Adégún ni yóò jẹ Olúbàdàn tuntun.
0
Lẹ́yìn Ọlọ́run, ìjọba ló tún kù.
0
Lẹ́yìn èyí ni àwọn agbófinró lọ sí ilé ìwòsàn tí wọ́n gbé Àìná lọ.
0
B'éèyàn pòòyì nígbà igba, ìdí 'ò ní kúrò níbi tó wà (láàye rę)
1
A kì í fini joyè àwòdì ká má lè gbádìẹ.
1
Ẹnu-isà là á ti í pínmọ eku.
1
Àyìnlá jẹun láìsan owó ìyá olójẹ.
0
Ẹlẹ́dẹ̀ ń pàfọ̀ ó rò pé òun ń ṣoge.
1
Apẹ́ẹ́jẹ kì í jẹ ìbàjẹ́ .
1
Bí a ó jọba lọla, àbá làá kọkọo dá.
1
Afurasí òṣèlú máa jìyà pé ó ń gbèrò láti gba ìjọba.
0
Agbègbè Ìkòròdú yìí jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn agbègbè tó ṣeé ṣe kí ẹ̀kún omi ti máa ń wáyé ní bẹ̀ tẹ́lẹ̀.
0
Àwọn alágbára á máa já ìjọba gbà mọ́ àwọn aláìlágbára lọ́wọ́.
0
Ẹrúkọ (tó) lórí kò ní mùndùnmúndùn.
1
Àjà ló lẹrù irọ́ ni pẹpẹ ń pa.
1
Gbogbo ọ̀nà tí ẹ̀dá bá mọ̀ ni kí ó tọ̀ láti gbé ìgbé-ayé ìrọ̀rùn.
0
Mo bẹ ìjọba pé kí wọ́n forí jìn mi fún èyí.
0
Bí obìnrín bá máa dán èké wò, a da aṣọ dúdú bora.
1
Àyìndé máa ń parọ́ lọ́pọ̀lọpọ̀ kódà èṣù ò parọ́ tó o.
0
Ẹni kánjú j'Olúwa, a á sòògùn k'ọjáa kádàrá.
1
Béèyàn bá mọ o wà, tó mọ o bò, Ọlọrun Ọba Nikan Ní í gbọko lowo irúu wọn.
1
Ọta ìbọn ba ọ̀kan nínú òṣìṣẹ́ inú ọjà níbi tí ó forí pamọ́ sí.
0
Àtàtàkurá: ẹnu ẹyẹ ò ran òkúta.
1
A fẹ́ ẹ nílé, a fẹ́ ẹ lóko; bọ́mọ́ bá ti lóyún, kò parí ná?
1
Adìẹ́ dà mí lóògùn nù; mo fọ́ ọ lẹ́yin.
1
Bí ìbágbé ò bá wọ̀, ká yàgò fúnra.
1
Ekiti ní àwọn ọ̀mọ̀wé pọ̀ jù sí ní gbogbo ilẹ̀ Yorùbá lápapọ̀
0
A-dÍfá-bí-ẹní-ń mùjẹ̀- dÍfá kò rí mu; Amùṣùà aya rẹ̀- ní òun ó fòjò wẹ̀.
1
Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá gbé oríkì yẹ̀wò.
0
B'ó bá róbì a á pa; eni tó f'ẹșe (fi ẹșẹbì) kan orí ę wò.
1
Màríà sọ pé inú igbó ni Bùsọ́lá kú sí nígbà tí wọ́n dúró láti sinmi.
0
Abíọ́dún kò rántí pé òun ran Dọ́kítà náà lọ́wọ́.
0
Bí obìnrin ò bá gbé ilé tó méjì, kì í mọ èyí tó sàn.
1
Àwọn olókìkí ni ilé-iṣẹ́ náà máa ń yàn gẹ́gẹ́ bí aṣojú.
0
Àwọn ènìyàn ń gba àdúrà fún Aláàfín.
0
A gbọ́ lẹ́nu àwọn èèyàn kan wí pé Òkìkíọlá kì í ṣe ọkọ gidi fún Dámilọ́lá.
0
A kì í fașíyàn f'ọkọ lẹệmejì.
1
Àyà jíjá máa ń wáyé láti ara àjàkálẹ̀-àrùn.
0
Bí a bá rẹkùn, àá wò ó fín ni.
1
Àti wá mọ èyí tó dára jùlọ nínú méjèèjì wá di ìṣòro.
0
Ààrẹ nìkan ló láṣẹ láti yọ adájọ àgbà kúrò nípò.
0
Aáyán fẹ́ gẹṣin; adìẹ ni ò gbà fún un.
1
Bí a bá dẹjú làá rímú.
1
Àwọn ìbéèrè ìdánwò sì máa ń jẹ́ bákan náà.
0
Ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí Ilẹ̀pa wó lù ṣèṣe gidigidi.
0
Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Èkó sọ pé òun fara mọ́ èrò táwọn ẹlẹgbẹ́ òun sọ pátá.
0
Àwọn ọlọ́pàá sọ wí pé Ọláolúwa ni orúkọ àgbẹ̀ ọ̀hún ń jẹ́
0
A níṣẹ́ iṣẹ́ ẹ, o ní ò ń lọ sóko; bó o bá lọ sóko ò ń bọ̀ wá bá a nílé.
1
Àwọn ọmọ ìta kọlu onírọ̀yìn kan ní ìlú Èkìtì.
0
Àìso àbà ló m'ẹyẹ wá jẹgbá, ẹyẹ kì í jẹgbá.
1
Bí eré, bí àwàdà ni ó ṣe kọ́kọ́ rí.
0
B'óbìnrin sàlejọ ọkọo rẹ níí wí fún.
1
Àwọn kan láàárín wọn máa ń ṣe aṣojú ilé-iṣẹ́ náà níbi gbogbo.
0
Ài sùn; àiwo nì ti Baàlé, bọrọ sẹgbẹfa, ọlọrọ ni yóó tán an.
1
Ẹgbẹ́dùn ṣàpèjúwe ìgbésẹ̀ níní àmì ìdánimọ̀ tuntun náà gẹ́gẹ́ bí èyí tó tọ́ lásìkò yìí.
0
Bàbá Ìjẹ̀bú tí ń fi owó ṣàánú ti ra ọkọ̀ tuntun.
0
Ẹyìn-àmù kì í ș'elé-ìgbín.
1
Àiro òjò mọ ló mójú tìsẹlẹrú.
1
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti ka ẹ̀sùn sí Lánrewájú lẹ́sẹ̀.
0
Gẹgẹ ìyàwó ń bọ wá dẹtẹ.
1
A fẹ́ lọ ṣe ìpàdé ní ọ́fììsì mínísítà náà.
0
Mò ń gbàdúrà lọ́sàn-án àti lóru fún ààbò ikọ̀ tó ń ṣọ́ ìlú yìí.
0
Bí a kò bá rẹ́ni bá là, ọlà kì í yá.
0
4438. Ẹlẹ́nu là ń bi ká tó gbá a.
1
Bí a kò bá rẹ́ni fẹ̀hìntì bí ọ̀lẹ là ńrí; bí a kò bá rẹ́ni gbójúlé, à tẹra mọ́ṣẹ́ ẹni.
1
Àwọn ọ̀nà tí mo fi gbaradì fún Ìdíje Àgbáyé nìyìí.
0
Wọ́n ní kí Páítọ̀ náà bá ìyàwó rẹ̀ sọ̀rọ̀ lórí aago.
0
Àwọn ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ti ń ṣèwádìí tó lọ́ọ̀rìn nípa ìṣẹ̀lẹ̀ ìbànújẹ́ yìí.
0
Àwọn àgbàlagbà tí wọ́n ti pé ọdún márùndínláàádọ́rin ni ilé-ìwòsàn náà wà fún.
0
Bọ̀rọ̀kìnnín lọ̀tá ìlú; afínjú lọba ń pa.
1
Ẹni tó ń se rere, kó múra sí rere. Ẹni tó ń sèkà, k'ó múra síkà.Àtoore-àtìkà ọkan kì í gbé.
1
Bí etu bá gbofá, áá fi han ará ilé e.
1
Àwọn nnkan wo lo rò pé ó yẹ kí o mọ̀ nípa àṣà àti ìṣe Yorùbá?
0
Àwọn ọba alayé káàkiri ilẹ̀ Yorùbá ni Ajéìgbé máa ń ṣàtìlẹyìn fún .
0
Èèyàn kì í gbẹsę l'éjì l'éjì (léèkan) kó má subúlébú.
1
Àwọn méjì tí wọ́n ránṣẹ́ pè ti ń ran iṣẹ́ ìwádìí àwọn ọlọ́pàá lọ́wọ́ báyìí.
0
Abiyamọ kì í rìn kó ṣánwọ́ ahá.
1