Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
audio
audioduration (s)
1.84
20
transcription
stringlengths
21
95
Ó ti pé ọgọ́rùn-ún ọjọ́ tí ìjọba ti f'òfin de wá.
Gómìnà obìnrin ẹyọ kan péré la ti ní ní ìpínlẹ̀ Ayédé
Inú àbótí ńlá ni Àjàní kó gbogbo àwọn aṣọ rẹ̀ sí.
Kò sí ìwé ẹ̀rí fun olùdíje tí àwọn ẹgbẹ́ onígbàálẹ̀ fà kalẹ̀.
Àmọ̀tẹ́kùn ti gba àṣẹ ìdáábòbò lọ́wọ́ ìjọba.
Ọ̀gá ni Bọ́lá jẹ́ fún Bọ̀dé lágbo òṣèlú.
Àsìkò àjàkálẹ̀ ààrùn yìí jẹ́ kí n di télọ̀ tó mọṣẹ́ gidi.
Ó ṣeé ṣe kí ọdún wáyé lábẹ́ àwọn òfin tuntun nípa arùn àjàkáyé
Ọmọ àlè ti fi ilé jóná báyìí nílùú Ìbàdàn.
Àrẹ̀mú faraya lórí báwọn jàǹdùkú ṣe ń borí ọmọogun wa.
Ọ̀daràn mẹ́jọ ni wón mú ní ìlú Èrúwà lánàá.
Lọ sí ilé Délé Gíwá láti wo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ń gbé ibẹ̀.
Àjọ elétò ìlera ti ní íjọba ti ra àwọn ohun ìgbógun ti ààrùn.
Omi gbé arákùnrin ẹni ọdún mẹ́tàlá kan lọ ní Ìbàdàn
Àdúrà ò ní padà gbà mọ́ nígbà tí àbòsí bá ti pọ̀ jù.
Wo ohun tí òṣìṣẹ́ yìí ṣe tí ọ̀gá rẹ̀ fi fún ní ẹ̀bùn owó.
Agbẹjọ́rò ẹbí olóògbé Láwuyì ti yá owó ńlá kan ní báǹkì
Arákùnrin tí àwọn ọlọ́pàá mú ní òun kìí ṣe olè.
Àwọn Dókítà kan ti da iṣẹ́ sílẹ̀ nítorí àti gba owó lọ́wọ́ ìjọba
Tírélà agbépo ṣekúpa ọmọ ọdún méjì àti àwọn mẹ́ta míì
Àwọn Fúlàní ya bo ilé ìtura àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wa
Wọ́n fi Ṣàǹgó búra fún ààrẹ Nàìjíríà tuntun.
Wọ́n ti rán Adéṣọlá lọ ésí ẹ̀wọ̀n ọdún méjìlélọ́gbọ̀n
Ìyálé mi ti di ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ nínú ìlú, kò sí ẹni tó le múu
Ọkọ àti ìyàwó ti gbọ̀nà oko lọ láti àárọ̀.
Ilé ẹjọ́ gíga wọ́gilé ìyọnípò Àdìsá gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ rẹ̀.
Ẹnìkan pe àwọn wí pé ilé kan ń jó ní agbègbè náà.
Ọwá Obòkun ni orúkọ ọba ìlú Iléshà, Ajerò ni ti Ìjerò
Túndé kó sí gbaga ọlọ́pàá nítórí ikú ọmọ ọdún mẹ́wàá kan.
Ó tẹ̀síwájú pé kò sí ẹnikẹ́ni tó farapa níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
Lékan ní òun kò lérò pé òun le mókè nínú iṣẹ́ orin.
Pásítọ̀ na àwọn ọmọ ìjọ láti mọ̀ bí wọn ṣe gbóná fún Ọ́lọ́run tó.
Gómìnà Makinde bá mọ̀lẹ́bí ọkùnrin náà kẹ́dùn lọ́jọ́ náà
Ìjọba àpapọ̀ ń sọ̀rọ̀ tòótọ́ fún wa.
Ìwòsàn ló bá Kẹ́mi dáwọ́ ìtọ̀ dúró.
Túńdé pe gbogbo ẹgbẹ́ jọ láti sọ fún wọn pé kí wọ́n gbaradì.
Bí àwọn ará ìlú ṣe fara mọ́ ṣíse àbẹ́rẹ́ àjẹsára ni mo ta kò
Ẹ̀bà gígan ni Bísí jẹ sùn lánàá.
Awọn akọ́mọlédè lórílẹ̀ èdè yìí ti rọ àwọn ọmọ Yorùbá lóyè
Ẹgbẹ́ fún ìdàgbàsókè ọrọ̀ ajé ti fún àwọn obìnrin lówó níbàdàn.
Nínú Ọlọ́pàá àti ààrùn jẹjẹrẹ, èwo ló yẹ ka bẹ̀rù?
Àwọn àgbàgbà ọlọ́pàá ti ṣàánú ọmọbìnrin tí wọn gbámú
Àwọn aṣòfin ilẹ̀ Nàìjíríà ṣọ̀rọ̀ ìwúrí nípa Ajímọ̀bí.
Olórí gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹni tó lóòótọ́, tí ò ní máa ṣọ̀tún-ṣòsì.
Olúọmọ oṣòdì má gbé jàgídíjàgan wá.
Ẹ tẹ ọkùnrin tó bá fipá bá obìnrin lòpọ̀ ní ọ̀dá, ìwà ìkà ni.
Ìdí tí Ìyábọ̀ Ọbásanjọ́ fi ṣe pàtàkì ní ìpínlẹ̀ Ògùn nìyí o
Àjẹ́ ni àwọn ìyá Àjànàkú àti Àlàbí.
Mo fẹ́ bá àwọn ọmọ Ajílẹ́yẹ ṣeré fún bí ọdún mẹ́ta síi
Ikú burúkú ló pa ìyàwó Rẹ̀mí ní ìjẹrin.
Ẹni tí ò bá lérò, tí ò létò, o lè jẹ́ olórí ti wa.
Olúmidé ti rọ àwọn ènìyàn pé kí wọn má fojú òṣèlú wo àbẹ̀wò òun.
Ǹkan mẹ́ta ló fàá tí jàndùkú fi ń yìnbọn pa àwọn ọlọ́pàá
Àwọn aṣewádìí náà gbọ́dọ̀ ri pé wọ́n ṣe ìwádìí wọn fínnífínní
Wọ́n ní àwọn méjìlá ní wọ́n bódòlọ.
Adébimpé gba omijé lójú Adédiméjì.
Àwọn jàndùkú jí Rẹ̀mí gbé.
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ arákùrin ajínigbé kan ní ìlú Òṣogbo.
Bùhárí ń bèèrè fún àforíjìn gbèsè tí a jẹ lọ́dọ̀ àjọ àgbáyé
Ìpinu mi fọ́dún yìí ni láti yí padà si obìnrin pátápátá.
Àwa la gbé ìgbá orókè nínú ìdíje eré bọ́ọ̀lù ní Ìbàdàn
Bílíònú mẹ́fà ni ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti yòó ná lórí Àmọ̀tẹ́kùn.
Gómìnà Ọbásànyà yọ ọ̀gá ikọ̀ ọlọ́pàá nípò.
Adéwálé fèsì padà pé àwọn àgbààgbà tó ní owó lọ́wọ́ wà níbẹ̀.
Ṣé lóòtọ́ ni pé ilé ẹjọ́ sọ pé kí Àrẹ̀mú lọ sí ẹ̀wọ̀n.
Wo ọ̀nà láti jẹ ànfàní ìforúkọsílẹ ọ̀fẹ́ tí ìjọba gbékalẹ̀.
Sanwó Olú ti gba àwòrán apanilẹ́rín kan nílùú Èkó.
Ọwọ́ àwọn agbófinró tẹ afurasú oníjìbìtì tó lu Kẹ́mi ní jìbìtì owó.
Láàárín ìdílé ẹlẹ́ni márùn-ún yìí, ọmọ kan ṣoṣo ló léè sọ̀rọ̀.
Irọ́ ni wọn ń pa, mi ò sálọ sí sílẹ̀ òkèrè nítorí ìwọ́de.
Òtútù àsìkò yìí pọ̀ lápọ̀ jù.
Esì àyẹwò ọmọ ati ìyáwọ ọmọ Atiku ti jáde.
Wo ìkílọ̀ Ìjọba àpapọ̀, Ọlọ̀pàá àti Gómìnà Sanwó-olú.
Ààrẹ àkọ́kọ́ ní Ọ̀yọ́ jáde láyé.
Mo ní kí wọ́n yé ṣe àwáwí fún bàbá Ìjẹ̀shà fún oun tó ṣẹ
Àwọn èèyàn pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìjàmbá ọkọ ní Èkó.
Orilẹ ede Nàìjíríà ni lati ni ilọsiwaju ninu iṣẹ sinimá.
Ẹni tó fí ìbínú lu Ábúdù ọlọ́kadà pa ní Abẹ́òkuta ti sálọ.
Ayẹyẹ elégún yẹn yóò párí ní Ọjọ́ Ajé tó ń bọ̀.
Odùduwà sọ fún Oyètọ́lá nípa ọ̀gá ilé ìwé mẹ́ta tó dá dúró
Ojú ẹni máa là, á rí tó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Wọ́n ti kéde ètò ìsìnkú Ajímájàṣán àti ọjọ́ tí wọn yóò sin-ín
Adébáyò wá kábàámọ̀ pé ọ̀pọ̀ nǹkan ni wọ́n ń tọwọ́ òṣèlú bọ.
Ọdún kẹ́ta rẹ̀é ti ọkọ àti ìyàwó ò tí ì bímọ.
Ìbànújẹ́ gba ìlú kan nígbà tí àṣìta ìbọn ba ọmọ ọdún méjì kan.
Lọ́dọ̀ àwọn agbẹjọ́rò tó ń gbé Ìshẹri ni mo ti kọ́kọ́ gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀
Màmá tó jẹ́ onímọ̀ òye kọjá lọ ní àárọ̀ kùtùkùtù lánàá
Wọ́n ní kí àwọn èèyàn dẹ́kun láti máa pe àwọn obìnrin ní aṣéwó.
Àwọn ológun ti gbàjọba ní ìlú kan tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Ọya
Gómìnà Oyètọ́lá ti pè fún alàáfíà láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀
Amọ̀fin tó ń ṣáájú ikọ̀ agbẹjọ́rò fún ẹgbẹ́ náà ní ìlànà.
Iléẹjọ́ ṣe ìdájọ́ iléìfowópamọ́ lori ìwà jìbìtì.
Ọlá yóò gúnlẹ̀ sí Ọ̀yọ́ ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀.
Èmi àti Túndé ti kọ́ ẹ̀kọ́ síi nípa ààlọ́ Yorùbá
Kí lẹ̀ ń bú ààrẹ fún nítorí Ọlọ́run.
Ènìyàn mẹjọ mìíràn tún ti ní ààrùn jẹjẹrẹ ní Nàìjíríà.
Ọkùnrin nìkan náà ni ó lè wo orò ní ilẹ̀ Yorùbá.
Rẹ̀mi ti kú nípa ìkọlù tó wáyé.
Àwọn olórí Yorùbá ti ní kò ní sí ètò ìdìbò lọ́dún tó ń bọ̀.
Ìtàn málegbàgbé ni àwọn ìtàn akọni bíi Mọ́remí ní àwùjọ Yorùbá.
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
195