audio
audioduration (s)
1.84
20
transcription
stringlengths
21
95
Ọpẹ́ àtàwọn míì ti tàbùkù bá ẹgbẹ́ wa.
Gbogbo orin tó bá kọ ló má ń mi ìgboro tìtì.
Wo àwọn àkọsílẹ̀ tí a kọ sí ara ògiri lọ́nà ilé ìsìn
Títì pa ni ìlẹ̀kùn àwọn mọ́ṣáláàṣí kan wà ní ìpínlẹ̀ Eko.
Tọ́lá gba mílíọ̀nù márùn-ún lọ́wọ́ ìjọba.
Tanítólúwa àti Ọrẹolúwa ti pàdé ara wọn ní ìlú ọba
Ìyábọ̀ Òjó fi sìgá dárà ní ilé epo bẹtiró ní ìlú ìlọrin.
Pátá jíjí ti wá di iṣẹ́ fún àwọn ọ̀dọ́ tó yọ̀lẹ nítorí owó.
Àwọn aṣòfin Nàíjíríà buwọ́lu fífi èsì ìdìbò ránṣẹ lórí ayélujára.
Oríire náà kìí ṣe ti òun nìkan, ti gbogbo orílè-èdè yí ni.
Àwọn jàǹdùkú fi aṣọ bo ọkọ̀ tí wón jí gbé.
Àwọn aṣòfin àgbà ti ké pe ìjọba láti wá ńkan ṣe sí ọ̀wọ́ngógó epo
Obìnrin méjìlá ló wà lára àwọn olóògùn olóró náà.
A ní ìgbàgbọ́ pé ètò ìbò ọdún yìí yóò yàtọ̀ sí ti tẹ́lẹ̀.
Wọ́n fẹ mọ ibi tí wọ́n ti ń ṣàmótó àwọn tó ní aarun olóde.
Wọn rí ọmọ tuntun kan ní ẹ̀bá odò kan ní Ilúpéjú lọ́jọ́sí.
Ẹjọ́ ń bẹ lọ́run fún gbogbo àwọn tí kò gbọ́ràn sí Bámilóyè lẹ́nu
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ awakọ̀ èrò ṣíná ìbọn níbi ìpolongo ìbò tí ó wáyé.
Ìyábọ̀ Òjó sọ pé oun kò sí nílé nígbà ìṣẹ̀lẹ̀ yìí