eng
stringlengths 1
539
| yor
stringlengths 2
509
|
---|---|
How heartwarming it is to hear today not only such names as Mary , John , Stephen , and Tom but also such names as Mamadou , Jegan , Reza , and Chan !
|
Ẹ wo bó ṣe ń múnú wa dùn tó lóde oní láti máa gbó ̣ àwọn orúkọ tí kì í ṣe Mary , John , Stephen , àti Tom nìkan , àmó ̣ tá a tún ń gbó ̣ àwọn orúkọ mìíràn bíi Mamadou , Jegan , Reza , àti Chan !
|
What a shock those attacks were for the whole country !
|
Ẹ wo ìpayà ńlán ̀ là tí àjálù wò ̣ nyẹn kó bá gbogbo orílè ̣ - èdè náà !
|
What a comforting thought that is !
|
Ẹ ò rí i pé èyí fini ló ̣ kàn balè ̣ !
|
How timely this advice is for us , since we live in a materialistic world where the emphasis is on gaining wealth by any means and at any cost !
|
Ẹ ò rí i pé ìmò ̣ ràn yìí bá a mu wé ̣ kú fún wa , níwò ̣ n bó ti jé ̣ pé inú ayé onífè ̣ é ̣ ọrò ̣ àlùmó ̣ ó ̣ nì là ń gbé , tó jé ̣ pé ò ̣ rò ̣ nípa bí wó ̣ n ṣe máa di ọló ̣ rò ̣ ló ̣ nàkọnà ni wó ̣ n ń tẹnu mó ̣ ṣáá !
|
No wonder the four Hebrews would not partake of the king 's delicacies !
|
Ẹ ò rí i pé ó tó ̣ bí àwọn ọmọ Hébérù mé ̣ rè ̣ è ̣ rin yìí ṣe kò ̣ tí wọn ò jẹ àwọn oúnjẹ adùnyùngbà ọba !
|
What a clever strategy !
|
Ẹ ò rí i pé ọgbó ̣ n gidi nìyẹn !
|
NE . ST . PETERSBURG , FL , Bayfront Center , 400 1st St . S .
|
ẸNÚGU 3 ( Gè ̣ é ̣ sì )
|
What about the billions of innocent people who have died since the rebellion in Eden ?
|
Ẹgbàágbèje àwọn aláìmọwó ̣ mẹsè ̣ èèyàn tó ti kú látìgbà ò ̣ tè ̣ tó wáyé ní Édé ̣ nì yẹn wá ńkó ̣ ?
|
Storm troopers closed down the office in Magdeburg and banned our meetings .
|
Ẹgbé ̣ ogun Násì lọ ti Bé ̣ té ̣ lì tó wà ní Magdeburg pa , wó ̣ n ní a ò gbó ̣ dò ̣ ṣe ìpàdé kankan .
|
A land of thick jungles , rugged mountains , and mighty rivers , Borneo is home to Chinese , Muslim Malays , and the indigenous Dayak - a largely river - dwelling people who were at one time fierce headhunters .
|
Ẹkùn ilè ̣ Borneo kún fún igbó kìjikìji , òkè gbágungbàgun àtàwọn odò ńláńlá , àwọn tó ń sọ èdè Chinese , àwọn ẹlé ̣ sìn Mùsùlùmí tó ń sọ èdè Malays àtàwọn Dayak tó jé ̣ ọmọ ìbílè ̣ ló sì pò ̣ jù níbè ̣ .
|
Another person decides that all days are the same .
|
Ẹlomiran ka gbogbo ọjó ̣ bákan náà .
|
Antonio , who lost his father in a road accident , explains : " It is like somebody sealing up your house and taking away the keys .
|
Ẹni tó bá kàn ló mò ̣ . Ò ̣ gbé ̣ ni kan tó ń jé ̣ Antonio , tí bàbá rè ̣ kú nínú ìjàn ̀ bá ọkò ̣ , ṣàpèjúwe bó ṣe rí lára rè ̣ , ó ní : " Ńṣe ló dà bí ìgbà tí ìjọba gbé ̣ sè ̣ lé ilé tí ẹnì kan ń gbé , tí wó ̣ n sì tì í pa .
|
Such thinking does not take God 's love and wisdom into account .
|
Ẹni tó bá ń ronú bé ̣ è ̣ ò gbà pé Ọló ̣ run ní ìfé ̣ àti ọgbó ̣ n .
|
The central historical figure in the outworking of God 's will is Jesus Christ , and when people study the Bible with Jehovah 's Witnesses , they learn a lot about him .
|
Ẹni tó jé ̣ òpómúléró nínú mímú ìfé ̣ Ọló ̣ run ṣẹ ni Jésù Kristi , táwọn èèyàn bá sì ké ̣ kò ̣ ó ̣ Bíbélì ló ̣ dò ̣ àwọn Ẹlé ̣ rìí Jèhófà , ohun púpò ̣ ni wó ̣ n máa ń kó ̣ nípa rè ̣ .
|
Second only to Jehovah , Christ Jesus set a fine example of long - suffering .
|
Ẹnì kan tó tún fi àpẹẹrẹ àtàtà lórí ìpamó ̣ ra lélè ̣ lé ̣ yìn ti Jèhófà ni Kristi Jésù .
|
" Newspapers should report on what you people are accomplishing here , " exclaimed one observer .
|
Ẹnì kan tó ń wò wó ̣ n bí wó ̣ n ṣe ń ṣiṣé ̣ náà sọ pé : " Ó yẹ kí àwọn ìwé ìròyìn jé ̣ kí aráyé mọ ohun tí è ̣ yin èèyàn wò ̣ nyí ń ṣe níbí . "
|
We immediately started to learn Luganda , a language with a beautiful songlike quality but very difficult to learn .
|
Ẹsè ̣ kẹsè ̣ la bè ̣ rè ̣ sí í kó ̣ èdè Luganda tó jé ̣ èdè tó máa ń dún bí orin , àmó ̣ ó ṣòro kó ̣ .
|
We read : " Well , when they heard of a resurrection of the dead , some began to mock , while others said : ' We will hear you about this even another time . ' " - Acts 17 : 29 - 32 .
|
Ẹsẹ náà kà pé : " Tóò , nígbà tí wó ̣ n gbó ̣ nípa àjín ̀ de àwọn òkú , àwọn kan bè ̣ rè ̣ sí ṣe ẹlé ̣ yà , nígbà tí àwọn mìíràn wí pé : ' Dájúdájú , àwa yóò gbó ̣ ò ̣ rò ̣ rẹ nípa èyí àní ní ìgbà mìíràn . ' " - Ìṣe 17 : 29 - 32 .
|
Henry VIII : Painting in the Royal Gallery at Kensington , from the book The History of Protestantism ( Vol . I )
|
Ọba Henry Kẹjọ : Àwòrán tí ń bẹ ní Royal Gallery nílùú Kensington , látinú ìwé náà , The History of Protestantism , ( Apá Kìíní )
|
A king will reign for righteousness itself ; and as respects princes , they will rule as princes for justice itself . "
|
Ọba kan yóò jẹ fún òdodo ; àti ní ti àwọn ọmọ aládé , wọn yóò ṣàkóso bí ọmọ aládé fún ìdájó ̣ òdodo . "
|
He was a king in Bible times .
|
Ọba ni ní àwọn àkókò tí a kọ Bíbélì .
|
Baptized in 1921 , Brother Barber has spent 78 years in the full - time ministry and has been a member of the Governing Body since 1978 .
|
Ọdún 1921 ni Arákùnrin Barber ṣèrìbọmi . Ó sì ti lo ọdún méjìdínló ̣ gó ̣ rin nínú iṣé ̣ òjíṣé ̣ alákòókò kíkún .
|
Missionaries arrived in 1987 and worked along with the only congregation in Conakry .
|
Ọdún 1987 làwọn míṣó ̣ nnárì dé ilè ̣ náà , ìjọ kan ṣoṣo tó wà ní Conakry ni wó ̣ n sì ń dara pò ̣ mó ̣ .
|
When applied , the Bible 's wisdom is " a tree of life to those who take hold of it , and those who keep firm hold of it will be called happy . "
|
Ọgbó ̣ n tó wà nínú Bíbélì máa ń " jé ̣ igi ìyè fún àwọn tí ó dì í mú , àwọn tí ó sì dì í mú ṣinṣin ni a ó pè ní aláyò ̣ " kìkì tí wó ̣ n bá ń fi ìmò ̣ ràn rè ̣ sílò .
|
The first man , Adam , lived for centuries .
|
Ọgó ̣ rò ̣ ò ̣ rún ọdún ni ọkùnrin àkó ̣ kó ̣ náà , Ádámù lò láyé .
|
Over the years , skeptics have challenged - and continue to challenge - the Bible 's accuracy regarding the names of people and places it mentions .
|
Ọjó ̣ pé ̣ táwọn tó ń ṣe lámèyító ̣ Bíbélì ti ń kọminú sórúkọ àwọn èèyàn àti orúkọ àwọn àdúgbò tí Bíbélì mé ̣ nu kàn , wọn ò sì tíì jáwó ̣ nínú ṣíṣe bé ̣ è ̣ .
|
The times when I served as a waiter in a hotel are long gone .
|
Ọjó ̣ pé ̣ tí mo ti fi iṣé ̣ ká máa gbé oúnjẹ fúnni ní òté ̣ è ̣ lì sílè ̣ .
|
Days and weeks passed .
|
Ọjó ̣ ń gorí ọjó ̣ , ò ̣ sè ̣ ń gorí ò ̣ sè ̣ .
|
My father died of cancer .
|
Ọkàn mi gbọgbé ̣ .
|
George lives in the United States and has been married for 59 years .
|
Ọkùnrin kan tó ń jé ̣ George tó ń gbé ní orílè ̣ - èdè Amé ̣ ríkà ti ṣègbéyàwó ló ̣ dún mó ̣ kàndínló ̣ gó ̣ ta sé ̣ yìn .
|
A man named Troy , who was hooked on Internet pornography , says : " I fought to purge wrong thoughts from my mind by focusing on positive thoughts instead .
|
Ọkùnrin kan tó ń jé ̣ Troy tí wíwo àwòrán ìṣekúṣe lórí Íńtáné ̣ è ̣ tì ti di bárakú fún sọ pé : " Ńṣe ni mo máa ń jìjàkadì kí n lè fọ àwọn èrò ìṣekúṣe kúrò nínú ọpọlọ mi .
|
It was reaped by three men , each with his own scythe and basket . "
|
Ọkùnrin mé ̣ ta ló máa ń lọ gé e wá , kálukú tòun ti dòjé àti apè ̣ rè ̣ rè ̣ . "
|
magazines and wants more literature to read during the winter months .
|
Ọkùnrin míì náà fé ̣ gba àwọn ìwé wa tí yóò máa kà , ó sì tún fé ̣ gba àwọn tó máa kó sí ibi tó ti ń tajà kí àwọn oníbàárà rè ̣ lè máa kà wó ̣ n .
|
Mates feel betrayed .
|
Ọkọ tàbí aya irú ẹni bé ̣ è ̣ á máa wò ó pé ó ń da òun .
|
His mate may no longer trust him , his children may already be hampered emotionally , and his health may be ruined .
|
Ọkọ tàbí aya è ̣ lè má gbà á gbó ̣ mó ̣ , ìdààmú ọkàn lè ti sọ àwọn ọmọ è ̣ dìdàkudà , kí ròkè rodò sì ti sọ òun náà di aláìlera .
|
Wise King Solomon aptly explained : " He that is showing favor to the lowly one is lending to Jehovah , and his treatment He will repay to him . "
|
Ọló ̣ gbó ̣ n Ọba Sólómó ̣ nì ṣàlàyé tó bá a mú gé ̣ lé ̣ , ó ní : " Ẹni tí ń fi ojú rere hàn sí ẹni rírẹlè ̣ , Jèhófà ni ó ń wín , òun yóò sì san ìlòsíni rè ̣ padà fún un . "
|
God " has established the earth on its foundations ; it will not be moved from its place forever and ever . " - Psalm 104 : 5 .
|
Ọló ̣ run " fi ìpìlè ̣ ayé sọlè ̣ sórí àwọn ibi àfìdímúlè ̣ rè ̣ ; a kì yóò mú kí ó ta gbò ̣ n - ó ̣ n gbò ̣ n - ó ̣ n fún àkókò tí ó lọ kánrin , tàbí títí láé . " - Sáàmù 104 : 5 .
|
" The Sacred Secret " Progressively Revealed
|
Ọló ̣ run Bè ̣ rè ̣ Sí Í Ṣí " Àṣírí Ọló ̣ wò ̣ " Náà Payá Díè ̣ díè ̣
|
God will use Jesus to undo the evil that Satan has done . - Read 1 John 3 : 8 .
|
Ọló ̣ run máa lo Jésù láti tún gbogbo nn ̀ kan tí Sátánì ti bàjé ̣ ṣe . - Ka 1 Jòhánù 3 : 8 .
|
The mistreatment of women certainly does not please God .
|
Ọló ̣ run máa ń pó ̣ n àwọn obìnrin lé , kì í sì í fi è ̣ tó ̣ wọn dù wó ̣ n .
|
God took my only girl .
|
Ọló ̣ run pa ọmọbìnrin kan ṣoṣo tí mo bí .
|
He reaches down , as it were , to deal kindly with God - fearing ones . - 11 / 1 , pages 4 - 5 .
|
Ọló ̣ run rẹ ara rè ̣ sílè ̣ ló ̣ nà ìṣàpẹẹrẹ , kó bàa lè fìfé ̣ bá àwọn tó bè ̣ rù rè ̣ lò . - 11 / 1 , ojú ìwé 4 àti 5 .
|
God said : " When you eventually come into the land that Jehovah your God is giving you , . . . and you have said , ' Let me set a king over myself like all the nations who are round about me ' ; you should without fail set over yourself a king whom Jehovah your God will choose . . . .
|
Ọló ̣ run sọ pé : " Lé ̣ yìn - ò ̣ - rè ̣ yìn , nígbà tí o bá dé sí ilè ̣ tí Jèhófà Ọló ̣ run rẹ yóò fi fún ọ , . . . tí o sì wí pé , ' Jé ̣ kí ń yan ọba kan lé ara mi lórí , bí ti gbogbo orílè ̣ - èdè tí ó yí mi ká ' ; ọba tí Jèhófà Ọló ̣ run rẹ yóò yàn ni kí ìwọ yàn lé ara rẹ lórí láìkùnà . . . .
|
Yes , God put in Moses ' hand the means by which he could prove that his message was from Jehovah .
|
Ọló ̣ run tipa bé ̣ è ̣ fi ohun tí Mósè máa fi mú káwọn èèyàn mò ̣ pé Jèhófà ló rán an lé e ló ̣ wó ̣ .
|
The true God gave righteous Noah explicit instructions on how to build an ark for the preservation of life through a global flood .
|
Ọló ̣ run tòótó ̣ sọ fún Nóà olódodo pé kó kan ọkò ̣ áàkì láti dáàbò bo àwọn è ̣ dá ẹlé ̣ mìí nígbà tí omi bá bo gbogbo ayé , ó sì sọ kúlè ̣ kúlè ̣ bó ṣe máa kan ọkò ̣ náà fún un .
|
So God said of that corrupt society : " I am bringing them to ruin . "
|
Ọló ̣ run wá sọ nígbà yẹn pé : " Èmi yóò run wó ̣ n , " ìyẹn àwọn èèyàn burúkú .
|
God promises us that he is on our side .
|
Ọló ̣ run ṣèlérí fún wa pé òun wà pè ̣ lú wa .
|
In the Ras Shamra texts , Baal is called the son of Dagan , but the meaning of " son " here is uncertain .
|
Ọmọ Báálì ni wó ̣ n pe Dagan nínú àwọn ìwé Ras Shamra , àmó ̣ ohun tí " ọmọ " túmò ̣ sí níhìn - ín kò fi bé ̣ è ̣ dáni lójú .
|
Humans have pondered such questions for thousands of years .
|
Ọmọ aráyé ti ń ronú lórí irú àwọn ìbéèrè bí èyí láti ẹgbẹẹgbè ̣ rún ọdún sé ̣ yìn .
|
I was 16 years old and had accompanied my parents to a religious meeting in Eindhoven , a city in the province of Brabant , in the Netherlands .
|
Ọmọ ọdún mé ̣ rìndínlógún ni mí nígbà náà , mo sì tè ̣ lé àwọn òbí mi lọ sí ìpàdé ìsìn kan nílùú Eindhoven , tó wà ní ẹkùn Brabant , ní orílè ̣ - èdè Netherlands .
|
Granddaughter
|
Ọmọ ọmọ
|
Profuse thanks , therefore , to the international , multilingual ' great crowd ' for the overwhelming part that they have played in the fulfilling of [ Jesus ' ] prophecy at Matthew 24 : 14 ! "
|
Ọpẹ gidigidi ni , nigba naa , fun ' ogunlọgọ nla ' elédè ahọn pupọ naa jakejado awọn orilẹ - ede fun ipa ribiribi ti wọn ti sà ní mimu asọtẹlẹ [ Jesu ] ninu Matteu 24 : 14 ṣẹ ! "
|
They place a high value on spiritual things .
|
Ọwó ̣ tó ṣe pàtàkì ni wó ̣ n fi ń mú ò ̣ ràn ìjọsìn .
|
What can others do to help fellow believers who live in religiously divided households ?
|
․ ․ ․ ․ ․ Kí la lè ṣe láti ran àwọn tá a jọ jé ̣ Kristẹni àmó ̣ tí wó ̣ n wà nínú ìdílé tí wó ̣ n ti ń ṣe è ̣ sìn ò ̣ tò ̣ ò ̣ tò ̣ ló ̣ wó ̣ ?
|
▪ Text - to - Self How does this information relate to my circumstances , my culture , my dilemmas ?
|
▪ Wo Ibi Tó Ti Kan Ìwọ Alára Báwo ni ò ̣ rò ̣ yìí ṣe bá mi mu , báwo ló ṣe bá àṣà ìbílè ̣ mi mu , báwo ló sì ṣe bá ìṣòro mi mu ?
|
effectively communicate with others
|
▪ mọ bó ṣe yẹ kó máa ṣó ̣ wó ná
|
▪ Pornography demeans both those who produce it and those who look at it . - 1 Thessalonians 4 : 3 - 5 .
|
▪ Àwòrán oníhòòhò ń tàbùkù sáwọn tó ń ṣe é àtàwọn tó ń wò ó . - 1 Tẹsalóníkà 4 : 3 - 5 .
|
" Sometimes because of my hectic schedule , prayer gets pushed aside . " - Preeti , 20 , Britain .
|
▪ Ìṣòro : ÀÌKA NN ̀ KAN SÍ . " Nígbà míì , torí pé mo ní ò ̣ pò ̣ nn ̀ kan láti ṣe , mo máa ń gbàgbé láti gbàdúrà . " - Preeti , ọmọ ogún ọdún láti ilè ̣ Gè ̣ é ̣ sì .
|
" I lose my concentration , and my mind seems to be on everything except what I 'm saying . " - Pamela , 17 , Mexico .
|
▪ Ìṣòro : ÌPÍNYÀ ỌKÀN . " Mi kì í pọkàn pò ̣ bí mo bá ń gbàdúrà , àwọn nn ̀ kan míì ni mo máa ń rò dípò kí n fọkàn sí ohun tí mò ń sọ . " - Pamela , ọmọ ọdún mé ̣ tàdínlógún [ 17 ] láti orílè ̣ - èdè Mé ̣ síkò .
|
● " If , then , you are bringing your gift to the altar and you there remember that your brother has something against you , leave your gift there in front of the altar , and go away ; first make your peace with your brother , and then , when you have come back , offer up your gift . " - Matthew 5 : 23 , 24 ; Ephesians 4 : 26 .
|
● " Nígbà náà , bí ìwọ bá ń mú è ̣ bùn rẹ bò ̣ níbi pẹpẹ , tí o sì rántí níbè ̣ pé arákùnrin rẹ ní ohun kan lòdì sí ọ , fi è ̣ bùn rẹ sílè ̣ níbè ̣ níwájú pẹpẹ , kí o sì lọ ; kó ̣ kó ̣ wá àlàáfíà , ìwọ pè ̣ lú arákùnrin rẹ , àti lé ̣ yìn náà , nígbà tí o bá ti padà wá , fi è ̣ bùn rẹ rúbọ . " - Mátíù 5 : 23 , 24 ; Éfésù 4 : 26 . Àn ̀ fààní Wà Nínú Níní Alábàágbéyàrá
|
A former Russian republic uses the most , averaging over 1.4 million gallons of water [ 5.3 million liters ] per person annually .
|
● Ibi tá a lè kà sí ilè ̣ ò ̣ gbìn ní orílè ̣ - èdè kan ni fífè ̣ ilè ̣ tí wó ̣ n nílò láti gbin gbogbo ohun tí wó ̣ n ń jẹ sí .
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.