Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
eng
stringlengths
1
539
yor
stringlengths
2
509
We do not guarantee the accuracy , completeness , or usefulness of any information on the service .
A kò lè fọwó ̣ sò ̣ yà pé ohun tá a bá kà lórí Íńtáné ̣ è ̣ tì jóòótó ̣ délè ̣ délè ̣ tàbí pé ó ṣeé mú lò .
The Unclean One Will Not Pass Over It
Aláìmó ̣ Kì Yóò Gbà Á Kọjá
The person who proudly proclaims ' Oh , I listen to the music , but it doesn 't affect me ' is either hopelessly naive or grossly ill informed
Bí ẹnì kan bá ń fó ̣ nnu pé , ' Ní tèmi o , mo máa ń gbó ̣ orin dáadáa , àmó ̣ kì í nípa kankan lórí mi , ' á jé ̣ pé onítò ̣ hún kò mọ ohun tó ń sọ tàbí pé kò dákan mò ̣ rárá
Welcome Home , Son !
Káàbò ̣ Ọmọ Mi !
I HAVE often had the unreasoning fear that I would prove unfaithful to Jehovah .
MO SÁBÀ máa ń ní ìbè ̣ rù tí kò tó ̣ pé mo máa ṣe ohun tí Jèhófà kò fé ̣ .
I am not good enough .
Mi ò kúnjú ìwò ̣ n tó .
Our Brothers Were There
Àwọn Ará Wa Dúró Tì Wá Gbágbáágbá
Better is a handful of rest than a double handful of hard work and striving after the wind .
È ̣ kúnwó ̣ kan ìsinmi sàn ju è ̣ kúnwó ̣ méjì iṣé ̣ àṣekára àti lílépa è ̣ fúùfù .
The Spirit and the Bride Keep On Saying : ' Come ! '
È ̣ mí Àti Ìyàwó Ń Bá A Nìṣó Ní Sísọ Pé : ' Máa Bò ̣ ! '
This Means Everlasting Life
Èyí Túmò ̣ Sí Ìyè Àìnípè ̣ kun
Slave for Jehovah
Ẹ Máa Sìnrú fún Jèhófà
Draw Close to God , and He Will Draw Close to You
Ẹ Sún Mó ̣ Ọló ̣ run , Yóò Sì Sún Mó ̣ Yín
" Your Father who is in the heavens . . . makes his sun rise on both the wicked and the good and makes it rain on both the righteous and the unrighteous . " - Matthew 5 : 45 .
" Baba yín tí ń bẹ ní ò ̣ run . . . ń mú kí oòrùn rè ̣ ràn sórí àwọn ènìyàn burúkú àti rere , tí ó sì ń mú kí òjò rò ̣ sórí àwọn olódodo àti aláìṣòdodo . " - Mátíù 5 : 45 .
" If you , although being wicked , know how to give good gifts to your children , how much more so will the Father in heaven give holy spirit to those asking him ! " - LUKE 11 : 13 .
" Bí è ̣ yin , tí ẹ tilè ̣ jé ̣ ẹni burúkú , bá mọ bí ẹ ṣe ń fi è ̣ bùn rere fún àwọn ọmọ yín , mélòómélòó ni Baba tí ń bẹ ní ò ̣ run yóò fi è ̣ mí mímó ̣ fún àwọn tí ń béèrè ló ̣ wó ̣ rè ̣ ! " - LÚÙKÙ 11 : 13 .
" Safeguard your heart , " and never become a slave of the Internet . - Proverbs 4 : 23 .
" Fi ìṣó ̣ ṣó ̣ ọkàn - àyà rẹ , " má sì sọ ara rẹ di ẹrú Íńtáné ̣ è ̣ tì . - Òwe 4 : 23 .
" Be modest in walking with your God . " - MICAH 6 : 8 .
" Jé ̣ ẹni tí ó mè ̣ tó ̣ mò ̣ wà ní bíbá Ọló ̣ run rẹ rìn . " - MÍKÀ 6 : 8 .
" From infancy " Timothy was trained in " the holy writings " by his mother , Eunice , and his grandmother Lois .
" Láti ìgbà ọmọdé jòjòló " ni ìyá Tímótì , ìyẹn Yùníìsì àti ìyá rè ̣ àgbà Ló ̣ ìsì ti kó ̣ ọ ní " ìwé mímó ̣ . "
" Picturesque " is the word that best expresses my first impression of Sierra Leone , with its many hills and mountains , bays and beaches .
" Orílè ̣ - èdè ẹlé ̣ wà " ni gbólóhùn tí mo lè lò láti ṣàpèjúwe bí ilè ̣ Sierra Leone ṣe rí lójú mi nígbà tí mo kó ̣ kó ̣ débè ̣ .
" Teach children how they should live , and they will remember it all their life . " - Proverbs 22 : 6 , Good News Translation
" Tó ̣ ọmọdékùnrin ní ìbámu pè ̣ lú ò ̣ nà tí yóò tò ̣ ; nígbà tí ó bá dàgbà pàápàá , kì yóò yà kúrò nínú rè ̣ . " - Òwe 22 : 6
Serving Jehovah - Honor and Privilege ( Z .
" Àjín ̀ de Èkíní " Ti Ń Lọ Ló ̣ wó ̣ !
The " other sheep " " go with " the spiritual Israelites in the work of preaching the good news of the Kingdom .
" Àwọn àgùntàn mìíràn " ń " bá " àwọn Ísíré ̣ lì tè ̣ mí " lọ " ní ti pé wó ̣ n ń ló ̣ wó ̣ sí iṣé ̣ ìwàásù ìhìn rere Ìjọba Ọló ̣ run .
" Anger " is a term used to describe a strong emotion or reaction of displeasure .
" Ìbínú " ni ò ̣ rò ̣ tá a fi ń ṣàpèjúwe bí nn ̀ kan ṣe máa ń rí lára èèyàn nígbà tí wó ̣ n bá sọ kòbákùngbé ò ̣ rò ̣ síni .
" But then , " he says , " a new game came out that I had looked forward to for a long time .
" Ṣùgbó ̣ n , " gé ̣ gé ̣ bó ṣe sọ , " lé ̣ yìn ìyẹn ni wó ̣ n gbé eré ìdárayá tuntun tí mo ti ń wò ̣ nà fún tipé ̣ tipé ̣ jáde .
" But become kind to one another , tenderly compassionate , freely forgiving one another . " - 4 : 32 .
" Ṣùgbó ̣ n kí ẹ di onínúrere sí ara yín lé ̣ nì kìíní - kejì , ní fífi ìyó ̣ nú oníjè ̣ lé ̣ ńké ̣ hàn , kí ẹ máa dárí ji ara yín fàlàlà . " - 4 : 32 .
" Make sure of the more important things . " - PHIL .
" Ẹ . . . máa wádìí dájú àwọn ohun tí ó ṣe pàtàkì jù . " - FÍLÍ .
Jehovah is " the happy God , " and he wants you to be happy too .
" Ọló ̣ run aláyò ̣ " ni Jèhófà , ó sì fé ̣ kíwọ náà láyò ̣ .
" God is a Spirit . " - John 4 : 24 .
" Ọló ̣ run jé ̣ È ̣ mí . " - Jòhánú 4 : 24 .
" Alcohol kills 55,000 youths per year , " reports the French daily Le Figaro .
" Ọtí líle ń ṣekú pa ẹgbè ̣ rún márùnléláàádó ̣ ta ò ̣ dó ̣ ló ̣ dún " lohun tí ìwé ìròyìn Le Figaro ti ilè ̣ Faransé sọ .
WE NEED to be struggling . . . for hearts and minds .
' IṢÉ ̣ kékeré kó ̣ ló máa gbà kéèyàn tó lè yí ìrònú àti ìmò ̣ lára àwọn apániláyà pa dà . '
' What is pursued ' may also apply to the righteous , who are often pursued by the wicked .
' Ohun tí a ń lépa ' tún lè tó ̣ ka sí àwọn olódodo , táwọn ẹni ibi sábà máa ń lépa .
Preaching Especially Memorable ( Mexico ) , 4 / 15
' Rí Olùkó ̣ ni , ' ' gbó ̣ ò ̣ rò ̣ lé ̣ yìn ' , 2 / 15
" Woe for the earth " came when World War I broke out in 1914 and brought to an end an era of standards very different from those of today .
' Ègbé dé bá ilè ̣ ayé ' nígbà tí Ogun Àgbáyé Kìíní bé ̣ sílè ̣ ló ̣ dún 1914 , tó sì mú òpin dé bá sànmánì ìlànà ìwà híhù tó yàtò ̣ gan - an sí ti òde òní .
What agreement does God 's temple have with idols ? . . .
' Ìfohùnṣò ̣ kan wo sì ni té ̣ ńpìlì Ọló ̣ run ní pè ̣ lú àwọn òrìṣà ? . . .
' Do I set aside time for preparing for Christian meetings ?
' Ṣé mo ti wá àkókò tí màá fi máa múra sílè ̣ fún àwọn ìpàdé ìjọ ?
Finding Beneficial Counsel , 8 / 15
' Ẹ Lọ , Kí Ẹ Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ È ̣ yìn ' 7 / 1
Waiting Attitude , 10 / 1
' Ẹ máa wínni láìretí ohunkóhun padà ' , 10 / 15
( 2 ) He revealed his status to avoid a scourging in Jerusalem .
( 2 ) Ó jé ̣ káwọn èèyàn mò ̣ pé òun jé ̣ ọmọ ìbílè ̣ Róòmù kí wó ̣ n má bàa nà án lé ̣ gba ní Jerúsálé ̣ mù .
Feel Misunderstood ?
( Dá 9 : 24 ) , 5 / 15
( Compare Isaiah 32 : 1 , 2 . )
( Fi wé Aísáyà 32 : 1 , 2 . )
( Read 1 Corinthians 7 : 32 - 35 . )
( Ka 1 Kó ̣ ríńtì 7 : 32 - 35 . )
( Read Isaiah 1 : 18 . )
( Ka Aísáyà 1 : 18 . )
( Read Hebrews 3 : 12 . )
( Ka Hébérù 3 : 12 . )
( Read John 12 : 34 . )
( Ka Jòhánù 12 : 34 . )
( Read Revelation 21 : 3 - 6 . )
( Ka Ìṣípayá 21 : 3 - 6 . )
( See verse 10 . )
( Ka ẹsẹ 10 . )
Jehovah directs his power in a controlled way .
( Kíróníkà 16 : 9 ) Jèhófà máa ń lo agbára rè ̣ ló ̣ nà tó ṣeé ṣàkóso .
( See the box " Memorial 2014 . " )
( Wo àpótí náà , " Ìrántí Ikú Kristi Ló ̣ dún 2014 . " )
( a ) In many cultures , what sexual practices became a way of life ?
( a ) Irú ìwà wo ló ti di bárakú láwọn ilè ̣ kan ?
( b ) In the ministry , how can we demonstrate our concern for foreigners ?
( b ) Báwo la ṣe lè fi hàn pé ò ̣ rò ̣ àwọn ará ilè ̣ òkèèrè jẹ wá lógún lé ̣ nu iṣé ̣ òjíṣé ̣ wa ?
( b ) What will we consider in the next article ?
( b ) Kí la máa gbé yè ̣ wò nínú àpilè ̣ kọ tó tè ̣ lé èyí ?
( b ) What reasons do we have for joy when viewing the overall report of our preaching activity ?
( b ) Kí làwọn ohun tó máa ń múnú wa dùn nígbà tá a bá ń wo àpapò ̣ ìròyìn iṣé ̣ ìwàásù wa ?
( b ) What will motivate us to apologize ?
( b ) Kí ló máa sún wa láti tọrọ àforíjì ?
( b ) What precedent for handling rebels had Jehovah set centuries earlier ?
( b ) Kí ni Jèhófà ṣe nípa ìdìtè ̣ tó wáyé rí ló ̣ pò ̣ ọdún sé ̣ yìn tó jé ̣ ká mọ ọwó ̣ tó fi ń mú irú ìwà bé ̣ è ̣ ?
( b ) What do the words of Matthew 11 : 27 - 29 reveal about Jehovah and Jesus ?
( b ) Kí ni àwọn ò ̣ rò ̣ tó wà nínú Mátíù 11 : 27 - 29 fi hàn nípa Jèhófà àti Jésù ?
( b ) Why are we interested in knowing how to pray ?
( b ) Kí nìdí tá a fi fé ̣ láti mọ bí a ó ṣe máa gbàdúrà ?
( b ) What steps must we take prior to baptism ?
( b ) Àwọn nn ̀ kan wo la gbó ̣ dò ̣ ṣe ká tó ṣèrìbọmi ?
( b ) To whom is the following article addressed , and to whom is it also of interest ?
( b ) Àwọn wo ni àpilè ̣ kọ tó kàn yóò bá sò ̣ rò ̣ , àwọn wo ni yóò sí tún jàn ̀ fààní nínú rè ̣ ?
( b ) What pertinent questions will we consider ?
( b ) Àwọn ìbéèrè pàtàkì wo ló yẹ ká gbé yè ̣ wò ?
* - 1 Corinthians 2 : 1 - 5 ; 4 : 1 .
* - 1 Kó ̣ ríńtì 2 : 1 - 5 ; 4 : 1 .
* - Mark 12 : 17 ; Titus 3 : 1 , 2 .
* - Máàkù 12 : 17 ; Títù 3 : 1 , 2 .
* You are not likely to be aware of those battles because your immune system repels or destroys most of the invaders before the onset of symptoms .
* A kì í mò ̣ tí àwọn nn ̀ kan yìí bá ń ṣẹlè ̣ nínú ara wa , torí pé kí àwọn májèlé yìí tó dá àìsàn sí wa lára ni àwọn ohun tó ń gbógun ti àrùn á ti mú wọn kúrò .
* After the water content is reduced to less than 18 percent , the cells are capped with a thin layer of wax .
* Bí omi tó wà nínú è ̣ bá ti dín kù dé nn ̀ kan bí ìdá márùn - ún , àwọn kòkòrò náà á fi ìda oyin fé ̣ lé ̣ fé ̣ lé ̣ bo afárá onígun mé ̣ fà - mé ̣ fà náà .
* When Frank complained about the noise , Jerry took offense at his manner .
* Frank lọ bá a pé ariwo wọn ti pò ̣ jù , ni Jerry bá da ò ̣ rò ̣ náà sí ìbínú , ó ní kò yẹ kó bá òun sò ̣ rò ̣ bé ̣ è ̣ .
* But the error of a few scholars pales in comparison to a much larger , more pervasive one .
* Nítorí náà , àṣìṣe àwọn ò ̣ mò ̣ wé kan kò tó nn ̀ kan kan rárá lé ̣ gbè ̣ é ̣ ti àwọn alátakò Bíbélì àti ti àwọn aṣáájú ìsìn .
* The 36 - square - mile [ 93 - sq - km ] island got that name from a famous 18th - century novel entitled Robinson Crusoe , written by the English author Daniel Defoe .
* Robinson Crusoe , ìwé ìtàn àròsọ olókìkí kan tí Daniel Defoe , gbajúmò ̣ òn ̀ kò ̣ wé ọmọ ilè ̣ Gè ̣ é ̣ sì nì kọ ní ò ̣ rúndún kejìdínlógún , ni orúkọ tí a fi sọ erékùṣù náà tó jé ̣ kìlómítà mé ̣ tàléláàádó ̣ rùn - ún níbùú lóròó .
* Some said that the garden sat atop an extremely high mountain that reached just above the confines of this degraded planet ; others , that it was at the North Pole or the South Pole ; still others , that it was on or near the moon .
* Àwọn kan sọ pé orí òkè kan tó ga gan - an ni ọgbà náà wà , tí ayé ẹlé ̣ ṣè ̣ yìí kò fi lè kó è ̣ gbin bá a , àwọn míì sọ pé , ọgbà náà wà ní ìhà Ìpè ̣ kun Àríwá ayé tàbí ìhà Ìpè ̣ kun Gúúsù ayé , àwọn míì tún sọ pé , orí òṣùpá tàbí ìtòsí rè ̣ ni ọgbà náà wà .
* What contempt Abram must have felt for these gifts !
* È ̣ bùn wò ̣ nyẹn ò tiè ̣ ní jọ Ábúrámù lójú rárá !
* God 's sovereignty toward our globe began to be asserted anew with the installation of Jesus Christ as heavenly King in the year 1914 .
* Ìṣàkóso Ọló ̣ run lórí ayé tá a sọ yìí pa dà bè ̣ rè ̣ lákò ̣ tun nígbà tí Ọló ̣ run fi Jésù Kristi jẹ ọba ní ò ̣ run ló ̣ dún 1914 .
* However , once the Christian congregation was established , Jesus ' direction would have application therein .
* Ṣùgbó ̣ n nígbà tá a dá ìjọ Kristẹni sílè ̣ lé ̣ yìn náà , àwọn tó wà nínú ìjọ náà ni ò ̣ rò ̣ náà wá ń bá wí .
1 , 2 . ( a ) What shows that everyone in the congregation can have a place he can cherish ?
1 , 2 . ( a ) Kí ló fi hàn pé olúkúlùkù ẹni tó wà nínú ìjọ ló lè ní ojúṣe tó yẹ kó mọrírì ?
1 , 2 . ( a ) In what sense are true Christians at war ?
1 , 2 . ( a ) Ò ̣ nà wo ni àwọn Kristẹni tòótó ̣ gbà wà lójú ogun ?
1 : 2 ; 1 Tim .
1 : 2 ; 1 Tím .
Youths Get Baptized ?
12 / 1
12 : 20 - How do we " heap fiery coals " upon an enemy 's head ?
12 : 20 - Báwo la ṣe ń kó " òkìtì ẹyín iná " lé ò ̣ tá lórí ?
13 : 16 ; 1 Pet .
13 : 16 ; 1 Pét .
15 : 4 .
14 : 16 ; Róòmù 15 : 4 .
14 Is Coffee Raising Your Cholesterol Level ?
14 Jíjí Èèyàn Gbé - Òwò Àwọn Apanilé ̣ kún - Jayé
16 , 17 . ( a ) Although Asa was victorious , what reminder did Jehovah give him ?
16 , 17 . ( a ) Bó tiè ̣ jé ̣ pé Ásà ja àjàṣé ̣ gun , ìránnilétí wo ni Jèhófà fún un ?
17 , 18 . ( a ) In what ways can a couple put spirituality first in their family ?
17 , 18 . ( a ) Àwọn ò ̣ nà wo ni tọkọtaya lè gbà fi Ọló ̣ run sípò àkó ̣ kó ̣ nínú ìdílé wọn ?
19 Can You Tell the Difference ?
18 Àwọn Ẹlé ̣ sìn Tìtorí Àlàáfíà Pé Jọ sí Ìlú Assisi
20 , 21 . ( a ) Why is love of excelling value ?
20 , 21 . ( a ) Kí nìdí tí ìfé ̣ fi ta yọ ló ̣ lá ?
13 Displaying Love in Times of Trouble
23 Fífi Ìfé ̣ Hàn Nígbà Ìṣòro
26 : 12 ; 111 : 1 ; Isa .
26 : 12 ; 111 : 1 ; Aísá .
3 Predicting the Future
3 Ohun Táwọn Kan Sọ Nípa Ọjó ̣ Iwájú
3 Is the Bible 's Guidance Relevant Today ?
3 Ṣé Ò ̣ rò ̣ Inú Bíbélì Wúlò Lóde Òní ?
38 : 8 ; Deut .
38 : 8 ; Diu .
4 , 5 . ( a ) How does Proverbs 18 : 15 relate to knowledge and understanding of Bible lands ?
4 , 5 . ( a ) Báwo ni Òwe 18 : 15 ṣe wé mó ̣ ìmò ̣ àti òye nípa àwọn ilè ̣ tí Bíbélì mé ̣ nu kàn ?
4 : 23 - 5 : 2 ; Luke 6 : 12 - 19 .
4 : 23 - 5 : 2 ; Lúùkù 6 : 12 - 19 .
4 : 7 - 9 ; 1 Pet .
4 : 7 - 9 ; 1 Pét .
4 We appreciate all that God has done for us .
4 A mọyì gbogbo ohun tí Ọló ̣ run ti ṣe fún wa .
4 Foretelling the Messiah
4 Àwọn Àsọté ̣ lè ̣ Bíbélì Nípa Mèsáyà
When we serve God out of love , how does he feel , and why ?
5 : 3 . Tá a bá ń sin Ọló ̣ run torí pé a nífè ̣ é ̣ rè ̣ , báwo ló ṣe máa ń rí lára rè ̣ , kí sì nìdí ?
5 Why Some Resort to Violence
5 Ìdí Tí Àwọn Kan Fi Ń Hùwà Ipá
5 ' 2 " 135 or less 136 - 163 164 or more
57 mítà 61 tàbí kó dín 62 sí 73 74 tàbí kó lé
6 Where Is This World Heading ?
6 Ibo Lò ̣ rò ̣ Ayé Yìí Ń Lọ ?
9 : 26 ; John 14 : 19 .
9 : 26 ; Jòh . 14 : 19 .
On to New Guinea
A Forí Lé New Guinea
Self - discipline affects our manner of speech as well as what we say .
A gbó ̣ dò ̣ máa kóra wa níjàánu nínú ò ̣ nà tá à ń gbà sò ̣ rò ̣ àti ohun tá à ń sọ pè ̣ lú .
Reportedly , it has had a measure of success in reducing the effects of RA .
A gbó ̣ pé ó ti ṣiṣé ̣ gan - an fún kíkojú làkúrègbé tó ń mú oríkèé ara wú .
We stayed up well into the morning hours talking about the Bible .
A jọ sò ̣ rò ̣ nípa Bíbélì títí di ò ̣ gànjó ̣ òru .
End of preview. Expand in Data Studio

English-Yoruba Parallel Dataset

This dataset contains parallel sentences in English and Yoruba (Nigeria).

Dataset Information

  • Language Pair: English ↔ Yoruba
  • Language Code: yor
  • Country: Nigeria
  • Original Source: OPUS MT560 Dataset

Dataset Structure

The dataset contains parallel sentences that can be used for:

  • Machine translation training
  • Cross-lingual NLP tasks
  • Language model fine-tuning

Citation

If you use this dataset, please cite the citation guide of the original OPUS MT560 dataset.

License

This dataset is released under the Creative Commons Attribution 4.0 International License.

Downloads last month
128

Collection including michsethowusu/english-yoruba_sentence-pairs_mt560