eng
stringlengths
1
539
yor
stringlengths
2
509
How did Jesus emphasize the need for us to safeguard our clear identification as Christians ?
Báwo ni Jésù ṣe tẹnu mó ̣ ìdí tó fi ṣe pàtàkì láti máa hùwà gé ̣ gé ̣ bíi Kristẹni tòótó ̣ nígbà gbogbo ?
How does she feel about delegating the driving to someone else ?
Báwo ni jíjẹ kí ẹlòmíràn máa wà á kiri ṣe rí lára rè ̣ ?
How reliable is what we read in our newspapers ?
Báwo ni ohun tá a bá kà nínú ìwé ìròyìn ṣe ṣeé gbà gbó ̣ tó ?
How does what we take into our mind affect our thinking ?
Báwo ni ohun tí à ń gbà sínú ọpọlọ wa ṣe ń nípa lórí ìrònú wa ?
What is revealed by our answer to the question , ' When will I engage in recreation ? '
Báwo ni ohun tó wà ló ̣ kàn wa ṣe lè hàn kedere nínú ìdáhùn wa sí ìbéèrè náà , ' Ìgbà wo ló yẹ kí n ṣe eré ìnàjú ? '
How could the prophet do this and convince King David that he needed to repent ?
Báwo ni wòlíì náà ṣe máa ṣe é , táá sì mú kí Dáfídì Ọba gbà pé ó yẹ kí òun ronú pìwà dà ?
How can Jehovah 's holy spirit help us to deal with any challenges that may confront us ?
Báwo ni è ̣ mí mímó ̣ Jèhófà ṣe lè ràn wá ló ̣ wó ̣ láti borí ìṣòro èyíkéyìí tó bá dojú kọ wá ?
How can humility help a couple to see their individual strengths in the right light ?
Báwo ni è ̣ mí ìrè ̣ lè ̣ ṣe lè mú kí tọkọtaya mọyì ànímó ̣ rere tí ẹnì kò ̣ ò ̣ kan wọn ní ?
The nation 's economy was mainly based on farming , herding , and bartering .
Báwo ni ètò káràkátà ṣe rí ní ilè ̣ Ísíré ̣ lì ìgbàanì ?
How does Revelation 6 : 2 portray Jesus as he is today ?
Báwo ní ìwé Ìṣípayá 6 : 2 ṣe ṣàpèjúwe irú ẹni tí Jésù jé ̣ nísinsìnyí ?
And how may others benefit from our conforming to God 's righteous standards ?
Báwo sì làwọn ẹlòmíràn ṣe lè jàn ̀ fààní nínú rírò ̣ tí a rò ̣ mó ̣ ò ̣ pá ìdiwò ̣ n òdodo Ọló ̣ run ?
How did the word " God " come to be inserted into that verse ?
Báwo wá ni ò ̣ rò ̣ náà " Ọló ̣ run " ṣe dénú ẹsẹ yìí ?
The High Price Parents Pay
Báwọn Òbí Ṣe Ń Forí Fá A
True , man 's mismanagement of the earth has apparently thrown the weather patterns off balance , resulting in severe floods in some areas and droughts in others .
Báwọn èèyàn ṣe ń ṣi ayé yìí lò ni ò jé ̣ kí ojú ọjó ̣ wà déédéé mó ̣ , ìdí sì nìyẹn tó fi jé ̣ pé àkúnya omi ń da àwọn ibì kan láàmú , nígbà tó jé ̣ pé ò ̣ dá omi nìṣòro láwọn ibòmíì .
How true that was of Jesus Christ !
Bé ̣ è ̣ gé ̣ é ̣ sì ni Jésù Kristi ṣe !
The bleeding also increased , and I realized that I was having contractions .
Bé ̣ è ̣ lè ̣ jè ̣ túbò ̣ ń dà lára mi , mo sì wá á rí i pé ọmọ ló ń mú mi .
Yes , there are still people who act with true Christian love .
Bé ̣ è ̣ ni , àwọn èèyàn ṣì wà tí wó ̣ n ń fi ìfé ̣ Kristẹni tòótó ̣ ṣèwà hù .
Yes , love for Jehovah moves us to treasure life , as he does .
Bé ̣ è ̣ ni , ìfé ̣ fún Jèhófà mú ká ka è ̣ mí sí pàtàkì bí Ọló ̣ run ṣe kà á sí pàtàkì .
Few places on earth escape the reach of the global media .
Bé ̣ è ̣ ni , ṣàṣà ibi ló wà láyé yìí tí wọn ò ti mò ̣ nípa ohun tó ń ṣẹlè ̣ kárí ayé .
Most certainly .
Bé ̣ è ̣ ni .
Yes , just as Jehovah and Jesus rejoice in imparting spiritual gifts , Christians do also .
Bé ̣ è ̣ ni o , bí Jèhófà àti Jésù ṣe máa ń yò ̣ nígbà tí wó ̣ n bá fúnni ní è ̣ bùn tè ̣ mí náà làwọn Kristẹni ṣe máa ń yò ̣ .
Yes , a letter may be a small thing .
Bé ̣ è ̣ ni o , lé ̣ tà kan lè má jọ èèyàn lójú .
Yes , the indigenous language field is truly " white for harvesting , " and all those who share in it feel greatly encouraged .
Bé ̣ è ̣ ni o , àwọn tó ń sọ èdè àbínibí yìí ti dà bí ohun ò ̣ gbìn tó " ti funfun fún kíkórè " lóòótó ̣ , gbogbo àwọn tó sì ń ṣíṣẹ ìkórè náà ni iṣé ̣ ò ̣ hún máa ń wú lórí .
Neither do condescending lectures .
Bé ̣ è ̣ náà ni nínà wó ̣ n lé ̣ gba ò ̣ rò ̣ ò ràn án .
If the repentant man became " swallowed up by his being overly sad " and gave up entirely , especially would the elders bear some responsibility for this before the merciful God , Jehovah .
Bí ' ìbànújé ̣ ẹni tó ronú pìwà dà náà bá pàpò ̣ jù ' tó sì ṣíwó ̣ sísin Ọló ̣ run , Jèhófà Ọló ̣ run aláàánú yóò kà á sí àwọn alàgbà ìjọ yẹn ló ̣ rùn pé wó ̣ n dá kún ìṣòro rè ̣ .
According to the Bible , then , Jehovah God has a place of dwelling .
Bí Bíbélì ṣe sọ , Jèhófà Ọló ̣ run ní ibi tó ń gbé .
Deliverance in Modern Times
Bí Jèhófà Ṣe Dá Àwọn Èèyàn Rè ̣ Nídè Lóde Òní
As indicated by Jesus , such apostasy , promoted by " the wicked one , " Satan , would grow and obscure true Christianity until " the conclusion of the system of things . "
Bí Jésù ṣe sọ , ìpè ̣ yìndà tí Sátánì , " ẹni burúkú náà " ṣagbátẹrù rè ̣ máa gbèrú , á sì bo ìsìn tòótó ̣ mó ̣ lè ̣ títí di " ìparí ètò àwọn nn ̀ kan . "
Learning Bible Truth
Bí Mo Ṣe Ké ̣ kò ̣ ó ̣ Bíbélì
Meeting Lloyd 's Family
Bí Mo Ṣe Mọ Ìdí lé Lloyd
According to Matthew 7 : 1 - 4 , how may we practice mercy daily ?
Bí Mátíù 7 : 1 - 4 ṣe sọ , ò ̣ nà wo la lè gbà máa ṣàánú àwọn èèyàn ?
Paul described such Christlike love this way : " Love is long - suffering and kind .
Bí Pó ̣ ò ̣ lù ṣe ṣàpèjúwe ìfé ̣ Kristi rèé , ó ní : " Ìfé ̣ a máa ní ìpamó ̣ ra àti inú rere .
To maintain our precious relationship with God and his Son , what are we happy to do ?
Bí a ò bá fé ̣ kí àjọṣe pàtàkì tá a ní pè ̣ lú Ọló ̣ run àti Ọmọ rè ̣ bà jé ̣ , kí la óò máa fayò ̣ ṣe ?
Once my condition had stabilized , I had an operation to implant a pacemaker .
Bí ara mi sì ṣe yá díè ̣ ni mo ṣe iṣé ̣ abẹ kan tí wó ̣ n ti fi è ̣ rọ tó ń mú ọkàn ṣiṣé ̣ sínú mi .
They contributed food and clothing when necessary as well as financial aid .
Bí mo bá nílò oúnjẹ , aṣọ àti owó , wó ̣ n máa ń fún mi .
As I studied anatomy , I saw how well - designed and complex living things are .
Bí mo ṣe ń ké ̣ kò ̣ ó ̣ nípa ohun tó ń ṣẹlè ̣ nínú ara èèyàn ni mo túbò ̣ ń rí i pé ohun àgbàyanu àti àwámáridìí gbáà ni àwọn ohun alààyè .
As I pulled into my driveway , I saw her waiting on the front steps of my home .
Bí mo ṣe ń wa mó ̣ tò wọlé , mo rí i tó dúró lórí àtè ̣ gùn iwájú ilé mi .
If they dig down into Sheol , from there my own hand will take them ; and if they go up to the heavens , from there I shall bring them down . " - Amos 9 : 1 , 2 .
Bí wó ̣ n bá walè ̣ lọ sínú Ṣìó ̣ ò ̣ lù , láti ibè ̣ ni ọwó ̣ mi yóò ti tè ̣ wó ̣ n ; bí wó ̣ n bá sì gòkè lọ sí ò ̣ run , láti ibè ̣ ni èmi yóò ti mú wọn sò ̣ kalè ̣ . " - Ámósì 9 : 1 , 2 .
They became demons . - Jude 6 .
Bí wó ̣ n ṣe di è ̣ mí èṣù nìyẹn . - Júúdà 6 .
Their ready participation at the meetings and their zeal in the ministry , as well as their caring attitude toward all in the congregation , enable the elders to discern their potential when considering them for additional assignments .
Bí wó ̣ n ṣe máa ń múra tán láti kópa láwọn ìpàdé àti ìtara tí wó ̣ n ní nínú iṣé ̣ òjíṣé ̣ , títí kan ìfé ̣ tí wó ̣ n ń fi hàn sí gbogbo èèyàn nínú ìjọ , ń ran àwọn alàgbà ló ̣ wó ̣ láti fòye mọ bí wó ̣ n ṣe tóótun tó nígbà tí wó ̣ n bá ń ronú àtigbé àfikún ẹrù iṣé ̣ lé wọn ló ̣ wó ̣ .
After they marry , those feelings help to bond them together as husband and wife .
Bí wó ̣ n ṣe ń ké ̣ ara wọn máa ràn wó ̣ n ló ̣ wó ̣ láti lè fira wọn ṣò ̣ kan bíi tọkọtaya .
For example , Bible counsel steers people away from harmful habits , such as the use of tobacco and the abuse of alcohol .
Bí àpẹẹrẹ , Bíbélì sọ pé ká yẹra fún àwọn àṣàkaṣà bí àmujù ọtí àti mímu sìgá .
For example , some 65 times in the first three Gospels and over 100 times in John 's Gospel , we read of Jesus using the term " Father . "
Bí àpẹẹrẹ , Jésù lo ò ̣ rò ̣ náà " Baba " ní nn ̀ kan bí ìgbà márùnléló ̣ gó ̣ ta [ 65 ] nínú ìwé Ìhìn Rere ti Mátíù , Máàkù àti Lúùkù , ó sì lé ní ọgó ̣ rùn - ún [ 100 ] ìgbà tó lò ó nínú Ìhìn Rere ti Jòhánù .
For example , he did not just tell his followers to seek first the Kingdom and God 's righteousness but said : " And all these other things will be added to you . "
Bí àpẹẹrẹ , Jésù ò kàn sọ fáwọn ọmọlé ̣ yìn rè ̣ pé kí wó ̣ n kó ̣ kó ̣ máa wá Ìjọba Ọló ̣ run àti òdodo Rè ̣ , àmó ̣ ó sọ pé : " Gbogbo nn ̀ kan mìíràn wò ̣ nyí ni a ó sì fi kún un fún yín . "
For instance , Moses commanded the sons of Levi : " At the end of every seven years , . . . you will read this law in front of all Israel . "
Bí àpẹẹrẹ , Mósè pàṣẹ fáwọn ọmọ Léfì pé : " Ní òpin ọdún méje - méje , . . . ìwọ yóò ka òfin yìí ní iwájú gbogbo Ísíré ̣ lì . "
For example , I met an evangelical preacher who tried to pressure me to accept Jesus as my Savior .
Bí àpẹẹrẹ , ajíhìnrere kan láti ṣó ̣ ò ̣ ṣì kan ń fúngun mó ̣ mi pé àfi kí n gba Jésù ní Olùgbàlà mi .
After the eggs are hatched , for example , the hen goes off with other hens while the male assumes the responsibility of caring for the young .
Bí àpẹẹrẹ , bí ẹyẹ náà bá pamọ tán , ńṣe ló máa bá àwọn ẹyẹ mìíràn lọ tí akọ á sì máa bójú tó àwọn ọmọ wé ̣ wé ̣ náà .
For instance , the UC Berkeley Wellness Letter , a newsletter on nutrition , fitness , and stress management published by the University of California , advises : " Start by adding a few minutes of increased activity to your day , and work up to 30 minutes most , and preferably all , days of the week . "
Bí àpẹẹrẹ , ilé ìwé gíga University of California fi ìwé kan ṣọwó ̣ síta tí wó ̣ n pè ní UC Berkeley Wellness Letter . Ìwé náà sò ̣ rò ̣ nípa oúnjẹ tó dáa fún ara , bí ara ṣe lè máa dá ṣáṣá , àti ohun téèyàn lè ṣe tí nn ̀ kan bá ń dà á láàmú .
After a long day at work , we may have to push ourselves to go to the meeting .
Bí àpẹẹrẹ , lé ̣ yìn tá a ti ṣiṣé ̣ lọ látàárò ̣ , ó lè jé ̣ pé ńṣe la máa ró ̣ jú lọ sípàdé torí pé ó ti rè ̣ wá tẹnutẹnu .
For example , each year millions of youths contract a sexually transmitted disease ( STD ) .
Bí àpẹẹrẹ , ló ̣ dọọdún ni ò ̣ pò ̣ mílíò ̣ nù àwọn ò ̣ dó ̣ ń kárùn látinú ìbálòpò ̣ .
For instance , while teaching others Bible truth , you can impart insight into 1 Thessalonians 4 : 3 - 7 , increasing their understanding and appreciation for Christian morality .
Bí àpẹẹrẹ , nígbà tó o bá ń kó ̣ àwọn ẹlòmíràn ní òtító ̣ Bíbélì , o lè ṣe àlàyé kínníkínní nípa 1 Tẹsalóníkà 4 : 3 - 7 , kí o tipa bé ̣ è ̣ fi kún òye wọn , kí wó ̣ n sì túbò ̣ máa fojú ribiribi wo ìwà rere Kristẹni .
For example , if a business agreement becomes harder to honor than expected , our loyalty to God and regard for the Bible should move us to keep our word .
Bí àpẹẹrẹ , tá a bá tọwó ̣ bọ ìwé àdéhùn iṣé ̣ pè ̣ lú ẹnì kan , á máa rí i dájú pé a ṣe ohun tá a ṣèlérí pé a máa ṣe , kódà bí kò bá tiè ̣ rọrùn pàápàá .
For instance , by proclaiming the truth about Jehovah 's wonderful qualities and his unchangeable purpose for mankind , we defend God 's name against Satan 's lies and slander .
Bí àpẹẹrẹ , tá a bá ń sò ̣ rò ̣ nípa àwọn ànímó ̣ Jèhófà fáwọn èèyàn àtàwọn ohun tó ní ló ̣ kàn fún aráyé , ṣe là ń fi hàn pé afò ̣ rò ̣ - èké - bani - jé ̣ ni Sátánì àti pé iró ̣ gbuu ló pa mó ̣ Jèhófà .
A loss of privileges , for example , can help a person realize how important it is for him to focus more on personal Bible study , meditation , and prayer .
Bí àpẹẹrẹ , té ̣ nì kan bá pàdánù àwọn àn ̀ fààní tó ní nínú ìjọ , ìyẹn á jé ̣ kó rí bó ti ṣe pàtàkì tó pé kéèyàn máa ké ̣ kò ̣ ó ̣ Bíbélì déédéé , kó máa ṣàṣàrò , kó sì máa gbàdúrà .
For example , if your teenager breaks a curfew , imposing an earlier curfew would be a related consequence .
Bí àpẹẹrẹ , tó bá jé ̣ pé ńṣe ni ọmọ rẹ pé ̣ níta , ìbáwí tó bá è ̣ ṣè ̣ náà mu ni pé kó o yí aago tí ọmọ náà gbó ̣ dò ̣ wọlé pa dà , kó o jé ̣ kó yá ju ti té ̣ lè ̣ lọ .
For example , material might be deliberately inserted into a film so that it will receive a more severe rating , making the movie seem more adult .
Bí àpẹẹrẹ , wó ̣ n kàn lè ṣàdéédéé fi ohun kan kún fíìmù kan kó bàa lè wọ ìsò ̣ rí fíìmù tó yẹ káwọn tó ti dàgbà wò .
For example , Ezra traveled back to Jerusalem with donated items from the Persian king - gold , silver , and other materials worth well over $ 100 million ( U.S . ) in today 's values .
Bí àpẹẹrẹ , É ̣ sírà kó góòlù , fàdákà àtàwọn nn ̀ kan míì tí ọba Páṣíà fi tọrẹ wá sí Jerúsálé ̣ mù , tá a bá sì díwò ̣ n gbogbo nn ̀ kan yẹn , wó ̣ n lé ní mílíò ̣ nù ló ̣ nà ọgó ̣ rùn - ún kan dó ̣ là [ $ 100 million ] .
For local people such wealth may be unimagined .
Bí àpẹẹrẹ , àwọn arìnrìn - àjò afé ̣ máa ń mú àwọn nn ̀ kan tó jojú ní gbèsè dání lọ síbi tí wó ̣ n bá rìnrìn - àjò lọ .
Presses have become larger , faster , and more sophisticated .
Bí àpẹẹrẹ , àwọn è ̣ rọ ìtè ̣ wé tí ó tóbi , tí wó ̣ n yára tí wó ̣ n sì díjú ti wà .
For instance , some youths have engaged in oral or anal sex or mutual masturbation , rationalizing that these acts are not so bad because they think they are technically not " having sex . "
Bí àpẹẹrẹ , àwọn ò ̣ dó ̣ kan máa ń fi ahó ̣ n lá è ̣ yà ìbímọ ara wọn , wó ̣ n máa ń ti ihò ìdí bára wọn ṣèṣekúṣe tàbí kí wó ̣ n máa fọwó ̣ pa è ̣ yà ìbímọ ara wọn kára wọn lè gbóná sódì , wó ̣ n á wá máa ronú pé ohun táwọn ń ṣe ò tíì burú tó bé ̣ è ̣ torí àwọn ò ṣáà tíì bá onítò ̣ hún sùn ní tààràtà .
For example , concerning the nations that the Israelites were to dispossess , Jehovah commanded : " You must form no marriage alliance with them .
Bí àpẹẹrẹ , àṣẹ tí Jèhófà pa fáwọn ọmọ Ísíré ̣ lì nípa àwọn orílè ̣ - èdè táwọn ọmọ Ísíré ̣ lì máa gba ilè ̣ wọn ni pé : " Ìwọ kò sì gbó ̣ dò ̣ bá wọn dána .
For example , those who were imprisoned in concentration camps in Nazi Germany managed to thrive .
Bí àpẹẹrẹ , ó ṣeé ṣe fún àwọn tí wó ̣ n fi sé ̣ wò ̣ n nínú àgó ̣ ìṣé ̣ niníṣè ̣ é ̣ nígbà ìjọba Násì ní ilè ̣ Jámánì láti rù ú là .
If opposition or persecution rob us of our livelihood or our freedom , we resolve to remain firm in the faith whatever trials we may face .
Bí àtakò tàbí inúnibíni bá mú kí iṣé ̣ oúnjẹ òòjó ̣ wa bó ̣ ló ̣ wó ̣ wa tàbí tá ò lómìnira mó ̣ , síbè ̣ , a óò dúró lórí ìpinnu wa láti má ṣe yẹsè ̣ kúrò nínú ìgbàgbó ̣ láìfi àdánwò èyíkéyìí pè .
If we too focus on the mercy Jehovah has shown us , we will avoid having our strength sapped by undue anxiety over past events that we cannot change .
Bí àwa náà bá ń ronú nípa àánú tí Jèhófà ti fi hàn sí wa , a kò ní jé ̣ kí àníyàn nípa àwọn ohun tó ti ṣẹlè ̣ kọjá tí a kò sì lè ṣe ohunkóhun nípa rè ̣ mu wá lómi .
How can a greater understanding of Jehovah 's love help those who are troubled by God 's permission of suffering ?
Bí àwọn tí inú wọn bà jé ̣ nítorí pé Ọló ̣ run fàyè gba ìpó ̣ njú bá ní ìmò ̣ sí i nípa ìfé ̣ Jèhófà , báwo lèyí á ṣe ràn wó ̣ n ló ̣ wó ̣ ?
As the people expressed their devotion to Jehovah , they would grow in godly fear and love and would be helped to walk in his ways .
Bí àwọn ọmọ Ísíré ̣ lì bá ń ṣe ohun wò ̣ nyí nínú ìjọsìn wọn , wó ̣ n á túbò ̣ bè ̣ rù Ọló ̣ run , ìfé ̣ tí wó ̣ n ní fún un á jinlè ̣ sí i , wó ̣ n á sì túbò ̣ mọ bí wó ̣ n ṣe lè máa rìn láwọn ò ̣ nà rè ̣ .
If your sibling constantly annoys you - bossing you around or invading your space - it might be hard not to let resentment build .
Bí è ̣ gbó ̣ n tàbí àbúrò rẹ bá ń múnú bí ẹ , tó máa ń fé ̣ ṣe bí ò ̣ gá lé ẹ lórí tàbí tó máa ń fé ̣ mọ gbogbo nn ̀ kan tó o bá ń ṣe , ó lè ṣòro fún ẹ láti gbójú fo àwọn ohun tó ń ṣe yìí dá .
When I am in the car with my son , I take advantage of the opportunity to talk with him .
Bí èmi àti ọmọ mi ọkùnrin bá wà nínú ọkò ̣ ayó ̣ ké ̣ lé ̣ , mo máa ń lo àn ̀ fààní yẹn láti bá a sò ̣ rò ̣ . "
As the present system of things moves toward its end , the foretold " pangs of distress " will continue .
Bí ètò nn ̀ kan ìsinsìnyí ṣe ń lọ sópin , ńṣe ni " ìroragógó wàhálà " tí Jésù sọ té ̣ lè ̣ yóò máa bá a nìṣó .
As your faith grows , so will your hope - a hope to live at a time when you will personally benefit from the miracles that Jehovah performs .
Bí ìgbàgbó ̣ rẹ bá ṣe ń lágbára sí i , bé ̣ è ̣ ni ìrètí rẹ á túbò ̣ máa dájú sí i , ìyẹn ìrètí pé wàá wà lára àwọn tó máa jàn ̀ fààní nínú àwọn iṣé ̣ ìyanu tí Jèhófà máa tó ṣe .
They react to situations on the basis of pride or selfishness , they manifest a rebellious attitude toward authority , and they give free rein to " the desire of the flesh and the desire of the eyes . " - Read 1 John 2 : 15 - 17 .
Bí ò ̣ ràn kan bá yọjú , wó ̣ n máa ń gbéra ga , wó ̣ n máa ń fi ìmọtara - ẹni nìkan hàn , wó ̣ n máa ń hùwà ò ̣ tè ̣ sí àwọn aláṣẹ , wó ̣ n sì máa ń gba " ìfé ̣ kúfè ̣ é ̣ ara àti ìfé ̣ kúfè ̣ é ̣ ojú " láyè . - Ka 1 Jòhánù 2 : 15 - 17 .
So he courageously took the lead in trying to warn the people of that wicked , godless society about the destruction that was heading their way .
Bí ó ṣe mú ipò iwájú lé ̣ nu iṣé ̣ kíkìlò ̣ fún àwọn èèyàn oníwà ibi àti àwọn aláìṣèfé ̣ Ọló ̣ run pé ìparun ń bò ̣ wá sórí wọn , fi hàn pé ó jé ̣ onígboyà .
Under Law , why unclean from natural sexual functions ? 6 / 1
Bí Ọló ̣ run Ṣe Ń Kó Àwọn Ohun Ti Ò ̣ run àti Ti Ayé Jọ , 2 / 15
The godly man or woman who endures the trials of a difficult marriage for the sake of conscience is precious to God .
Bí ọkùnrin tàbí obìnrin kan tó jé ̣ olùbè ̣ rù Ọló ̣ run bá ń fara da àdánwò nínú ìgbéyàwó rè ̣ nítorí è ̣ rí ọkàn , irú ẹni bé ̣ è ̣ ṣe iyebíye lójú Ọló ̣ run .
We are urged to " pray for one another , " even though we do not always get immediate proof that such prayers are being answered .
Bíbélì gbà wá níyànjú láti " máa gbàdúrà fún ara [ wa ] lé ̣ nì kìíní - kejì , " àní bó tilè ̣ jé ̣ pé ìgbà gbogbo kó ̣ la máa ń rí è ̣ rí lójú ẹsè ̣ pé Ọló ̣ run ti dáhùn irú àdúrà bé ̣ è ̣ .
The Bible does warn about the bad consequences of overindulgence in alcohol .
Bíbélì kìlò ̣ nípa ohun tó máa ń tìdí mímu ọtí líle lámujù yọ .
" There exists a way that is upright before a man , but the ways of death are the end of it afterward , " warns the Bible .
Bíbélì kìlò ̣ pé : " Ò ̣ nà kan wà tí ó dúró ṣánṣán lójú ènìyàn , ṣùgbó ̣ n àwọn ò ̣ nà ikú ni òpin rè ̣ ní àsè ̣ yìnwá - àsè ̣ yìnbò ̣ . "
Daily Bible reading greatly contributed to my spiritual progress .
Bíbélì kíkà ojoojúmó ̣ ti ràn mí ló ̣ wó ̣ gan an láti tè ̣ síwájú nípa tè ̣ mí .
The genuineness of our love can be tested by the Bible 's command to " support the weak , be patient toward all . "
Bíbélì rò ̣ wá pé " ẹ máa ṣètìlẹyìn fún àwọn aláìlera , ẹ máa ní ìpamó ̣ ra fún gbogbo ènìyàn . "
The Bible urges fathers to avoid exasperating their children , " that they do not become downhearted . "
Bíbélì rọ àwọn baba pé kí wó ̣ n má ṣe máa dá àwọn ọmọ wọn lágara " kí wó ̣ n má bàa soríkodò . "
The Bible condemns " stirring up competition . " - Galatians 5 : 26 .
Bíbélì sì sọ pé kò dára láti máa ' ru ìdíjé sókè . ' - Gálátíà 5 : 26 .
The Bible speaks of " pure religion , " or " worship that is clean and undefiled . "
Bíbélì sò ̣ rò ̣ nípa " ìsìn mímó ̣ , " tàbí " ìjọsìn tí ó mó ̣ , tí ó sì jé ̣ aláìlé ̣ gbin . "
The Bible mentions markets at city gates - " the Sheep Gate , " " the Fish Gate , " and " the Gate of the Potsherds . "
Bíbélì sò ̣ rò ̣ nípa ọjà ní àwọn ẹnubodè ìlú , irú bíi " Ẹnubodè Àgùntàn , " " Ẹnubodè Ẹja " àti " Ẹnubodè Èéfó ̣ Ìkòkò . "
The Bible observes : " Where there is no wood the fire goes out , and where there is no slanderer contention grows still . "
Bíbélì sọ pé : " Níbi tí igi kò bá sí , iná a kú , níbi tí afò ̣ rò ̣ - èké - banijé ̣ kò bá sì sí , asò ̣ a dá . "
" The former things will not be called to mind , " says the Bible .
Bíbélì sọ pé : " Àwọn ohun àtijó ̣ ni a kì yóò sì mú wá sí ìrántí . "
The blood of Jesus his Son cleanses us from all sin .
Bíbélì sọ pé : " È ̣ jè ̣ Jésù Ọmọ rè ̣ sì ń wè ̣ wá mó ̣ kúrò nínú gbogbo è ̣ ṣè ̣ . "
The Bible says : " Look out not only for your own interests , but also for the interests of others . "
Bíbélì sọ pé : " Ẹ má ṣe máa mójú tó ire ara ẹni nínú kìkì àwọn ò ̣ ràn ti ara yín nìkan , ṣùgbó ̣ n ire ara ẹni ti àwọn ẹlòmíràn pè ̣ lú . "
God is for us a refuge and strength , a help that is readily to be found during distresses .
Bíbélì sọ pé : " Ọló ̣ run jé ̣ ibi ìsádi àti okun fún wa , ìrànló ̣ wó ̣ tí a lè rí tìrò ̣ rùn - tìrò ̣ rùn nígbà wàhálà . "
The Bible states that Barnabas led the former persecutor " to the apostles , " evidently referring to Peter ( Cephas ) and James , the brother of the Lord , apprising them of Saul 's conversion and of his preaching in Damascus .
Bíbélì sọ pé Bánábà mú Só ̣ ò ̣ lù onínúnibíni té ̣ lè ̣ rí yìí " lọ bá àwọn àpó ̣ sítélì . " È ̣ rí fi hàn pé Pétérù ( ìyẹn Kéfà ) àti Jákó ̣ bù arákùnrin Olúwa làwọn àpó ̣ sítélì yìí .
The Bible foretold that Christianity would be hijacked and used for evil ends .
Bíbélì sọ té ̣ lè ̣ pé ìgbà kan ń bò ̣ tí àwọn kan yóò máa lo è ̣ sìn Kristẹni láti fi ṣe ibi .
The Bible clearly states : " God is not unrighteous so as to forget your work and the love you showed for his name . "
Bíbélì sọ ó ̣ kedere pé : " Ọló ̣ run kì í ṣe aláìṣòdodo tí yóò fi gbàgbé iṣé ̣ yín àti ìfé ̣ tí ẹ fi hàn fún orúkọ rè ̣ . "
The Bible pointedly says : " There is a frustrating of plans where there is no confidential talk . "
Bíbélì ti sò ̣ rò ̣ síbi tó ̣ rò ̣ wà nígbà to sọ pé : " Àwọn ìwéwèé máa ń já sí pàbó níbi tí kò bá ti sí ò ̣ rò ̣ ìfinúkonú . "
They are not told to show their respect for that gift by displaying a symbol of Jesus or merely confessing their belief in him .
Bíbélì ò sọ pé gbígbé àmì Jésù kiri tàbí fífi ẹnu lásán sọ pé àwọn nígbàgbó ̣ nínú Jésù ló máa fi hàn pé wó ̣ n mọyì è ̣ bùn yìí .
The Bible does not say that such a command applies to Christians .
Bíbélì ò sọ pé Ọló ̣ run pa irú àṣẹ bé ̣ è ̣ fáwa Kristẹni .
The Bible explains that in God 's new world of righteousness , the power of God will again cause the sort of miraculous healings that Jesus performed while on earth .
Bíbélì ṣàlàyé pé nínú ayé tuntun òdodo ti Ọló ̣ run , agbára Ọló ̣ run yóò mú kí fífi iṣé ̣ ìyanu woni sàn tún wáyé bí irú èyí tí Jésù ṣe nígbà tó wà lórí ilè ̣ ayé .
Like him , they boldly declare God 's prophetic word .
Bíi ti Jeremáyà , wó ̣ n ń fi ìgboyà kéde ò ̣ rò ̣ àsọté ̣ lè ̣ Ọló ̣ run .
Like Martha , what joyful event are you looking forward to ?
Bíi ti Màtá , ìṣè ̣ lè ̣ tó ń mó ̣ kàn ẹni yò ̣ wo lò ń fojú só ̣ nà fún ?
I feel as did the apostle Paul , who wrote : " I am grateful to Christ Jesus our Lord , who imparted power to me , because he considered me faithful by assigning me to a ministry . "
Bíi ti àpó ̣ sítélì Pó ̣ ò ̣ lù lò ̣ rò ̣ rí lára mi , ẹni tó kò ̣ wé pé : " Mo kún fún ìmoore sí Kristi Jésù Olúwa wa , ẹni tí ó fi agbára fún mi , nítorí tí ó kà mí sí olùṣòtító ̣ nípa yíyan iṣé ̣ òjíṣé ̣ kan lé mi ló ̣ wó ̣ . "
Like their counterparts in Egypt , the Mexican pyramids are many centuries old and are shrouded in mystery .
Bíi ti àwọn ẹlẹgbé ̣ wọn ní Íjíbítì , àwọn òkè aboríṣóńṣó - bìdírè ̣ kè ̣ tè ̣ tó jé ̣ ti àwọn ará Mé ̣ síkò ti wà fún ò ̣ pò ̣ ò ̣ rúndún , àràmàn ̀ dà sì lò ̣ ràn wọn jé ̣ .
" I have yet to meet a theologian who considers [ Jehovah 's Witnesses ] to be Christians , " said the bishop .
Bíṣó ̣ ò ̣ bù náà sọ pé , " Mi ò tíì rí ẹlé ̣ kò ̣ ó ̣ ìsìn tó ka àwọn [ Ẹlé ̣ rìí Jèhófà ] sí Kristẹni .